YO/Prabhupada 0589 - We are Disgusted with these Material Varieties



Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972

Nitorina ife okan yi pe mofe wole sinu ara Oluwa, mofe di kankan pelu re... gege bi apeere pe " omi iwonba kekere nimi. Nisin mofe wole sinu omi okun nla. Nitora masi d'omi okun." Apeere ti awon alakowe Mayavadi man funwa niyen. taba po omi okun ati omi kekere na, wan ma di ikan. Irori nikan leleyi je. Aimoye moleku omi to wa ninu okun na. kasowipe eyin ti parapo pelu omi na, te wole sinu Brahman, samudra, omi okun, Lehin na eyin ma ba ategun lo, nitoripe omi sin ba ategu lo lati omi okun asi di sanma lehin na atun jabo sori ile, lehin na atun pada s'omi okun. Nkan ton sele niyen. Nkan ton pe ni āgamana-gamana, tonwa atun parapo. beena kini iwulo? Sugbon imoye Vaisnava yi niwipe awa o fe parapo pelu omi yi; awa fe d'ja ninu omi-okun yi. Nkan to da niyen. Teyin badi eja nla tabi eja kekere... kosejo. Teyin ba lo jina sinu omi yi, lehin na eyin o ni ba atugn lo. Eyin ma wa nibe.

Beena, odo metalokan, ina Brahman, Nirbheda-brahmānusandhi. Awon tonfe wole sinu igbese Brahman, fun awon eyan bayi ko daju. Wanti salaye ninu Śrīmad-Bhāgavatam: vimukta-māninaḥ. Vimukta-māninaḥ. Won rowipe "Nisin moti wole sinu ina Brahman. Moti wa dada." Rara, kon sebe tiosewu. Nitoripe won sowipe, āruhya kṛcchreṇa paraṁ padaṁ tataḥ patanty (SB 10.2.32). Lehin awon awe gbigba ati inira, eyan le wa sori ipo, param padam, toba si wole sinu ina Brahman. Beena latibe otun le subu. Asi sokale. Nitoripe Brahman, emi wayi, anandamaya lo je Bi Krsna, tabii eni to peju, Eledumare, ni ānandamayo 'bhyāsāt (Vedānta-sūtra 1.1.12), sac-cid-ānanda-vigrahaḥ (Bs. 5.1). Beena taba wole sinu igbese Brahman, eyan o le di anandamaya. Gege beyan ton lo soke lori ofurufu. Beena lati duru sori ofurufu, kon se anandamaya. teyin ba le ni idaabo ni awon isogbe kan, lehin na anandamaya niyen. Bibeko, eyin gbodo pada si isogbe yi. Beena nirviśeṣa, laisi orisirisi nkan, kolesi ananda. Nkan orisirisi ni iya igbadun. Awon nkan aye yi ti su wa. Nitorina awon eyan imi fe paari awon nkan orisirisi wanyi, awon elomi fe je ko posi. Sugbon eleyi o le funwa ni idunnu pipe tafe. teyin ba losinu ina Brahman, te gba idaabo lati Krsna tabi Narayana.... Aimoye awon isogbe to wa ninu in Brahman. Vaikunthaloka lonpe won. Vaikunthaloka to gaku ni Goloka Vrndavana. Beena teyin ba ni orire to po to lati ni idaabo ninu awon isogbe wanyi, lehin na eyin ma ni idunnu tayeraye ninu imoye. Bibeko, lati wole sinu ina Brahman nikan, nkan to da ko niyen. Nitoripe awa fe ananda. Beena ninu ipo tio si nkankan kole si ananda. Sugbon nitoripe awa o ni iroyin kankan, awon alakowe Mayavadi wanyi, lati awon isogbe Vaikuntha, won ma pada wa si ile aye yi. Āruhya kṛcchreṇa paraṁ padaṁ tataḥ patanty adhaḥ (SB 10.2.32). Ninu aye yi nitumo Adhaḥ. Moti salaye aimoye igba. Awon sannyasi pataki, ton fi ile aye yi sile pe mithyā, jagan mithyā, loje, ton ba ipo sannyasa, lehin asikp diie, won pada si eto oselu. Nitoripe won le sewaadi sinu Brahman. Wanti wole sinu awon ise wanyi fun ananda, Nitoripe ananda.. Awa fe ānandamayo 'bhyāsāt (Vedānta-sūtra 1.1.12). Beena ti ananda mimo yi o basi mo, o gbodo wa, won gbodo wa sori ipo kekere. Ipo kekere ni ile aye yi je. Apara. T'awa o ba le gba anada mimo yi, tabi igbadun to gaju yi, beena agbodo gba eyi to wa ninu aye yi. Nitoripe awa sife awon igbadun wanyi. Gbogbo eyan lon wa igbadun yi.