YO/Prabhupada 1064 - Oluwa si wa ninu okan gbogbo awon eda: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1064 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1063 - Funwa ni irorun lati ise ati abajade ise wa|1063|YO/Prabhupada 1065 - Eyan gbodo ko ni alakoko pe ara eda yi ko loje|1065}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|DeeccJeN26Y|The Lord Lives Within the Core of Heart in Every Living Being - Prabhupāda 1064}}
{{youtube_right|DeeccJeN26Y|Oluwa si wa ninu okan gbogbo awon eda - Prabhupāda 1064}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660219BG-NEW_YORK_clip08.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660219BG-NEW_YORK_clip08.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Eda to daju ju, won ma salaaye ninu Bhagavad-gita ninu apa iwe ton salaye nipa iyato laarin awon jiva ati isvara. Kṣetra-kṣetra-jña. Wanti salaaye nipa kṣetra-jña yi, kṣetra-jña na l'Oluwa je, atio awon jiva, tabi awon eda, awon na daju. Sugbon iyato to wa niwipe awon eda o mo ju nkan ton sele ninu ara won, sugbon Oluwa mo nkan ton sele ninu gbogbo ara awon eda. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati ([[Vanisource:BG 18.61|BG 18.61]]).  
Oluwa wa ninu ọkan gbogbo ẹda alãye kọọkan, Imoye ti o gaju, yio ni alaye ninu Bhagavad Gita. ninu ori iwe ti iyatọ to wa laarin jiva ati īśvara yio ni alaye. Kṣetra-kṣetra-jña. Wanti salaaye nipa kṣetra-jña yi, Oluwa ni kṣetra-jña, ati awon jiva, tabi awon ẹda alãye, awon na nimọ ninu. Sugbon iyato to wa niwipe awọn ẹda alãye nimọ pato ti ara rẹ sugbọn Oluwa nimọ ti gbogbo ara. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati ([[Vanisource:BG 18.61 (1972)|BG 18.61]]).  


Oluwa n'be ninu okan gbogbo awon eda, nitorina o mo gbogbo ironu okan, ise, awon eda. Oye ka ranti. Won de ti salaaye wipe Paramatma, tabi Eledumara, wa ninu okan gbogbo awon eda bi isvara, ni oludari osin fun won ni itosona. Oun lon fun wn ni itosona. Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭhaḥ ([[Vanisource:BG 15.15|BG 15.15]]). Owa ninu okan gbogbo eyan, oun lon fun won ni itosona lati huwa bon sefe si. Awon eda man gbagbe nkan toye kan se. Ni alakoko asi gbiyanju lati huwa bakanna, lehin na asi bosinu idimu awon ise ati ibajade karma re. Sugbon lehin igba toba farale, toba wole sinu ara eda imi... Gege b'eyan to ba bo aso kan, fun aso imi, beena, wanti salaaye ninu Bhagavd-gita pe vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya ([[Vanisource:BG 2.22|BG 2.22]]). Gege b'eyan sen bo ewu orisirisi, beena ni awon eda sen bo ara orisirisi, Irin ajo emi, ati awon ibajade ounkoun toti se koja. Beena o le paaro awon ise wanyi ti eda na ba wa lori ipo iwa rere, tosi mo iru iwa wo toye ko se, toba de se beena, lehin na gbogbo ise ati ibajade awon nkan toti se seyin ma yipo. Nitorin fun igba die ni karma wa fun. Ninu awon nkan marun to ku - īśvara, jīva, prakṛti, kāla, ati karma— awon nkan merin wanyi ma wa tayeraye, sugbon karma, fun igba die lo ma wa.  
