YO/Prabhupada 0642 - Krishna Consciousness Turns this Material Body into Spiritual Body



Lecture on BG 6.1 -- Los Angeles, February 13, 1969

Olufokansi: Prabhupada? Eyin sowipe iwon emi eda pe ikan ninu irun ori ton gesi egbeerun mewa. Ninu odo metalokan, s'emi na si tobi to bayi?

Prabhupada: Hm?

Olufokansi: Emi yi, nigbato ba pada...

Prabhupada: Ipo re t'alakoko niyen. Boya ninu ile aye yi tabi ninu ile aye, nkankana loje. Sugbon lesekese teyin ba ni ara eda ninu ile aye yi, beena ninu odo metalokna eyin le ni ara mimo. So ye yin? Iwon kekere leyin je, sugbon emi na le fee si. Ifesi na si wa ninu aye yi, ti emi wa bati ni asepo peluu oun eleo aye yi. Ninu odo metalokan, ninu emi ni ifesi yi ma sele. Ninu ile aye yi emi nimi. Mo yato si ara eda yi nitoripe, oun eleo aye yi l'ara yi je, emi nimi. Agbara to lemi nimi, sugbon ara eda yi ko l'egbara kankan. ninu odo metalokan gbogbo nkan loje emi to lagbara. Kosi nkankan tio lemi. Nitorina ara won si l'emi. Gege bi omi pel'omi, omi, otan. Sugbon omi ati ororo - iyato towa niyen. Beena, emi nimi, Emi, ororo. Beena mowa ninu omi, iyato towa niyen. Sugbon tinba wa ninu ororo, lehin na gbogbo nkan ti da niyen. Beena awon alanigbagbo wanyi, kosi bonsele ni ara eda. wanfe duro sori ipo emi lasan. Iropnu ton ni niyen. Sugbon awa taje Vaisnava, awa fe sise fun Krsna, nitorina awa si ni owo, ese at'enu at'ahon, gbogbo nkan. Beena l'awa se ni ara eda yi. Beena beyin se ti ni ara eda yi lat'oyun iya yi, beena awa ti nii ara mimo yi ninu odo metalokan. Konse lati oyun iya, sugbon ilana towa niwipe ayin leri gba.

Olufokansi: Eyin o lese nkan bayi bi eke na. Koseni tole tan awon eyan je.

Prabhupada: Bi eke?

Olufokansi: Beeni, koseni tole ni ara mimo yi fun ara re, "Oh oye kin ni ara eda mimo yi. Ninu adase."

Prabhupada: Adase ninu imoye Krsna yi wa lati yi ara eda yi si mimo. Bawo lase lese? Moti fun yin ni apeere yi aimoye igba, pe teyin ba fi irin sinu ina. Bo sen gbona si, beena losen di ina. Ti irin na ba gbona gan - itumo re niwipe irin na ti ni awon amuye ina - teyin ba fi irin na fi kan ibikibi, oma huwa bi'na. Beena, ara eda yi, botilejepe nkan eda yi loje - awon apeere to po gan wa. Teyin ba fi ina monamona sori irin, konsepe irin na ti di in monamona. Sugbon toba ti ni ina monamona, teyin ba fowokan, ina monamona yi ma gbe yin lesekese. Gege bi irin ina. Kopa, kopa loje. Sugbon lesekese toba ni ina monamona yi, teyin ba fowokan, ina yi ma gbe yin. Awon apeere na po gan. Beena ti ara yin ba ya si mimo, lehin na kole si awon ise ile aye yi mo. Igbadun iye ara nitumo ise ile aye yi. beena beyan base yasi mimo to, beena ni awon idimu ile aye yi ma tan laaye re. Koni si awon ise ile aye yi mo.

Beena bawo losele se? Apeere na ti wa: Eyin gbodo fi irin na sinu ina ni gbogbo'gba. Eyin gbodo wa ninu imoye Krsna yi ni gbogbo'gba. Lehin na ara eda yin ma ya si mimo. Oni ofin ede Sanskrit kan ton pe ni mayat, mayat-pratyaya. Itumo Mayat, oro kan wa, bi svaramaya. Bi wura nitumo Svarnamaya Ton ba fi wura fise eyin le pe ni wura. Tonba fi awon nkan imi fise, sugbon wan fi wura fi kun, wura to po, wura na loje. Beena, ti ara eda yi ma kun fun awon ise mimo wanyi, nkan mimo na niyen. Nitorina awon eyan mimo, ni orile-ede yin ti awon eyan ba ku won ma sin won, sugbon ni India pelu awon ilana Veda, awon eyan pataki nikan ki won o le fina jo ara re. Nkan mimo niyen. Eyin oo le fina jo ara sannyasi nitoripe nkan mimo loje. Beena bawo lose le di mimo? Apeere kanna. Nigbati awon ise aye yi ba tan, ara eda yi ma yasi mimo. Beena ti ile aye yi ba kun fun ioye Krsna, koseni ton sise fun igbadun iye ara re, fun itelorun Krsna, ile aye yi ma di odo metalokan lesekese Asiko die loyeke lo lati ni imoye eto na. Ounkoun teyin ba lofun Krsna, fun itelorun Krsna nikan, nkan mimo niyen. gege bi awa sen lo gbohungbohun yi lati soro nipa Krsna, lehin na nkan mimo loje. Bibeko kini iyato laarin prasadam ati ounje lasan? Awasin pin prasadam, awon eyan ma sowipe, " kilode ti prasadam se wa? eso kanna t'awa n'je, teyin ba ti ge si wewe oti di prasadam?" Wonle sowipe. Bawo lose di prasadam? Sugbon prasadam loje. Looto prasadam loje. Gege bi apeere kanna, tinba mu irin, irin gbigbona, tinba sowipe " Ina leleyi." Elomi le sowipe, " Bawo lose je ina? Irin leleyi." Ma sowipe, " Fowokan." Ser i bayi? Awon apeere to wa leleyi, Nigbati awon ise yi - looto ninu imoye giga kosi nkankan toje ohun elo aye yi. Kosi oun elo aye yi, nkan mimo nigbogbo awon yi je, nitopripe mimo ni Krsna je. Emi ni Krsna, oun elo aye yi,ni agbara Krsna yi je. Nitorina emi na loje. Sugbon nitoripe won le lonilokulo, konse fun Krsna, nitorina nkan aye yi leleyi. Beena egbe imoye Krsna yi wa lati ya awon nkan si mimo. Gbogbo nkan, awon awujo, gbogbo nkan. Egbe to dara niyen. Oye ko ye awon eyan. toba le ya ile aye yi si mimo - looto ko daju, sugbon bi ero yi se je niyen. Sugbon ti awon eyan ba gbiyanju lati lo ilana mimo yi, ile aye re ma ya si mimo.