YO/Prabhupada 1080 - Isonisoki ti Bhagavad-gita - Oluwa ni Krishna. Oluwa fun awon egbe eyan kan soso ko ni Krishna je: Difference between revisions
YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...") |
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next)) |
||
Line 1: | Line 1: | ||
<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> | <!-- BEGIN CATEGORY LIST --> | ||
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]] | [[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]] | ||
[[Category:Prabhupada | [[Category:Prabhupada 1080 - in all Languages]] | ||
[[Category:YO-Quotes - 1966]] | [[Category:YO-Quotes - 1966]] | ||
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]] | [[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]] | ||
Line 10: | Line 10: | ||
[[Category:Yoruba Language]] | [[Category:Yoruba Language]] | ||
<!-- END CATEGORY LIST --> | <!-- END CATEGORY LIST --> | ||
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE --> | |||
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1079 - Iwe mimo ti gbogbo awon eyan gbodo ka dada ni Bhagavdad-gita je|1079|YO/Prabhupada 0001 - Ki egbe wa fe s'egbe-gberun lona mewa|0001}} | |||
<!-- END NAVIGATION BAR --> | |||
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | <!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | ||
<div class="center"> | <div class="center"> | ||
Line 18: | Line 21: | ||
<!-- BEGIN VIDEO LINK --> | <!-- BEGIN VIDEO LINK --> | ||
{{youtube_right|6nQyRCL9CaQ| | {{youtube_right|6nQyRCL9CaQ|Isonisoki ti Bhagavad-gita - Oluwa ni Krishna. Oluwa fun awon egbe eyan kan soso ko ni Krishna je<br />- Prabhupāda 1080}} | ||
<!-- END VIDEO LINK --> | <!-- END VIDEO LINK --> | ||
<!-- BEGIN AUDIO LINK --> | <!-- BEGIN AUDIO LINK --> | ||
<mp3player> | <mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip24.mp3</mp3player> | ||
<!-- END AUDIO LINK --> | <!-- END AUDIO LINK --> | ||
Line 30: | Line 33: | ||
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT --> | <!-- BEGIN TRANSLATED TEXT --> | ||
Isonisoki Bhagavad-gita - Ọlọrun kan ti o wa ni Krishna. Krishna ki ise Ọlọrun fun egbe ipinya. Oluwa kede ni gbangba ninu ìka kẹhin ti Bhagavad gita : | |||
:mala-nirmocanaṁ puṁsāṁ | :mala-nirmocanaṁ puṁsāṁ | ||
:jala-snānaṁ dine dine | :jala-snānaṁ dine dine | ||
:sakṛd gītāmṛta-snānam | :sakṛd gītāmṛta-snānam | ||
:saṁsāra-mala-nāśanam | :saṁsāra-mala-nāśanam | ||
:(Gītā-māhātmya 3) | |||
Oluwa gba gbogbo ojuse. Fun ẹni ti o ba fi ara rẹ fun u, Oluwa gba gbogbo ojuse, O si se igbẹkẹle fun iru eniyan bẹ lori ẹsan ere gbogbo ẹṣẹ. | |||
:gītā su-gītā kartavyā | :gītā su-gītā kartavyā | ||
