YO/Prabhupada 0733 - Time is so Valuable, if You Pay Millions Gold Coins, You Cannot Get Back a Moment: Difference between revisions
(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0733 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...") |
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next)) |
||
Line 7: | Line 7: | ||
[[Category:YO-Quotes - in USA, San Francisco]] | [[Category:YO-Quotes - in USA, San Francisco]] | ||
<!-- END CATEGORY LIST --> | <!-- END CATEGORY LIST --> | ||
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE --> | |||
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0732 - I Cannot Serve the Air or the Sky. I Must Serve a Person|0732|YO/Prabhupada 0734 - One Who Cannot Speak, He Becomes a Great Lecturer|0734}} | |||
<!-- END NAVIGATION BAR --> | |||
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | <!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | ||
<div class="center"> | <div class="center"> | ||
Line 19: | Line 22: | ||
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page --> | <!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page --> | ||
<mp3player> | <mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/680315SB-SF_clip1.mp3</mp3player> | ||
<!-- END AUDIO LINK --> | <!-- END AUDIO LINK --> | ||
Latest revision as of 13:07, 21 September 2017
Lecture on SB 7.6.1 -- San Francisco, March 15, 1968
Ese iwe to lewa gan leleyi lati Canakya sloka. ke bale ri mi asiko wa se dara to. lati ese iwe yi , ema mo. Canakya Pandita sowipe.. Onisel pataki ni Canakya Pandita je. Alakoso ijobo loje si Oba India. O sowipe, āyuṣaḥ kṣaṇa eko 'pi na labhya svarṇa-koṭibhiḥ. O sowipe " iseju kan ninu aye yin.." iseju. Ka ma wa soro nipa wakati ati odo, sugbon iseju. On soro nipa iseju. gege bi oni Ojo 15, osu keta odun 1968, ago meje aabo Nisin odun 1968, ago meje aabo ti koja, nisin ago 7:36 lon lu, kosi besele pada ke mu asiko to ti koja yi pada ele san aimoye dollar, " Edakun pada, o ti tan, kole pada. Beena Canakya Pandita sowipe " Asiko wa niyi, teba tie son wo repete eyin o le ra asioko toti koja." Nkan toti sonu ti sonu. Na cen nirarthakaṁ nītiḥ: teyin ba lo asiko yin ni ilokulo lai jeere kankan," na ca hānis tato 'dhikā, " se le ronu aduru ipaadanu teyin ni." awon nkan teyin yin o le ni pada, teba tie son gbogbo ow aye yi, ti gbogbo eleyi ba sonu, sele siro nkan teyin ti sonu.
beena Prahlada Maharaja sowipe dharmān bhāgavatan, lati ni imoyre Krsna tabi Olorun, je nkan tose pataki gan awa o gbodo lo asiko kankan nilokulo. Oye ka bere lesekese. Kilode? Durlabhaṁ mānuṣaṁ janma. Mānuṣaṁ janma. O sowipe ara eda yi le lati ri. lati aimoye ibimo lale ri lo. Gege na awujo aye isin o mo iyi ara eda yi wan rowipe fun igbadun bi ologbo at'aja lo wa fun. Aja at'ologbo wan gbadun awon ofin merin aye; jiejun, sisun, igbeja ara eni ati imo ako ati abo. Beena ile aye eda yi o wa fun isekuse bi awon ologbo ati aja. fun nkan imi ni iloe aye eda wa fun. Imoye Krsna ni nkan imi na. Nitoripe laisi imoye Krsna, koseni tole ni oye nipa Krsna, tab'Olorun, nkan t'aye yi je nkan timo je, latibo ni moti wa ,nibo nimon lo. Aon nkan t'aye yi wa fun niyen. Beena o sowipe " lati kekere..." eleyi se pataki gan. lati kekere, ninu awon ile-iwe, niu awon ile-iwe giga, agbudo fi bhāgavata-dharma, yi fihan tabi imoye Krsna yi Eleyi se pataki, sugbon awon eyan o mo. wan rowipe ile aye yi bose ri leleyi, pe ko ju bayi lo, pe ko s;aye atunwa, wan nigbagba ninu nkan wanyi. Aimokan wan leleyi. Aye ma wa tayeraye, aye yi mako wa fu aye keji.