YO/Prabhupada 1061 - Ninu Bhagavad-gita, lati ni oye nipa ooto oro marun orisirisi ni koko oro re je: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1061 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1060 - Afi teyan ba gba Bhagavad-gita pel'emi to resile...|1060|YO/Prabhupada 1062 - Awa sin'iwa lati fe ni idari lori iseda aye yi|1062}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|G9JE15msxco|In this Bhagavad-gita the Subject Matter is Comprehending Five Different Truths - Prabhupāda 1061}}
{{youtube_right|G9JE15msxco|Ninu Bhagavad-gita, lati ni oye nipa ooto oro marun orisirisi ni koko oro re je<br />- Prabhupāda 1061}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660219BG-NEW_YORK_clip05.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660219BG-NEW_YORK_clip05.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 30: Line 33:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Beena Oluwa Krsna, tio soka le wa, yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati ([[Vanisource:BG 4.7|BG 4.7]]), lati da ipinnu aye gidi. Ti awon eda eyan ba gbagbe ipinnu aye yi, ipinnu gidi aye eda eyan, lehin na dharmasya glanih loje, idamu fun ise eda eyan. Beena ninu aimoye eda eyan, eyan toba ji emi imoye nipa ipo re so ke, fun eyan bayi lon se s'oro Bhagavad-gita. Okunkun aye yi ti gbe wa mi bi ekun, Olorun si ni ore-ofe to po gan fun awon eda aye yi, nipataki fun awon eda eyan, Oti salaye lori Bhagavad-gita, tosi so ore re Arjuna di akeeko re.  
Koko ọrọ Bhagavad-gita jẹ oye ijinlẹ ti ipilẹ òtítọ marun. Be ni Oluwa Krsna, ti sọkalẹ wa, yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati ([[Vanisource:BG 4.7 (1972)|BG 4.7]]), lati tun fi eredi aye gidi mulẹ nigba ti eniyan ba gbàgbé ero naa, eredi ile aye ẹya ẹda eniyan, lehin na dharmasya glanih loje, idamu fun ise eda eyan. Ti oran ba se ri bayi, ninu ọpọlọpọ, awọn eniyan ti wọn ti daji, ti o fi inu l’oye ipo rẹ, ani oun si ni ẹni na ti wọn sọ iwe mimọ Bhagavad Gita yi fun. Okunkun aye yi ti gbe wa mi bi ẹkun, ṣugbọn ãnu Oluwa pọ to bẹ lori awọn ẹda alaaye, paapa awọn eniyan, fun idi eyi ni O se sọ Bhagavad Gita, ti o ṣi fi Arjuna ọrẹ rẹ ṣe akẹkọ.  

Arjuna toje alabasepo ti Krsna si gaju gbogbo awon alaimokan ninu aye yi. Sugbon Arjuna si wa ninu aimokan lori ile ogun Kuruksetra lati le bi Olorun nipa awon isoro aye yi beena Olorun le salaaye fun ijeere awon iran ojoowaju eda eyan, lati le seto igbese aye re gege na ki ipinnu aye re bale wa ni pipe.  
Bi Arjuna se jẹ ojisẹ Oluwa Ọlọrun, iye rẹ kọja gbogbo aimọkan, ṣugbọn Arjuna wa fi aimọkan se wahu lori papa oju ogun Kurukṣetra lati le se ibéèrè lọwọ Oluwa Ọlọrun nipa awọn isoro aye, ki Oluwa le se alaye wọn fun anfani iran awọn ọmọ eniyan lọjọ iwaju ki o se ètò ipinnu aye rẹ ki o si le huwa ni ibamu ati ki o se isẹ rẹ, isẹ aye ọmọ eniyan ni aṣepé.  

