YO/Prabhupada 0718 - Sons and Disciples Should Be Always Chastised



Morning Walk -- February 1, 1977, Bhuvanesvara

Olufokansi (1): Srila Prabhupada, gege bi itan te sofun wa nipa olumogaji, bawo lasele sofun awon oni sayensi kon gba imoye Krsna ati Bhagavad-gita? Bawo lasele sofun awon oni sayensi kon gba imoye Bhagavad-gita? Isoro towa niwipe..

Prabhupada: Rara, otooro ni, eyin o le f'agidi se. otooro niyen. Ti koba je otooro, agidi niyen. Toba je ooto, ele f'agidi se, gege bhi baba sen f'agidi fun omore, " Losi ile-iwe." Nitoripe o mo wipe lai kawe ile aye omo re ma baje, nitorina losen lagidi. Wan l'agidi funmi na. Mio si feran lati lo si ile iwe. (Erin) Iya mi si f'agidi mumi llo. baba mi o lo agidi. Mama mi si wa okurin kan lati mumi losi ile-iwe. Nigbami agbodo lagidi.

Gurukṛpā: sugbon olorin niyen. Awon obi yin dabi Olori fun yin.

Prabhupada: Beeni.

Gurukrpa: Sugbon awon eyan yi o fe gba pe olori niwa. Wan sowipe " nkankan laje. Niotooro gan mo moju e lo."

Prabhupada: Iranu imi tun niyen, iranu imi. Baba-iya, awon lon toju wa, wan le lo agidi fun wa.

Svarupa Damodara: A le fi ogbon to ju won lo fihan won.

Prabhupada: Beeni. Omode le je ode, sugbon awon obi re o ni fe ko wa bayi titi lo. O le l'agidi. Ijoba na, Kilode ti awon olopa se wa? Teyin ba fe di omo odaran, wansi f'agidi fi ko yin. Agbodo lo agidi.

Olofokansi (1): Sugbon omode na gbodo ri wipe nkan to da lon se fun.

Prabhupada: Omode o le. Oniranu loje. Oye kan fi bata fi na legba. Lehin na a ri. Omode na o le ri. Putraṁ ca śiṣyaṁ ca tāḍayen na tu lālayet (Cāṇakya Paṇḍita): "Awon omde at'akeko agbodo jagbe mo won." Oro Canakya Pandita niyen." E ma bawon je." Lālane bahavo doṣās tāḍane bahavo guṇāḥ...Teban soro die die siwon , e ma bawon je. Teba jagbe mo won, wan ma deyan to da. Nitorina, boya omo tabi akeko, egbodo g=jagbe mo won." Oro Canakya pandita niyen. Kosejo pe eyin soro die die si won.

Gurukrpa: Awon eyan fe ke soro to da si won> Won o fe ke jagbe mo won.

Prabhupada: Ipo awon akeko niyen. Caitanya Mahāprabhu sowipe, guru more mūrkha dekhi' (CC Adi 7.71). Caitanya Mahāprabhu toje Olorun fu ara re lo so bayi pe "Guru Maharaja mi sowipe ode ni moje." kigbe mo. Agbodo lo nigbami. Cāṇakya Paṇḍita, toje Oluko pataki, na funwa ni imoran, tāḍayen na tu lālayet: E kigbe mo won. Bibeko, won ma baje."

Svarūpa Dāmodara: Omode to logbon mope fun nkan to da lonsen kigbe mo.

Prabhuapda: Beeni. Beeni.