YO/Prabhupada 0720 - Control Your Lusty Desire by Krishna Consciousness



Lecture on BG 16.10 -- Hawaii, February 6, 1975

Aja sin kigbe " Yow! Yow! Yow!" Ko mope wanti fokun so mole." (erin) Ode loje, lesekese ti oga re bade - Wasi bi" (erin) maya l'oga. " Oniranu yi, wasi bi." " Beeni." Inure sin dun" " Eyan pataki nimi." Awujo aja leleyi, naṣṭa-buddhaya, ogbon won ti sonu... Awon eyan tio logbon. Kāmaṁ duṣpūram. Beena kāmam, awon ifekufe l'okan wan... ifekufe kun ninu okan won. Awa o le fipami. Sugbon ema se ni duṣpūram - nkan ti o ni itelorun. Lehin na o tan. E je ko paari. E je kole paari. Nitorina, gege bi awujo Veda, ifekufe yi wa, sugbon eyin o le lo afi teba fe bimo. Nkan ton pe ni puram niyen, itumo re ni iwonba die.

Beena lon se ko awon brahmacari. titi de odun marun le logun, kole ri obirin. Ko tie le foju ri. Brahmacari leleyi. Kole ri. Asi dagba bayi, o si le tesiwaju bi brahmacari Naiṣṭhika-brahmacārī. Sugbon ti ko bale lese, o le fe iyawo. Ile aye gṛhastha life, olori ile. Nitoripe laarin odun maarun le logun si odun aadota, igba idodo leleyi, ifekufe si le gan lokan re. Eni tio ba le faramo.. fun gbogbo eyan ko. Awon naiṣṭhika-brahmacārī po gan. Naiṣṭhika-brahmacārī - won o mo obirin ninu gbogbo aye won. sugbon kolese se ninu asiko tawa yi, kolese se na lati di brahmacari na. asiko tawayi yato. Nitorina ele lo ifekufe yin ninu imoye Krsna. Bibeko kolese se.

Yad-avadhi mama cetaḥ kṛṣṇa-padāravinde. O ni Oba kan toni ifekufe gan l'okan. O si fi iru ile aye yi sile to di olufokansi. Nigbato si wa lori ipo to da, o sowipe, Yāmunācārya— oun ni guru Rāmānujācārya - O sowipe yad-avadhi mama cetaḥ kṛṣṇa-padāravinde: "latigbati mo ti fi okan mi ninu ise ese bi ododo ti Krsna," yad-avadhi mama cetaḥ kṛṣṇa-padāravinde nava-nava-dhāmany udyataṁ rasa, "lojo juo tin mon sise fun Krsna, mon ri awon igbadun to yato." teyan ba wa ninu ile aye mimo oma ri awon nkan wanyi igbadun mimo, lati ise s'Olorun. Ile aye mimo leleyi. Beena Yāmunācārya sowipe, yad-avadhi mama cetaḥ kṛṣṇa-padāravinde nava-nava-dhāmany udyataṁ rantum āsīt: "Nisin ti mon gbadun awon ijeere mimo lati ise tin monse fun Krsna," tad-avadhi, " latigbana," bata nārī-saṅgame... Nigbami awa man gbadun awon igbadun aye yi bi imo ako ati abo. Nkan ton pe ni nārī-saṅgame niyen. Obirin nitumo Nari, asepo nitumo sanga. gege na awon eyan ton sise yiti wan o ba ni asepo mo, won ma bere sini ronu nipa re. Beena Yamunacarya sowipe "Asepo pelu obirin nikan ko, sugbon tin ma ronu nipa iru nkan bayi," tad-avadhi bata nārī-saṅgame smaryamāne, smaryamāne, "ironu lasan," bhavati mukha-vikāraḥ, oh, lesekese ni okan ma yi kuro: Iru nkan iranu wo leleyi?" Suṣṭhu niṣṭhī...( o se beni ton tuto) Ile aye pipe leleyi (erin). Aye pipe. Beeni. tawa ban ronu nipa imo ako ati abo, ironu Won ka awon iwe nipa imo ako ati abo. aasepo ninu ironu wa niyen. Asepo gidi ati tironu. Eyna gb o bo lowo awon ironu wanyi, kema bosinu nkan tio le teyin lorun - lainiteloun, duspuram.