YO/Prabhupada 0534 - Don't Try to See Krishna Artificially



Radhastami, Srimati Radharani's Appearance Day -- London, August 29, 1971

Prabhupāda: agbudo tele awon Gosvami bon se wa Krsna ati Radharani ninu ilu Vrndavana, tabi ninu okan re. ilana bhajana caitanya Mahaprabhu niyen: imolara iyasoto vipralambha, vipralambha-sevā. gege bi Caitanya Mahaprabhu sen wa Krsna, Osi jabo sinu okun. Ojade kuru ninu yara re ni ale. Koseni to mobi tolo. Bon oun sen wa Olorun niyen. Ilana ise ifarafun Olorun gege bi Caitanya Mahaprabhu se kowa. konsepe kakon dide ka sowipe " Ati ri Krsna ati Radharani ninu rasalila" Rara, bayi ko. Egbudo wa wan. teba se wa Krsna si, bee lema mo boya eyin na tin ni ilosowaju. Ema gbiyanju lati ri Krsna. egbiyanju lati ni mo bseri lati wa wan, lehin na gbogbo nkan ma lo dada. akeko Oluwa Caitanya niyen. Nitoripe pelu aw o le ri Krsna pelu oju lasan. Ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved grāhyam indriyaiḥ (CC Madhya 17.136). pelu ogbon wa kosi basele ri Krsna, kosi basel gbo nipa oruko re. sugbon sevonmukhe hi jihvādau. teba sise fun Olorun.. nibo nise na ma beere.Jihvadau. Lati ahon niise na ma bere. lat'ese, tabi oju tabi eti ko. Lati ahon. Sevonmukhe hi jihvādau. teba bere ise yi lati ahon... Bawo? Ekorin Hare Krsna. lo ahon re. Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare, Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare. ke je Krsna prasadam. Ise meji pere ni ahon wa ni: Lati soro, Hare Krsna; ati lati gba prasadam. pelu ilana yi eyin na le ni ilaju si Krsna.

Elesin: Haribol!

Prabhupāda: Ema tie gbiyanju pe efe ri Krsna. Kosi besele ri pelu oju lasan. kosi besele gbo nkna ton so pelu eti lasan. Kosi besel fowo kan. Sugbon teban sise fun Olorun pelu ahon yin, asi farahan si yin: " Emi ni". Nkan tafe niyen. egbiyanj lati monipa bon sen wa Krsna bi Radharani, gege bi Olouwa Caitanya se hon wa, kesi fi ahon yin sise fun Oluwa; nijokan tebati dagba eyin na ma foju ri Krsna.

Ese Pupo.