YO/Prabhupada 0637 - Without Krishna's Presence Nothing Can Exist



Lecture on BG 2.30 -- London, August 31, 1973

Beena Krsna ti salaaye koko oro yi, apareyam itas tu viddhi me prakṛtiṁ parāṁ yayedaṁ dhāryate. Jīva-bhūtāṁ mahā-bāho yayedaṁ dhāryate jagat (BG 7.5). Beena emi yi si dagba. Wanti salaaye gbogbo e ninu Bhagavda-gita. Awon isogbe orun nla wanyi, kilode tonse fo lori ofurufu? Wanti salaaye na. Gām āviśya aham ojasā dhārayāmi (BG 15.13). Egbiyanju ko ye yin. Ako afefe nla 747 le ko awon eyan to po to ogorun maarun si mefa, asi fo lori ofuru laisi isoro kankan. Kilode? Nitoripe oniwako na wa nibe. Konse ero lasan. Ema rowipe nitoripe o tobi gan nitorina losen fo. Rara. Oniwako ako afefe yi wa ninu e. Osi l'ero ninu re na, sugbon konse nitori awon ero ton to jo sinu loyeko fo, sugon nitori oniwako ako afefe na. Se ijiyan kankan wa? Ti oni wako yi o ba sini bee, gbogbo ero yi ma wolule. Lesekese. Beena oro to wa ninu Bhagavad-gītā, gām āviśya aham ojasā. Krsna lon wonu awon isogbe nla wanyi. Aṇḍāntara-stha-paramāṇu-cayāntara-stham. Wanti salaaye ninu Brahma-samhita.

eko 'py asau racayituṁ jagad-aṇḍa-kotiṁ
yac chaktir asti jagad-aṇḍa-cayā yad-antaḥ
aṇḍāntara-stha-paramāṇu-cayāntara-sthaṁ
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
(Bs. 5.35)

Ti Krsna o ba wole sinu awon elo aye yi, kosi nkankan tole sise. Aṇḍāntara-stha. Ninu agbaye yi, O wa nibe bi Garbhodakaśāyī Viṣṇu. Nitorina ni agbaye yi se wa. Aṇḍāntara-stha. Ninu agbaye yi awon eda too po gan wa ninu e. Awon atomu gan. sastra gan sowipe ninu awon atomu, Paramatma loje, o wa ninu ara eda gbogbo awon eyan. Konse ninu awon eda towa laye nikan ko, sugbon owa ninu paramanu, atomu. Nisin wan sewaadi lori agbara atomu. Sugbon o si le fun won. Wan sin pin, won pin si wewe. Nitoripe koi ti ye won pe Krsna wa ninu e.

Beena laisi Krsna ninu awon nkan wanyi, kosi bosele wa laaye. Nitorina, eni toba ni ilosiwaju ninu imoye Krsna, Krsna nikan lon ri. Ko foju si idaabo too wa nita. Nitoripe laisi Krsna kosi nkankan tole wa laaye. Ninu Caitanya-caritāmṛta, wan sowipe: sthāvara-jaṅgama. Awon eda meji lowa: awon ton rin ati awon tio le rin. sthavara ni awon tonle rin ati jangama ni awon tio le rin. Sthāvara-jaṅgama. Ati sthavara, eyi tio le rim. Beena awon eda mejeji lon wa. Been ele ri awon eda meji wanyi, awon imi wan rin, awon imi o le rin. Sugbon enito je maha-bhagavata o le ri awon eda meejeji, awon ton rin ati awon tio le rin. sugbon ko foju si eto pe won rin tabi won o le rin. Krsna lon ri. Nitoripe o mowipe agbara ninu eda to wa laye nitumo nkan ton rin. Beena agbara Krsna na ni agbara to wa ninu awon eda wanyi. Oun aye yi ni eyi tio le rin, Agbara Krsna na niyen.