:kim anyaiḥ śāstra-vistaraiḥ | :kim anyaiḥ śāstra-vistaraiḥ | ||
:yā svayaṁ padmanābhasya | :yā svayaṁ padmanābhasya | ||
:mukha-padmād viniḥsṛtā | :mukha-padmād viniḥsṛtā | ||
:(Gītā-māhātmya 4) | |||
"Eyan le se imọ-toto ara rẹ lojoojumọ nipa fifi omi wẹ, ṣugbọn ẹni ti o ba wẹ lẹẹkan soso ninu omi mimọ odo Ganga ti Bhagavad Gita, fun oluwarẹ idọti ode aye ti ni ibori patapata." Gītā su-gītā kartavyā kim anyaiḥ śāstra-vistaraiḥ yā svayaṁ padmanābhasya mukha-padmād viniḥsṛtā. Nitoripe Ẹni Isaju Eledumare funra Rẹ ni o sọ ọrọ inu Bhagavad Gita, ko ni wulo ki awon eniyan ka iwe ilana Vediki miiran. Ohun ti a nilo nikan ni lati ma farabalẹ gbọ ati ki a si maa ka Bhagavad Gita deede, gītā su-gītā kartavyā... Dandan ni ki awon eyan gba ona yi Gītā su-gītā kartavyā kim anyaiḥ śāstra-vistaraiḥ. Nitoripe ni asiko tawayi, akitiyan aye asan ti gba awọn eniyan l’ọkan to bẹ ti ko se ṣee fun wọn lati ka gbogbo iwe ilana Vediki. Iwe mimo kan soso yi le sise na nitoripe oun ni koko oro gbogbo awon iwe Veda, ati paapa nitori ti o jẹ ọrọ ti Ẹni Isaju Eledumare sọ. | |||
:bhāratāmṛta-sarvasvaṁ | :bhāratāmṛta-sarvasvaṁ | ||
:viṣṇu-vaktrād viniḥsṛtam | :viṣṇu-vaktrād viniḥsṛtam | ||
:gītā-gaṅgodakaṁ pītvā | :gītā-gaṅgodakaṁ pītvā | ||
:punar janma na vidyate | :punar janma na vidyate | ||
:(Gītā-māhātmya 5) | |||
Bi o ti wa ni owe: Ẹni ti o mu omi odo Ganga, ti ni igbala, kini ka ti sọ tẹni ti o mu didun inu ti Bhagavad-Gita? Bhagavad-Gītā ni aladun pataki ti inu Mahābhārata, Viṣṇu Oluwa Krishna ni Viṣṇu àtètèkọse. Viṣṇu-vaktrād viniḥsṛtam. Bhagavad Gita ti ẹnu Ẹni Isaju Eledumare jade Ati gaṅgodakaṁ, Ganga si ti olojubioro ẹsẹ ti Oluwa wa. Bhagavad Gita si ti ẹnu Ẹni Isaju Eledumare jade. Dajudaju, ko si iyatọ nibẹ laarin ẹnu ati ẹsẹ Ọlọrun Ọba, sugbọn lati inu iwadi laisi ojúsàájú a ti le mọyi pe Bhagavad Gita tilẹ tun se pataki diẹ ju omi odo Ganga. | |||
:sarvopaniṣado gāvo | :sarvopaniṣado gāvo | ||
:dogdhā gopāla-nandana | :dogdhā gopāla-nandana | ||
:pārtho vatsaḥ su-dhīr bhoktā | :pārtho vatsaḥ su-dhīr bhoktā | ||
:dugdhaṁ gītāmṛtaṁ mahat | :dugdhaṁ gītāmṛtaṁ mahat | ||
:(Gītā-māhātmya 6) | |||
Bi maalu ni Gitopanisad se ri, | Bi maalu ni Gitopanisad se ri, ati Oluwa Ọlọrun, ti o gbajumọ bi olusọagutan, si nfunwara Maalu yi. Sarvopaniṣado. koko ọrọ ninu gbogbo awọn Upaniṣads, kan ri gẹgẹ bi Maalu, Oluwa Ọlọrun, ti o gbajumọ bi olusọagutan, si nfunwara Maalu yi. pārtho vatsaḥ. Arjuna on ri bi ọmọ-malu, su-dhīr bhoktā. Awọn ọjọgbọn ati awọn jọsin mimọ ni wọn si ni lati mu wara aladun yi. Su-dhīr bhoktā dugdhaṁ gītāmṛtaṁ mahat. Adun na, wara Bhagavad-gita, wa fun awọn jọsin alakọwe. | ||
:ekaṁ śāstraṁ devakī-putra-gītam | :ekaṁ śāstraṁ devakī-putra-gītam | ||