Beena ninu Bhagavad-gita otoo oro marun orisirisi lowa ninu re. Otooro talakoko niwipe, Ta l'oloorun je. Ipo talakoko ninu ikeeko nipa sayensi Olorun. Beena wanti salaaye nipa sayensi Olorun nibi. Eyi to kan, ni ipo awon eda aye yi, jiva. Isvara ati jiva. Olorun, Eledumare, isvara loruko re je. Oludari nitumo Isvara, ati jiva, awon eda aye yi.. Awon eda o kin se isvara tabi oludari. Awon lon wa labe idari Oluwa. Tin ba rowipe "koseni toni idari lori mi, mole se bi mosefe," iwa eyan to logbon ko niyen. Gbogbo awon eda lon wa labe idari nkan Ninu aye yi, o wa labe idari nkan. Beena ninu Bhagavad-gita koko oro to wa ni eto isvara, oludari to gaju, ati awon eda ton wa labe idari re, ati prakrti, iseda aye yi, ile aye yi. aasiko, tabi igbese aye wa ninu ile aye yi, tabi iseda gbogbo agbaye, ati iye asiko, tabi asiko taye raye. ati karma. Ise nitumo Karma. Gbogbo nkan, gbogbo agbaye yi lo kun fun orisirisi ise. Awon eda nipataki, gbogbo won lon sise orisirisi. Beena agbodo keeko lati Bhagavad-gita, isvara, eni t'olorun je, jiva, tani awon eda wanyi, ati prakrti, nkan ti ile aye yi je, ati bi asiko se ni idari lori re, ati iru ise wo ni awon ise wanyi?
Bẹẹ ninu Bhagavad-gita yi awọn oko ọrọ ibẹ jẹ oye ijinlẹ ti ipilẹ òtítọ marun. Ni akọkọ o ti salaye imọ Ọlọrun. O jẹ ti iwadi alakọkọ ti imọ ijinlẹ Ọlọrun. Imọ ijinle ti Ọlọrun ti ni alaye nibi. Lẹhinna ipo ti o jẹ ofin fun awọn ẹda alãye, jīvas. Isvara ati jiva. Olorun, Eledumare, isvara loruko re je. Oludari nitumo Isvara, ati jiva, awon eda alaaye yi.. Jīvas, awọn ẹda alãye ti wọn ndari wọn, wọn ki ise īśvara Ti mo ba sọ pé "ko si ẹniti o ndari mi, ati pe mo jẹ ominira, o jẹ alainironu. Ni gbogbo ọwọ ni ẹda alãye ti ni idari, O kere ju ninu igbesi aye hilahilo rẹ Bẹ lo jẹ ti koko-ọrọ inu Bhagavad-gita kan īśvara, oludari ti o ga julọ, ati jīvas, awọn ẹda alãye ti wọn ndari. Prakriti, awọn ohun elo ti isẹda. ati akoko, iye ọjọ aye ti gbogbo agbaye, tabi asehan ti isẹda ati iye asiko, tabi asiko taye raye. ati karma ti o tumo si aṣayan iṣẹ-ṣiṣe. Gbogbo nkan, gbogbo agbaye, ọna-isalu kun fun orisirisi akitiyan. Awon eda nipataki, gbogbo ẹda alaaye ni wọn nkopa ninu orisirisi akitiyan. Bẹẹ ninu Bhagavad Gita a gbọdọ kọ ohun tí Ọlọrun jẹ, isvara, jiva,kini awọn ẹda alaaye jẹ, kini prakriti, kini agba aye, bi akoko se nse ndari rẹ, ati kini akitiyan awọn ẹda alãye.

Nisin ninu awon eto marun wanyi, ninu Bhagavad-gita wanti daale pe, Olorun, tabi Krsna tabi Brahman tabi Paramatma... Ele pe ni ounkoun teba fe. Sugbon Olori to gaju. Oni olori to gaju gbogbo wa to wa. Beena olori to gaju yi lo lagbara ju. Awon eda aye yi sini iwa bi oludari to gaju. gege bi oludari to gaju, Olorun, Oun loni idari lori agbaye, lori ile aye yi, Wan ma salaaye ninu awo apa iwe ti Bhagavad-gita pe iseda aye yi kole danikan wa. On sise labe itosona Olorun. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram ([[Vanisource:BG 9.10|BG 9.10]]). "Ile aye yi n'sise labe itosona mi, "mayādhyakṣeṇa, "labe itosona ijoba mi."  
Lara awọn ipilẹ koko ọrọ marun wọnyi ninu Bhagavad-Gita o ti wa ni idasilẹ, wipe Ọlọrun Eledumare, tabi Krsna, tabi Brahman, tabi oludari to ga julọ, tabi Paramātmā Ẹ le lo orukọ ti ẹ ba fẹ. Sugbọn oludari to ga julọ. Oludari ti o ga julọ wa. Oun ni atobi julọ Didara awọn ẹmi alààye dabi ti oludari to ga julọ Gege bi oludari to gaju, Olorun, Oluwa ni iṣakoso lori gbogbo asayan àlámọrí ti isẹda Bi yio se wa ni alaye ninu awọn ori iwe ikẹhin Bhagavad Gita wipe isẹda aye ko ni ominira tikararẹ. Ni abẹ akoso Ọlọrun Ọba ni o ti nṣiṣẹ. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram ([[Vanisource:BG 9.10 (1972)|BG 9.10]]). " Isẹda aye yí nṣiṣẹ labẹ itọsọna mi." "mayādhyakṣeṇa, "labe itosona ijoba mi."
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:29, 14 June 2018