Oluwa wa ninu ọkan gbogbo ẹda alãye kọọkan, O nimọ awọn ero inu irinkerindo ti awọn jīvas ni pato. Ko yẹ ki a gbagbe eleyi. O tun ti wa ni alaye pe Paramātmā, Ọlọrun Eledumare, ngbe ninu ọkàn gbogbo eniyan bi īśvara, bi oludari, o si nfun ẹda alãye ni itọsọna. O nse itosona. Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭhaḥ ([[Vanisource:BG 15.15 (1972)|BG 15.15]]). O ngbe ninu ọkàn gbogbo eniyan, o si nfun ẹda alãye ni itọsọna lati se bi o ti wu. Ẹda alãye gbàgbé ohun to ni lati ṣe. akọkọ yio se ipinnu lati sisẹ ni ọna kan, lẹhinna a bọ sinu idimu karma awọn isẹ ọwọ rẹ ati ere wọn. Lẹhin ti iku ba ti pa l’ara da, a gbe ara miiran wọ... gẹgẹ bi a se nparọ aṣọ kan fun imiran, bakanna, o ti wa ni alaaye ninu Bhagavd-gita pe vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya ([[Vanisource:BG 2.22 (1972)|BG 2.22]]). Gege bi eyan se nwo ewu orisirisi, beena ni awon eda se nyi ara pada ni orisirisi, Bi ẹmi ba se kuro bayi lati ara kan si ara miran, a jẹ iya awọn ise ọwọ rẹ ati ere wọn ti o ti rekọja. Awọn akitiyan wọnyi le se yipada nigbati ẹda alãye ba wa ninu ipo rere, ni ilera ọkan, ti o si mọ iru akitiyan ti o yẹ ki o gbọwọle. Ti o ba se bẹ, gbogbo awọn ise ọwọ rẹ ati ere wọn ti o ti rekọja le ni ayipada. Nitori naa, karma ki ise fun ayeraye. wipe ninu awọn ohun marun yi -- īśvara, jiva, prakriti, kala ati karma -- mẹrin ni wọn jẹ ainipẹkun, sugbọn karma ki ise fun ayeraye.  


Nisin isvara to daju, isvara to daju ju, ati iyato laarin isvara to daju ju at'Oluwa, ati awon eda ninu asiko tawayi, bose je niyen. Imoye, t'Oluwa ati awon eda, imoye yi wa ni pipe. Konsepe lati asepo pelu awon nkan aye yi ni imoye na ti jade. Asise towa ninu ironu yi niyen. Imoye to sowipe lati akojopo oawon nkan aye yi nii imoye wa ti jade Bhagavad-gita o gba iru awon nkan bayi. Kosi bonsele se. Idaabo aye yi le funwa ni imoye imi tio jo imoye ton tinu wa jade, gege bi ina ton jade lati inu igo, ina yi asi jo awo igo na. Beena, imoye Oluwa, ko ni nkankan se pelu ile aye yi. Oluwa, gege bi Krsna, O sowipe, mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ ([[Vanisource:BG 9.10|BG 9.10]]). Nigbato ba sokalew wa sinu ile aye yio, imoy ere o ni nkankan pelu awon nkan aye yi. Toba jepe imoye re wa labe agbara ile aye yi, kosi bosele soro lori Bhagavad-gita. Kosi beyan sele soro lori agbaye to wa ni pipe lai bolowo idoti imoye aye yi. Beena Oluwa o ni idoti kankan. Sugbon imoye aye wa lasiko yi, si ni doti aye yi. Beena, gege bi Bhagavad-gita sen ko wa, agbodo ya imoye ile aye yi si mimo, ninu imoye mimo yi, lale sise na,. Nkan to ma jeki inu wa dun niyen. Kosi basele fi ipaari si ise wa. Agbodo ya ise wa si mimo. awon ise yi tati yasi mimo lon pe ni bhakti. Itumo Bhakti niwipe, won daabi ise lasan, sugbon ise idoti ko loje. Ise mimo loje. Beena awon eyan lasan le riwipe awon olufokansi n'sise bi awon eyan lasan na, sugbon eni tio l'ogbon, kole mo wipe awon ise t'olufokansi tabi ise Oluwa, kosi bonsele doti pelu oun ile aye yi, idoti awon guna meta, ipo iseda, sugbon imoye to gaju. Imoye wa ti kodoti ile aye yi, oye ka mo.  