:eko devo devakī-putra ev | :eko devo devakī-putra ev | ||
:eko mantras tasya nāmāni yāni | :eko mantras tasya nāmāni yāni | ||
:karmāpy ekaṁ tasya devasya sevā | :karmāpy ekaṁ tasya devasya sevā | ||
:(Gītā-māhātmya 7) | |||
Nisin, oye ki gbogbo aye | Nisin, oye ki gbogbo aye kẹẹkọ ninu Bhagavad-gita, ẹkọ na. Evaṁ śāstraṁ devakī-putra-gītam. iwe mimọ kan soso lo wa, iwe mimọ kan soso fun gbogbo araiye, fun gbogbo araiye, eyini ni Bhagavad-gita yi. Devo devakī-putra eva. Ki Ọlọrun kan wa fun gbogbo aye - Śrī Kṛṣṇa. eko mantras tasya nāmāni. ati orin kan, mantra kan, adura kan, kikepe orukọ Rẹ: Hare Kṛṣṇa Hare Kṛṣṇa Kṛṣṇa Kṛṣṇa Hare Hare, Hare Rāma Hare Rāma Rāma Rāma Hare Hare. Eko mantras tasya nāmāni yāni karmāpy ekaṁ tasya devasya sevā. Ise kan soso lowa lati sise fun Eledumare. Ti eniyan ba kẹkọọ Bhagavad-Gita, awọn eniyan yio si nitara gidigidi lati lati ni ẹsin kan, Ọlọrun kan, iwe mimọ kan soso, ati ojúṣe kan. Eyi ti ni isosoki ninu Bhagavad-gita. Ọlọrun kan kan soso yi ni Krishna. Krishna ki ise Ọlọrun fun ẹgbẹ ipinya, bi orukọ Krishna se jamọ... Bi a ti salaaye tẹlẹ, Krishna tumọ si idunnu to gaju lọ. | ||
<!-- END TRANSLATED TEXT --> | <!-- END TRANSLATED TEXT --> |
Latest revision as of 13:13, 21 September 2017
660219-20 - Lecture BG Introduction - New York
Isonisoki Bhagavad-gita - Ọlọrun kan ti o wa ni Krishna. Krishna ki ise Ọlọrun fun egbe ipinya. Oluwa kede ni gbangba ninu ìka kẹhin ti Bhagavad gita :
- mala-nirmocanaṁ puṁsāṁ
- jala-snānaṁ dine dine
- sakṛd gītāmṛta-snānam
- saṁsāra-mala-nāśanam
- (Gītā-māhātmya 3)
Oluwa gba gbogbo ojuse. Fun ẹni ti o ba fi ara rẹ fun u, Oluwa gba gbogbo ojuse, O si se igbẹkẹle fun iru eniyan bẹ lori ẹsan ere gbogbo ẹṣẹ.
- gītā su-gītā kartavyā
- kim anyaiḥ śāstra-vistaraiḥ
- yā svayaṁ padmanābhasya
- mukha-padmād viniḥsṛtā
- (Gītā-māhātmya 4)
"Eyan le se imọ-toto ara rẹ lojoojumọ nipa fifi omi wẹ, ṣugbọn ẹni ti o ba wẹ lẹẹkan soso ninu omi mimọ odo Ganga ti Bhagavad Gita, fun oluwarẹ idọti ode aye ti ni ibori patapata." Gītā su-gītā kartavyā kim anyaiḥ śāstra-vistaraiḥ yā svayaṁ padmanābhasya mukha-padmād viniḥsṛtā. Nitoripe Ẹni Isaju Eledumare funra Rẹ ni o sọ ọrọ inu Bhagavad Gita, ko ni wulo ki awon eniyan ka iwe ilana Vediki miiran. Ohun ti a nilo nikan ni lati ma farabalẹ gbọ ati ki a si maa ka Bhagavad Gita deede, gītā su-gītā kartavyā... Dandan ni ki awon eyan gba ona yi Gītā su-gītā kartavyā kim anyaiḥ śāstra-vistaraiḥ. Nitoripe ni asiko tawayi, akitiyan aye asan ti gba awọn eniyan l’ọkan to bẹ ti ko se ṣee fun wọn lati ka gbogbo iwe ilana Vediki. Iwe mimo kan soso yi le sise na nitoripe oun ni koko oro gbogbo awon iwe Veda, ati paapa nitori ti o jẹ ọrọ ti Ẹni Isaju Eledumare sọ.
