YO/Prabhupada 0565 - I am Training them How to Control the Senses



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akoroyin: Eje kin bere nkan lowo yin tosese sele laipe yi. Asese ni bere awujo kan fun awon omode. Kini mofe so? Nkan toje eto ijiyan laarin okurin, tabi laarin awon okurin America ati ife obirin fun Oloruntabi awon ofin mewa wanyi, isoro to wa niyen, pelu eto imo ako ati abo. Ni ilu yi won ti ko wa wipe, imo ako ati abo nkan tio da ni. Ade tin jade kuro ninu ironu bayi, sugbon nigbati awon omode yi, ban dagba.. ni ilu wa yi, mio mo nipa awon ilu imi. A bere sini in isoro tole gan. Nisin nkan timon so yi nkan totii sele si gbogbo wa niyen.

Prabhupada: Beeni, gbogbo wa.

Akoroyin: Sugbon o dabi wipe awon ile ajosin ni ilu geesi wanyi o le wa ona lati fun awon eyan lasiko ewe yi nkan tonle mu dani lati ni oye pe nkan ton sele nkan to lewa ni, ati bonsele faramo. Kode si nkankan ninu asa awon geesin ton ko tabi ton salaaye si awon omo-okurin tab'obirin bonsele faramo, isoro nla loje. O sele si emi na. Gbogbo wa. Nisin ninu iwaasu yin seyin ni nkan teyin fuh awon omo-okurin wanyi tonle mu dani..

Prabhupada: Beeni.

Akoroyin: .. ton le mu dani, toba jebe, kiniyen?

Prabhupada: Beeni, beeni mon fun won.

Akoroyin: Kiniyen?

Prabhupada: Moti sofun awon akeeko mi kon se igbeyawo. Mio gba kon gbe pelu ololufe tio kin s'oko tabi iyawo si won. rara. Eyin gbodo se gbayawo, bii okurin jeje, e huwa to da si iyawo, e toju oko yin bi eni ton seto fun yin. Nkan ti mon ko won leleyi. Omo okurin yi sese se igbe yawo ojo merin seyin. Alakowe loje. Beena moni opolopo ninu awon akeeko mi tonti se igbeyawo, wonsi gbe ni alafia. Omo-obirin yi na ti fe oko, won gbe tele tele bi ololufe. Mio fe iru nkan bayi. Mio gba.

Akoroyin: E jekin bere, fun eni to ba je omo odun merinla, medogun, tabi merindinlogun?

Prabhupada: Nkankan niyen. Nkan imi niwipe awa ti ko awon omo okurin yi lati di brahmacari. Brahmacārī. Itumo Brahmacārī ni lati gbe aye akura.

Akoroyin: Hm?

Prabhupada: Howard, salaaye nipa iwa brahmacari.

Akoroyin: Beeni, oye mi.

Hayagriva: Ona lati ni idari lori iye ara w aniyen, osin ko wa basele ni idari lori iye ara wa. Nigbami, awon eyan okin se igbeyawo titi omo-okurin na tii pe odun 22, 23, 25.

Akoroyin: se ninu asa re.

Prabhupada: Beeni. Ama wa omo obirin kan pel'odun 16, 17 omo okurin na o gbodo ju 24 lo. Masi igbeyawo fun won, Seri bayi? ati nitoripe won ti fokan le imoye Krsna, ife fun imo ako ati abo to wa ninu okan won o po. seri bayi? Won ni nkan imi lati se. Paraṁ dṛṣṭvā nivartate (BG 2.59). seri bayi? Atii ropo re. Awa o sowipe " Ema se bayi" , sugbon ati fun won ni nkan to da ju. Seri bayi? Lehin na lesekese " ema se" yi ma wa toba ya. Se ri bayi?

Akoroyin: Lasiko to da.

Prabhupada: lesekese. Awa ti fun won ni nkan to da.

Akoroyin: kini yen?

Prabhupada: Gege bi awon omo-okurin at'obirin wa won sise ninu imoye Krsna, ninu ise ile-ajosin, wan ku aworan pelu oda, wan tewe jade, ati bayi bayi lo. Inu won si dun> won o lo si sinima, won o losi ile-ijo, won o moti, won o fa siga. Beena moti ko won lati ni idari lori ara won. Osi daju pe nitoripe gbogbo awon omo-okurin at'obirin wanyi, olugbe America niwon. Lati India ko nimoti mu won wa. Kilode ton se gba? Ilana eto yi dara gan, wansi feran re. Teyin ba pin ilana yi, gbogbo nkan ma yonju.

Akoroyin: Beena..

Prabhupada: Awa o sowipe ema ni asepo pel'obirin tabi kema ni imo ako ati abo. Nkan tan so ko niyen. Sugbon afe ke se gbogbo e lona to da ninu imoye Krsna. Ipinnu won gaju. Awon kekere ni gbogbo eleyi. Beena gbogbo nkan ti da.