Onimọ to ga julọ īśvara, ati iyato laarin isvara to gaju ju tabi Oluwa, ati awon eda ninu asiko tawayi, o ri bayi. imoye ti Ọlọrun ati ti ẹda alãye ni wọn jẹ imọlẹ Ki ise wipe imoye bẹrẹ si ndagba labẹ awọn ayidayida apapọ awọn ohun elo aye. Asise ni eyinni jẹ. Ero ori ti o wipe imoye bẹrẹ si ndagba labẹ awọn ayidayida apapọ awọn ohun elo aye ko ni asẹ ninu Bhagavad Gita. Ko le jẹ bẹ Imoye ti le tan mọlẹ sodi nipa ibora ti awọn ohun elo ọran aye, gẹgẹ bi ina ti o tan mọlẹ nipasẹ dingi gẹgẹ bi ina ti o tan mọlẹ nipasẹ dingi alawọ le fihan gẹgẹ bi awọ kan. Beena, imoye Oluwa, ko ni nkankan se pelu ile aye yi. Oluwa, gege bi Krsna, O sowipe, mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ ([[Vanisource:BG 9.10 (1972)|BG 9.10]]). Nigbati o sọkale sori-lẹ agbaye, ohun elo aye ko ni ipa lori imoye Rẹ. Ti o ba ti ni ipa lori Rẹ, o ma wa laitọ fun lati sọrọ lori ọrọ imọlẹ bi o ti se ninu Bhagavad Gita Eniyan ko le sọ ohunkohun nipa ti aye imọlẹ lai ni ominira kuro ninu abawọn ọkan aye. Bẹẹ ni abawọn aye ko ni ipa lori Oluwa. Sugbon imoye aye wa lasiko yi, si ni doti aye yi. Iwe mimọ Bhagavad Gita fi kọni pé a ni lati ya imoye ti o ti ni abawọn aye yi si mimọ, Ninu imoye mimọ, awọn ise wa yoo wa ni ibaamu si ifẹ ti īśvara eyi yoo ṣi fun wa ni idunnu. Ki ise pe a ni lati siwọ ninu gbogbo awọn akitiyan. Awọn akitiyan wa ni lati ni ya si mimọ. awọn akitiyan alailabawọn ni a npe ni bhakti. Awọn akitiyan ninu bhakti le dabi awọn akitiyan ti ki ise pataki, sugbọn wọn ko ni abawọn. Ise mimọ lo je. Alaimọkan eniyan le ri pe olufọkansin nhuwa tabi nsisẹ bi eniyan yẹpẹrẹ, sugbọn iru alaimoye eniyan bẹ, se aimọ wipe awọn akitiyan ti ẹlẹsin tabi isé Oluwa, ko nni ibajẹ nipa imoye eleeri tabi abawọn aye, Wọn ni imọlẹ lori awọn ipo mẹta ti isẹda. o yẹ ki a mọ pe akoko ti a wa yi imoye wa ti ni abawọn.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:29, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Oluwa wa ninu ọkan gbogbo ẹda alãye kọọkan, Imoye ti o gaju, yio ni alaye ninu Bhagavad Gita. ninu ori iwe ti iyatọ to wa laarin jiva ati īśvara yio ni alaye. Kṣetra-kṣetra-jña. Wanti salaaye nipa kṣetra-jña yi, Oluwa ni kṣetra-jña, ati awon jiva, tabi awon ẹda alãye, awon na nimọ ninu. Sugbon iyato to wa niwipe awọn ẹda alãye nimọ pato ti ara rẹ sugbọn Oluwa nimọ ti gbogbo ara. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati (BG 18.61).

