YO/Prabhupada 0555 - Sleeping In The Matter Of Spiritual Understanding



Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968

Prabhupāda: Ilana eto wa ni tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170). ele ya iye ara yin si mimo,tryin ba sise ninu imoye Krsna. Iye ara yin o ni fun yin ni idamu mo. teyin bafe ni idari lori iye ara yin, egbodo ni idari lori ahon nialakoko. Lehin na eyin le ni idari lori awon iye ara to ku dada. Beena teyin ba fun ahon yin nise lati korin Hare Krsna, ati jijeun Krsna prasadam - eyin ma riwipe iye ara yin tini idari na. Ona lati ni idari lori iye ara wa leleyi, ahon. sugbon teyin ba jeki ahon yin se bosefe si, eyin o le ni idari kankan lori ahon na. Asiri towa niyen lati niiidari lori iye ara wa. Tesiwaju.

Tamāla Kṛṣṇa: 69: Nkan toje ale fun gbogbo eda, asiko lati ji soke ni fun awon ton ni idari lori ara won, asiko lati ji soke fun gbogbo aon eda , ale loje fun alakowe to logbon." Purport: " Awon okurin ologbon meji ototo lowa. Ikan ni ogbon lati gbadun ile aye yi, ikeji si logbon lati ni imo-ara re. Awon ise fun okurin ologbon je ale fun awon ton feran igbadun aye yi. Awon eyan aye yi si feran lati sun laale nitori aimokan ton ni nipa imora-eni. Alakowe yi, ma wa ni jiji nigbati awon onigbadun aye yi ban sun."

Prabhupāda: Itumo ale ni asiko tawon eyan ban sun, igbaton ba wa ni jiji ni ojo. Imoye nipa ojo at'ale niyen. Awon eyan aye yi won sun ninu eto imoye mimo. Beena ise ti awon onigbadun aye yin n'se loju ojo, looto ale loje. fun eni toje alakowe to logbon, asi riwipe awon eyan yi ni ouhun tonle lo fi ni imora-eni, ara eda eyan. Sugbn won lo nilokulo pelu orun sisun. Ati awon oni gbadun aye yi na won ri wipe, " Oh awon omo okurin imoye Krsna yi, won ti fi gbogbo nkan sile wonsin korin Hare Krsna. Iranu wo leleyi. Won sun." Se tiri bayi? Beena fun awn onigbadun aye yi, ale ni ise tan'se, sisun. fun eni tomo ara-re, sisun ni ise tonse. Se ri bayi? Odi keji loje. Won riwipe awon eyan ninu imoye Krsna won loasiko won nilokulo. awon eyan ninu imoye Krsna sin ri won beyan ton lo asiko nilokulo. Ipo wa leleyi. E tisiwaju.

Tamāla Kṛṣṇa: Awon alakowe bayiman ri igbadun mimo ninu ilosiwaju lori asa mimo, sugbon awon eyan ton wa ninu ise aye yi, ton sun lori eto imora-eni, awon igbadun iye ara re ni alaa soso toni."

Prabhupāda: Beeni. Won laala, " Nisin mofe se bayi. Toba ya ma se bayi, mani nkan bayi. Toba ya, ma ni nkan bayi. Toba ya ma pa ota mi. Toba ya mase bayi." Bonsen ronu leleyi. Tesiwaju.

Tamāla Kṛṣṇa: "Nigbami asi ni idunnu ati ibanuje ninu orun yi. Ologbon alakowe yi awon igbadun ati ibanuje aye yi o joo loju."

Prabhupāda: Eni toje alakowe ton sewaadi lori eto imora-eni, o ma dada wipe, " kasowipe tinba se loojowaju awon ise nla bayi bayi, tabi... Mole ko ile oke giga." Sugbon nitoripe on rorun dada, o mowipe " Kini mofe se pelu awon nkan wanyi? Lesekese tinba jade lati ipo yi, gbogbo nkan wanyi ma wa nibi, masi gba ara eda imi lati bere aye imi." Ironu denu leleyi.