YO/Prabhupada 0665 - Krishna's Planet, Goloka Vrndavana, Is Self-illuminated
Lecture on BG 6.13-15 -- Los Angeles, February 16, 1969
Tamal Krishna:idaduro aye iyonda onje ki eyon wole si inu emi orun, ti ijoba olorun apejuwe ijoba olorun ni kedere ninu Bhagavad-gītā si ibi ti kosi iwulo fun orun tabi osupa, tabi ina ti oloyinbo
prabhupada: nisin wa ri pe ninu Bhagavad-Gita, a ti tele morope ninu ipin keji osowipe, lonakona bi oshee wa niyen
- na tad bhāsayate sūryo
- na śaśāṅko na pāvakaḥ
- yad gatvā na nivartante
- tad dhāma paramaṁ mama
- (BG 15.6)
nisin krsna olorun shee alaye ijoba re,bi oshee ri ni orun yen,ibi ti ijoba mi wa, ko si idi tianilati lo imole orun ko si idi tianilati lo imole osupa,kosi idi tianilati lo inaa nisin iwo o le ri iru ijoba ninu agbaye yi ti oba rin irin ajo pelu sputnik abi ero Kankan, iwo ma ri awon ibi ti ko si imole orun,ti ko si imole osupa imole osupa sanlalu,ni gbogbo agbaye ni imole orun wa ibo ni wa ti ri ibi ti owa beee? eyi tumosi wipe kosi ibeyen koja orun lo won so naa pe: paras tasmāt tu bhāvo 'nyo 'vyakto 'vyaktāt sanātanaḥ (BG 8.20). koja ile aye iseda ile aye iyonda yi atun ni emi iseda miiran ao mo iseda ibiyi ti aye iyonda,ati kinni amawamo nipe emi iseda oni lati gbo latiodo krsna olorun ti o gbe nibe bibeko wa di oponu ni gbogbo aye re.ibiyi ni alaye na wa bawo ni iwo le mor owun tio mor,ti o le de,ti o le mor,oye re kosi ni pipe bawo ni iwo le mor? oni lati gbo na ni bi oshe je pe oni lati gbo nipa baba re lati odor mama re, ko si ona miiran baba shee ajeri, iya na shee ajari," wipe baba re ni,o ni lati gba o le sadanwo,koja ona re lehinna, ti ogba fe mor nipa emi orun ati ijoba olorun oni lati gbo lenu eyan to ni ase kosi oro ibeere tabi adanwo oye, ko gbo nikan ni so gbigbo tumosi pe bi iwo shee ma ni igbagbo fun okurin ton shee jeje bi baba re, ti o ba gbo ase iyare bekan na ninu iwe vediki,ti awa gba gege bi iya,ase iya,oye iya ase iya.. Veda-mātā.ni won pe ni Veda-mātā veda tumosi oye ti angba lati odor iya wa veda-mata, oye iya, oni lati mo eni ti krsna olorun je ibibiyi de ni krsna olorun ton shalaaye funrare, oni lati gbagbor lehinna iwo ma wa ni oye,bibeko kosi ona imiiran seese iwo o le shee idanwo Kankan. tesiwaju
Tamal Krishna:" gbogbo aye ni ijoba oorun wa ni itana funrawon,bi ti orun oorun ile aye iyonda
prabhupada:won waabe nitoripe nibiyi,aye yii,ile aye yi ko le tanna funrare nitorina onidi imole tonwa lati odor orun, abi eyi tonwa lati odor ina tabi osupa sugbon nibeyen are krsna olorun ni imole tin wa, ijoba re na wa apeere kan ni orun, ara orun ni imole isogbe reee ti wa ti koba si ninu aaye iyonda yi isogbe orun ti o ni Imole,kin ni ama wo soooo nipa ijoba olorun ni gbogbo isogbe to wa nibe,won wa ni imole,imole jade lara won,gegebi okuta-iyebiye okuta-iyebiye bi diamondii, okan lara okuta-iyebiye diamondii tio ba fi si iyara to lokuku,yio tanna imole funra re kosi ibeere imole re lati mor pe diamondii ni oun de tanna funrare ni ile aye iyonda yi, wa ri pe ijoba krsna,krsna ganganGoloka Vṛndāvana o mole funrare won ti fun wa ni aworan nini Śrīmad-Bhāgavatam,pe omonle funra re opolopo million aye lo wa ni orun,tesiwaju