YO/Prabhupada 0740 - We Have to See Through the Pages of Sastra
Lecture on CC Adi-lila 1.7 -- Mayapur, March 31, 1975
Advaita acyuta anādi ananta-rūpam. Kṣīrodakaśāyī Viṣṇu fun ara re leleyi towa ninu okan gbogbo wa. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati (BG 18.61). īśvara, antaryāmī, to wa l'okan gbogbo wa, ni Kṣīrodakaśāyī Viṣṇu. ninu okan wa nikan ko, sugbon ninu gbogbo nkan agbaye yi. Aṇḍāntara-stha-paramāṇu-cayā... Paramāṇu. atomu nitumo Paramāṇu bayi ni Visnu se wa nigbogbo ibikibi. Koleye wa sugbon pelu ore-ofe Krsna, a le ni oye nipa ijuwe to wa ninu sastras. Bibeko, aw o le mo bi awon nkan wanyi se fe sele. Abodo gba be. Śāstra-cakṣuṣaḥ. Agbodo ri latinu awon iwe sastra. Bibeko kolese se.
Beena teba fe mo visnu-tattve, taba fe mo Krsna, Ipo to ni, wanti juwe re ninu sastra. taba si gba lai fi nkan kun, lai ni ogbon kankan.. kolese se. Agbodo gba bee. Nitorina awon sastra ti so funn wa wipe. Bhagavad-gītā ti sowipe, yaḥ śāstra-vidhim utsṛjya vartate-kāma-kārataḥ (BG 16.23): " teyin o ba tele ijuwe sastr, teba si se nkan to wunyin." lehin na siddhiṁ sa avāpnoti, " lehin na kosi besele di pipe." Agbodo tele sastra; bibeko kos'ona imi lati fi ni oye nipa ipo Krsna, bo sen wa bi Visnu, tabi Narayana. NIgbami awon eyan man jiyan pe lati Visnu ni Krsna ti wa. Otooro niyen na otooro na loje, pe ti awon eda ba fe wa, lati Ksirodakasayi Visnu lon tin wa. Sugbon Ksirodakasayi Visnu lati Krsna loti wa. Oro yi le sugbon taba tele awon sastra ta gba ole ye wa die.
Beena Nityānanda Rāma... yasyāṁśa sa nityānanda-rāmaḥ. Nityānanda ni Balarāma. Nitorina lose sowipe, nityānandākhya-rāmaḥ. Gege bi Śrī Caitanya Mahāprabhu... Kṛṣṇāya-kṛṣṇa-caitanya nāmne: " Mo si teriba si Krsna toti farahan nisin bi Krsna Caitanya." Krsna loje. Beena, Balaramani Nityananda. balarāma hoilo nitāi. Nitorina lonse sonibi pe nityānandākhya-rāmaḥ: Rāma, Balarāma, sugbon nisin oti farahan bi Nityananda."
Ese pupo.
Olufokansi: Haribol(Ipaari)