- bhāratāmṛta-sarvasvaṁ
- viṣṇu-vaktrād viniḥsṛtam
- gītā-gaṅgodakaṁ pītvā
- punar janma na vidyate
- (Gītā-māhātmya 5)
Bi o ti wa ni owe: Ẹni ti o mu omi odo Ganga, ti ni igbala, kini ka ti sọ tẹni ti o mu didun inu ti Bhagavad-Gita? Bhagavad-Gītā ni aladun pataki ti inu Mahābhārata, Viṣṇu Oluwa Krishna ni Viṣṇu àtètèkọse. Viṣṇu-vaktrād viniḥsṛtam. Bhagavad Gita ti ẹnu Ẹni Isaju Eledumare jade Ati gaṅgodakaṁ, Ganga si ti olojubioro ẹsẹ ti Oluwa wa. Bhagavad Gita si ti ẹnu Ẹni Isaju Eledumare jade. Dajudaju, ko si iyatọ nibẹ laarin ẹnu ati ẹsẹ Ọlọrun Ọba, sugbọn lati inu iwadi laisi ojúsàájú a ti le mọyi pe Bhagavad Gita tilẹ tun se pataki diẹ ju omi odo Ganga.
- sarvopaniṣado gāvo
- dogdhā gopāla-nandana
- pārtho vatsaḥ su-dhīr bhoktā
- dugdhaṁ gītāmṛtaṁ mahat
- (Gītā-māhātmya 6)
Bi maalu ni Gitopanisad se ri, ati Oluwa Ọlọrun, ti o gbajumọ bi olusọagutan, si nfunwara Maalu yi. Sarvopaniṣado. koko ọrọ ninu gbogbo awọn Upaniṣads, kan ri gẹgẹ bi Maalu, Oluwa Ọlọrun, ti o gbajumọ bi olusọagutan, si nfunwara Maalu yi. pārtho vatsaḥ. Arjuna on ri bi ọmọ-malu, su-dhīr bhoktā. Awọn ọjọgbọn ati awọn jọsin mimọ ni wọn si ni lati mu wara aladun yi. Su-dhīr bhoktā dugdhaṁ gītāmṛtaṁ mahat. Adun na, wara Bhagavad-gita, wa fun awọn jọsin alakọwe.
- ekaṁ śāstraṁ devakī-putra-gītam
- eko devo devakī-putra ev
- eko mantras tasya nāmāni yāni
- karmāpy ekaṁ tasya devasya sevā
- (Gītā-māhātmya 7)
Nisin, oye ki gbogbo aye kẹẹkọ ninu Bhagavad-gita, ẹkọ na. Evaṁ śāstraṁ devakī-putra-gītam. iwe mimọ kan soso lo wa, iwe mimọ kan soso fun gbogbo araiye, fun gbogbo araiye, eyini ni Bhagavad-gita yi. Devo devakī-putra eva. Ki Ọlọrun kan wa fun gbogbo aye - Śrī Kṛṣṇa. eko mantras tasya nāmāni. ati orin kan, mantra kan, adura kan, kikepe orukọ Rẹ: Hare Kṛṣṇa Hare Kṛṣṇa Kṛṣṇa Kṛṣṇa Hare Hare, Hare Rāma Hare Rāma Rāma Rāma Hare Hare. Eko mantras tasya nāmāni yāni karmāpy ekaṁ tasya devasya sevā. Ise kan soso lowa lati sise fun Eledumare. Ti eniyan ba kẹkọọ Bhagavad-Gita, awọn eniyan yio si nitara gidigidi lati lati ni ẹsin kan, Ọlọrun kan, iwe mimọ kan soso, ati ojúṣe kan. Eyi ti ni isosoki ninu Bhagavad-gita. Ọlọrun kan kan soso yi ni Krishna. Krishna ki ise Ọlọrun fun ẹgbẹ ipinya, bi orukọ Krishna se jamọ... Bi a ti salaaye tẹlẹ, Krishna tumọ si idunnu to gaju lọ.