Oluwa wa ninu ọkan gbogbo ẹda alãye kọọkan, O nimọ awọn ero inu irinkerindo ti awọn jīvas ni pato. Ko yẹ ki a gbagbe eleyi. O tun ti wa ni alaye pe Paramātmā, Ọlọrun Eledumare, ngbe ninu ọkàn gbogbo eniyan bi īśvara, bi oludari, o si nfun ẹda alãye ni itọsọna. O nse itosona. Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭhaḥ (BG 15.15). O ngbe ninu ọkàn gbogbo eniyan, o si nfun ẹda alãye ni itọsọna lati se bi o ti wu. Ẹda alãye gbàgbé ohun to ni lati ṣe. akọkọ yio se ipinnu lati sisẹ ni ọna kan, lẹhinna a bọ sinu idimu karma awọn isẹ ọwọ rẹ ati ere wọn. Lẹhin ti iku ba ti pa l’ara da, a gbe ara miiran wọ... gẹgẹ bi a se nparọ aṣọ kan fun imiran, bakanna, o ti wa ni alaaye ninu Bhagavd-gita pe vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya (BG 2.22). Gege bi eyan se nwo ewu orisirisi, beena ni awon eda se nyi ara pada ni orisirisi, Bi ẹmi ba se kuro bayi lati ara kan si ara miran, a jẹ iya awọn ise ọwọ rẹ ati ere wọn ti o ti rekọja. Awọn akitiyan wọnyi le se yipada nigbati ẹda alãye ba wa ninu ipo rere, ni ilera ọkan, ti o si mọ iru akitiyan ti o yẹ ki o gbọwọle. Ti o ba se bẹ, gbogbo awọn ise ọwọ rẹ ati ere wọn ti o ti rekọja le ni ayipada. Nitori naa, karma ki ise fun ayeraye. wipe ninu awọn ohun marun yi -- īśvara, jiva, prakriti, kala ati karma -- mẹrin ni wọn jẹ ainipẹkun, sugbọn karma ki ise fun ayeraye.

Onimọ to ga julọ īśvara, ati iyato laarin isvara to gaju ju tabi Oluwa, ati awon eda ninu asiko tawayi, o ri bayi. imoye ti Ọlọrun ati ti ẹda alãye ni wọn jẹ imọlẹ Ki ise wipe imoye bẹrẹ si ndagba labẹ awọn ayidayida apapọ awọn ohun elo aye. Asise ni eyinni jẹ. Ero ori ti o wipe imoye bẹrẹ si ndagba labẹ awọn ayidayida apapọ awọn ohun elo aye ko ni asẹ ninu Bhagavad Gita. Ko le jẹ bẹ Imoye ti le tan mọlẹ sodi nipa ibora ti awọn ohun elo ọran aye, gẹgẹ bi ina ti o tan mọlẹ nipasẹ dingi gẹgẹ bi ina ti o tan mọlẹ nipasẹ dingi alawọ le fihan gẹgẹ bi awọ kan. Beena, imoye Oluwa, ko ni nkankan se pelu ile aye yi. Oluwa, gege bi Krsna, O sowipe, mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ (BG 9.10). Nigbati o sọkale sori-lẹ agbaye, ohun elo aye ko ni ipa lori imoye Rẹ. Ti o ba ti ni ipa lori Rẹ, o ma wa laitọ fun lati sọrọ lori ọrọ imọlẹ bi o ti se ninu Bhagavad Gita Eniyan ko le sọ ohunkohun nipa ti aye imọlẹ lai ni ominira kuro ninu abawọn ọkan aye. Bẹẹ ni abawọn aye ko ni ipa lori Oluwa. Sugbon imoye aye wa lasiko yi, si ni doti aye yi. Iwe mimọ Bhagavad Gita fi kọni pé a ni lati ya imoye ti o ti ni abawọn aye yi si mimọ, Ninu imoye mimọ, awọn ise wa yoo wa ni ibaamu si ifẹ ti īśvara eyi yoo ṣi fun wa ni idunnu. Ki ise pe a ni lati siwọ ninu gbogbo awọn akitiyan. Awọn akitiyan wa ni lati ni ya si mimọ. awọn akitiyan alailabawọn ni a npe ni bhakti. Awọn akitiyan ninu bhakti le dabi awọn akitiyan ti ki ise pataki, sugbọn wọn ko ni abawọn. Ise mimọ lo je. Alaimọkan eniyan le ri pe olufọkansin nhuwa tabi nsisẹ bi eniyan yẹpẹrẹ, sugbọn iru alaimoye eniyan bẹ, se aimọ wipe awọn akitiyan ti ẹlẹsin tabi isé Oluwa, ko nni ibajẹ nipa imoye eleeri tabi abawọn aye, Wọn ni imọlẹ lori awọn ipo mẹta ti isẹda. o yẹ ki a mọ pe akoko ti a wa yi imoye wa ti ni abawọn.