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Koko ọrọ Bhagavad-gita jẹ oye ijinlẹ ti ipilẹ òtítọ marun. Be ni Oluwa Krsna, ti sọkalẹ wa, yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati (BG 4.7), lati tun fi eredi aye gidi mulẹ nigba ti eniyan ba gbàgbé ero naa, eredi ile aye ẹya ẹda eniyan, lehin na dharmasya glanih loje, idamu fun ise eda eyan. Ti oran ba se ri bayi, ninu ọpọlọpọ, awọn eniyan ti wọn ti daji, ti o fi inu l’oye ipo rẹ, ani oun si ni ẹni na ti wọn sọ iwe mimọ Bhagavad Gita yi fun. Okunkun aye yi ti gbe wa mi bi ẹkun, ṣugbọn ãnu Oluwa pọ to bẹ lori awọn ẹda alaaye, paapa awọn eniyan, fun idi eyi ni O se sọ Bhagavad Gita, ti o ṣi fi Arjuna ọrẹ rẹ ṣe akẹkọ.

Bi Arjuna se jẹ ojisẹ Oluwa Ọlọrun, iye rẹ kọja gbogbo aimọkan, ṣugbọn Arjuna wa fi aimọkan se wahu lori papa oju ogun Kurukṣetra lati le se ibéèrè lọwọ Oluwa Ọlọrun nipa awọn isoro aye, ki Oluwa le se alaye wọn fun anfani iran awọn ọmọ eniyan lọjọ iwaju ki o se ètò ipinnu aye rẹ ki o si le huwa ni ibamu ati ki o se isẹ rẹ, isẹ aye ọmọ eniyan ni aṣepé.

Bẹẹ ninu Bhagavad-gita yi awọn oko ọrọ ibẹ jẹ oye ijinlẹ ti ipilẹ òtítọ marun. Ni akọkọ o ti salaye imọ Ọlọrun. O jẹ ti iwadi alakọkọ ti imọ ijinlẹ Ọlọrun. Imọ ijinle ti Ọlọrun ti ni alaye nibi. Lẹhinna ipo ti o jẹ ofin fun awọn ẹda alãye, jīvas. Isvara ati jiva. Olorun, Eledumare, isvara loruko re je. Oludari nitumo Isvara, ati jiva, awon eda alaaye yi.. Jīvas, awọn ẹda alãye ti wọn ndari wọn, wọn ki ise īśvara Ti mo ba sọ pé "ko si ẹniti o ndari mi, ati pe mo jẹ ominira, o jẹ alainironu. Ni gbogbo ọwọ ni ẹda alãye ti ni idari, O kere ju ninu igbesi aye hilahilo rẹ Bẹ lo jẹ ti koko-ọrọ inu Bhagavad-gita kan īśvara, oludari ti o ga julọ, ati jīvas, awọn ẹda alãye ti wọn ndari. Prakriti, awọn ohun elo ti isẹda. ati akoko, iye ọjọ aye ti gbogbo agbaye, tabi asehan ti isẹda ati iye asiko, tabi asiko taye raye. ati karma ti o tumo si aṣayan iṣẹ-ṣiṣe. Gbogbo nkan, gbogbo agbaye, ọna-isalu kun fun orisirisi akitiyan. Awon eda nipataki, gbogbo ẹda alaaye ni wọn nkopa ninu orisirisi akitiyan. Bẹẹ ninu Bhagavad Gita a gbọdọ kọ ohun tí Ọlọrun jẹ, isvara, jiva,kini awọn ẹda alaaye jẹ, kini prakriti, kini agba aye, bi akoko se nse ndari rẹ, ati kini akitiyan awọn ẹda alãye.

Lara awọn ipilẹ koko ọrọ marun wọnyi ninu Bhagavad-Gita o ti wa ni idasilẹ, wipe Ọlọrun Eledumare, tabi Krsna, tabi Brahman, tabi oludari to ga julọ, tabi Paramātmā Ẹ le lo orukọ ti ẹ ba fẹ. Sugbọn oludari to ga julọ. Oludari ti o ga julọ wa. Oun ni atobi julọ Didara awọn ẹmi alààye dabi ti oludari to ga julọ Gege bi oludari to gaju, Olorun, Oluwa ni iṣakoso lori gbogbo asayan àlámọrí ti isẹda Bi yio se wa ni alaye ninu awọn ori iwe ikẹhin Bhagavad Gita wipe isẹda aye ko ni ominira tikararẹ. Ni abẹ akoso Ọlọrun Ọba ni o ti nṣiṣẹ. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram (BG 9.10). " Isẹda aye yí nṣiṣẹ labẹ itọsọna mi." "mayādhyakṣeṇa, "labe itosona ijoba mi."