YO/Prabhupada 0647 - Yoga Means Connection With The Supreme
Lecture on BG 6.2-5 -- Los Angeles, February 14, 1969
Olufokansi: Ese iwe kerin. " Eni toti de ipo giga ninu yoga toba ti fi awon nkan aye yi sile Ko sise mo fun igbadun ara re, kode sise mo fun ijeere (BG 6.4)."
Prabhupada: Beeni. Ipo to gaju ninu ilana yoga leleyi, adase yoga. Onitoun ti de ipo yoga. Ipaarapo nitumo yoga. Gege bi apeere na. Kasowipe won ge ekana mi kuro. tabi apa ero. teyin ba yo kuko ninu ero, te fisegbe kan. teyin basi fi sinu ero na, asi bere sini sise. Cutacut, cutacut, cutacut, a sise. Oti paapo, nitumo yoga. Beena, awa ti yato nisin. Awon ise ile aye yi, ijeere aye yi, ilokulo asiko ni gbogbo wan. Mudha. Mudha. Wanti juwe won ninu Bhagavad-gita bi mudha. Asiwere nitumo Mudha. Kilode? Iru onisowo pataki bayi leyin pe ni oniranu, kilode? Ton pa aimoye dollara lojojumo. Sugbon wanti juwe wan, mudha, asiwere, nitoripe wo sise gan, kilon gbadun? Iwonba ounje, orun ati imo ako atii abo na lon gbadun. Otan. Eni ton pa aimoye dollar lojojumo, iyen o wipe o le ba aimoye obirin sun leekana. Rara. Kolese se. Agbara re lati ba awon obirin sun nkankanna loje pel'eni ton pa dollar mewa. Agbara re lati jeun nkankan na loje pelu okuron tonpa dollar mewa. Beena kole ronu pe " Igbadun aye mi nkankana loje pelu okurin tonpa dollar mewa. Lehin na kilode ti mosen sise gan bayi lati pa aimoye owo lojojumo? Kilode ti mosen lo agbara mi nilokulo?" Se ri bayi? mudha lon pe awon eyan bayi.
Na māṁ duṣkṛtinaḥ (BG 7.15) - looto oye ko sise, nigbato ba pa dollar to po yi lojojumo, oye ko lo asiko at'agbara re, lati fi ni oye nipa Oluwa, kinidi fun aye yi. Nitoripe koni isoro oro aje kankan. Beena osi ni asiko to po gan, o le lo ninu imoye Krsna tabi Oluwa. Sugbon koni se. Nitorina lose je mudha. Ketekete nitumo Mudha. Ogbon ori re o da. Eni toba ti wole sinu ipo yoga onitoun ti fi gbogbo ife okan aye yi sile. teyan ba ti wa pipe ninu yoga, lehin oni itelorun. Koni ife okan aye yi mo. Ipo pipe niyen. Ko sise mo fuin igbadun ara re tabi ijeere aye yi. Itunmo ise ijeere wanyi niwipe, eyin le pa owo fun igbadun iye ara yin. Eyan sin sise fun igbadun iye ara yin, eyin pa owo jo fun igbadun iye ara yin. Kasowipe awon ibajade rere. Gege bi Veda se so, awon ibajade orire, nibikibi, Teyin ba sorire, teyin ba fun eyan lowo lofe, iwa rere niyen. Teyin ba fun awon l'owo lati fi da ile-iwosan, teyin ba fun awon l'owo lati fi si ile-iwe, ile eko ofe, iwa rere leleyi. Sugbon fun igbadun iye ara lonwa fun. Kasowipe mofe fun awon eyan l'eeko lofe. Laye atunwa, emi na ma ni awon nkan fun ikeeko to da, Ma di alakowe, tabi kini ipo to da. Sugbon leyin gbogbo e, kini eroo to wa nibe? tinba ni ipo to da, tinba ni ipo to da, bawo nimo sefe lo? Fun igbadun ara mi. Dada, otan. Nitoripe mio le lo fun nkankan. Ise ijeere leleyi. Tin ba los'orun, ipo aye to da. Kasowipe, ni orile America, eyin ni ipo aye toda ju India lo. Sugbon kinitumoi, " ipo aye to daju?" Ounjue jije kanna, sisun, l'ona to da, otan. Eyin o se nkan imi to da., Awon na jeun. Wan je ounje tio fibe da, eyin na jeun dada. Sugbon eyin na jeun, Ko ju bee lo. Beena ipo aye mi koni nkankan se pelu imoye mimo. Jijeun to da, sisun, imo ako ati abo, otan. Beena ise ijeere niyen. Igbadun iye ara imi ni ise ijeere wanyi, sugbon lori igbadun iye ara nigbogbo e. lati ni ipaapo pelu Eledumare nitumo yoga. Nigbateyin ba ni asepo peluu Eledumare, lesekese, gege bi Dhruva Maharaja. Lesekse teyin ba ri Oluwa, Narayana... Omode na sinse awon awe inira, lati ri Olorun. O si ri. Sugbon nigbato ri, lehin na o sowipe, svāmin kṛtārtho 'smi varaṁ na yāce (CC Madhya 22.42). " Oluwa mi, moti ni itelorun pipe. Mio fe nkankan , ibukun kankan lati yin." Nitoripe kini wulo ibukun yi? Itumo ibukun yi niwipe eyin ma ni ijoba to da tabi iyawo to da, tabi ounje toda, nkan toda. Awon nkan wanyi lawa n'pe ni ibukun. Sugbon lootoro nigbateyin ba ni asepo pel'Oluwa, eyin o ni fe iru ibukun bayi. Oti ni itelorun. Itelorun pipe. Svāmin kṛtārtho 'smi varaṁ na yāce (CC Madhya 22.42).
Itan Dhruva Maharaja timo ti sofun yin tele, pe omode odun marun loje. iyawo baba re si buu. O joko sori ese baba re, tabi of e joko sibe. iyawo baba re si sofun wipe, " Oh, ma joko sori ese baba re nitoripe lat'oyun mi ko loti wa." Beena nitoripe omo ksatriya loje, botilejepe omo odun maarun, inu si bi gan. Beena o si lo ba iya re. " Mama mi, iyawo baba mi ti bu mi bayi." O si bere sini sukun. Iya re sowipe, " Kilofe kin se omo mi? Baba re nife fun iyawo re ju mi lo. Kini mole se?" "Rara, Mofe ni ijoba bi ti baba mi. E sofunmi bi mosele ri gba." Iya re sofun, " Omo mi, ti Krsna, Oluwa, ba fun e nibukun na, ole rigba." "Nibo l'Oluwa yi wa? Iya sowipe, " Oh mo gbowipe Oluwa n'be ninu aginju, awon alufa man losibe lati lo ba." Beena o si losinu aginju na, osi gbawe pelu inira to po, osi ri Oluwa. sugbon nigbato ri Olorun, Naraya, ijoba baba re o joo loju mo. Kosi joo loju mo. O sowipe, " Olorun mi, moti ni itelroun. Mio fe nkankan mo, ijoba temi , ijoba baba mi." Osi salaaye wipe, Mo jade wa sewaadi fun okuta sugbon moti ri awon okuta iyebiye." Beena itumo re niwipe oti ni itelorun. Nigbateyin ba ni asepo pel'Oluwa, lehin na eyin ma eyin le ni aimoye igbadun ju bose wa ninu aye yi. Imo Olorun niyen. Ipo pipe yoga niyen.