YO/Prabhupada 0562 - My Authority is Vedic Literature



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Prabhupāda: iwe mimo Veda ni ijeerisi timo ni. beeni. Eyin ma ri ninu Bhagavad-gita... Seti ri iwe wa Bhagavad-gita?

Akoroyin: Beeni. Moni'kan ni ile ise mi. Moti ri.

Prabhupada: Awon ijuwe wa.. Ijuwe awon nkan wanyi wa nibe. Ijuwe iseda imi toje iseda mimo wa nibe. Iseda ile aye yi leleyi. Sanma, teyin ri, agbaye kan loje. Beena, aimoye agbaye to wa. gbogbo eleyi paapo, ni sanmo ile aye yi. leyin gbogbo e ni sanmo mimo, to gaj eleyi lo. awon isogbe mimo na wa. Beena iroyin tawa ti gba yi lati Bhagavad-gita, kama wa so nipa iwe mimo Veda. Bhagavad-gita, nkantan ka lojojumo leleyi, lori gbogbo agbaye, sugbon ko ye awon eyan. Sugbon won ti d'oluko Bhagavad-gtia, tabi lati mowipe " Oluwa nimi," Otan. Sugbon wan o fe gba iroyin kankan. Oni ese iwe kan ninu Apa kejo, paras tasmāt tu bhāvo 'nyo 'vyakto 'vyaktāt sanātanaḥ (BG 8.20). Pe iseda kan wa lori t'aye yi to wa taeraye. Iseda yi ma wa, lehin igbami atun paari. Sugbon iseda yi ma wa tayeraye. Awon nkan wanyi wa nibe. Been, awon isogbe na wa tayeraye. Awon eda nibe na wa tayeraye. Nkan ton pe ni sanatana niyen. Tayeraye nitumo Sanatana, laisi ipaari, laisi ibeere. Sugbon iseda yi, ara eda tani yi, oni ibeere ati ipaari, beena ounkoun, ised aye yi ni ibere ati opin. Beena egbe imoye Krsna yi fe ko awon eyan lati lasi iseda tayeraye yi.

Akoroyin: Iwaadi fun eda eyan.

Prabhupada: Beeni. Isewaadi to wa niyen. Gbogbo wa lafe ni idunnu nitoripe iwa gbogbo eda laye yi niyen. Iwa adayeba fun ni lati ni idunnu, sugbon ko mo bosele ni idunnu. Ofe ni inu re dun nibi ti awon nkan merin wanyi wa, awon isoro, ibimo, iku, aisan ati ojo arugbo. Opolopo awon oni sayensi fe ni idunnu lati fun awon eyan ni idunnu, sugbon onisayensi wo loti fi ipaari si iku, ojo arugbo, tabi aisan? Se onisayensi kankan ti danwo?

Akoroyin: Mio mo.

Prabhupada: Lehin na ki leleyi? Kilode ton se sowipe " Awa tini ilosiwaju to po, Ilosiwaju wo lani nipa awon nkan merin wanyi?" Kosi nkankan. sugbon won ni igberaga pe wanti ni ilosiwaju to po gan ninu eto ikeeko, sayensi. Sugbon awon nkan merin wanyi, won wa bonse wa.Se ri bayi? won ti ni ilosiwaju ninu eto iwosan, sugbon kos'ogun na tojepe teyin ba mu " Konisi aisan mo, se ri." Se ogun bayi wa? beena ilosowaju wo lonni? Dipo awon orisirisi aisan lon jade lojojumo. Won ti da ohun ijagun nuclear, kiniyen? Lati pa awon eyan. Sugbon eyin ti da nkan toma pa awon eyan to po si , ilosiwaju teni niyen. Awon eyan n'ku nigbogbo'gba sugbon eyin ti da nkan to ma pa won kiakia. Otan. Se nkan to da niyen? Beena kosi ona abayo kankan fun iku... Won fe fi ipaari si, olugbe eda eyan ton po si. Sugbon nibo ni ona abayo na wa? Niseju kan, eyan meta lon bisinu aye yi. Isiro to wa niyen. Beena kosi ona abayo kankan fun ibimo, kosi ona abayo fun iku, kosi ona abayo fun aisan kode si ona abayo kankan fun ojo arugbo. Oni oni sayensi pataki kan, Alakowe Einstein, oun na si ku lojo arugbo re. Kilode toun na o fi ipaari si ojo arugbo? Gbogbo wa lafe wa nigba ewe wa. Nibo ni ilana na wa? Beena awon eyan yi o fe mo bonsele fi ipaari si nitoripe o kajo nkan ton mo. Won kon saako lasan, otan. won o mo nkan ti isoro gidi wa je, ati basele yonju e. Ko jo won loju. Sugbon ninu egbe imoye Krsna yi. Awa ni ona abayo fun gbogbo awon isoro aye yi, ti awon eyan ba mu ni pataki. Beeni. Won ti juwe gbogbo e ninu Bhagavad-gita. E je kon gbiyanju lati ni oye re. Eje ka se idanwo yi. Kilode ton se nkan tonfe bose wu won?