YO/Prabhupada 0136 - Bayi ni imoye yi se wa lat'oke de le: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0136 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1975 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Sanand]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Sanand]]
[[Category:YO-Quotes - in India]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0135 - Kosi besele siro ojo-ori Veda|0135|YO/Prabhupada 0137 - Kini opin aye|0137}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|SisxSH6QWGc|By Disciplic Succession Knowledge has Come Down - Prabhupāda 0136}}
{{youtube_right|SFTHwtFnSuw|By Disciplic Succession Knowledge has Come Down - Prabhupāda 0136}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/751225LE.SAN_clip1.mp3</mp3player>  
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/751225LE.SAN_clip1.mp3</mp3player>  
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 26: Line 30:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Olorun ni tumo Bhagavān. Lona meta: brahmeti paramātmeti bhagavān iti śabdyate ([[Vanisource:SB 1.2.11|SB 1.2.11]]). leyan le mo Otito to daju ju laye yi Eyan leni imoye Otito yi ni alakoko bi Brahman, Kini ipo awon jñānī, ikeji ni Paramātmā, eleyi ni ipo awon yogi iketa je imoye Olorun ni ona to daju gan, oye Olorun bi eyan. Olorun ni eto tose pataki ju Tabefe mo nipa Oorun, Olorun si wanbe bi sūrya-nārāyaṇa, tabi Olori isogbe-Oorun. Wansi ti funwa ni oruko re ni Bhagavad-gītā - Vivasvān. Olorun si soro ninu iwe kerin, imaṁ vivasvate yogaṁ proktavān aham avyayam: ([[Vanisource:BG 4.1|BG 4.1]]) Niibere mosalaaye gbogbo sayensi Bhagavad-gītā, si orisa-oorun, Vivasvān," Vivasvān manave prāhur manur ikṣvākave 'bravīt. orisa-oorun si salaaye fun Manu, Manu na salaaye fun omo-okurin re. bayi ni imoye yi se wa lat'oke de le. gege na taba soro nipa jñāna, agbudo gbo latenu eyan. Ninu imoye Otitio to gaju Bhagavān ni oro to kehin, Osi soro ninu Bhagavad-gītā.  
Olorun ni tumo Bhagavān. Lona meta: brahmeti paramātmeti bhagavān iti śabdyate ([[Vanisource:SB 1.2.11|SB 1.2.11]]). leyan le mo Otito to daju ju laye yi Eyan leni imoye Otito yi ni alakoko bi Brahman, Kini ipo awon jñānī, ikeji ni Paramātmā, eleyi ni ipo awon yogi iketa je imoye Olorun ni ona to daju gan, oye Olorun bi eyan. Olorun ni eto tose pataki ju Tabefe mo nipa Oorun, Olorun si wanbe bi sūrya-nārāyaṇa, tabi Olori isogbe-Oorun. Wansi ti funwa ni oruko re ni Bhagavad-gītā - Vivasvān. Olorun si soro ninu iwe kerin, imaṁ vivasvate yogaṁ proktavān aham avyayam: ([[Vanisource:BG 4.1 (1972)|BG 4.1]]) Niibere mosalaaye gbogbo sayensi Bhagavad-gītā, si orisa-oorun, Vivasvān," Vivasvān manave prāhur manur ikṣvākave 'bravīt. orisa-oorun si salaaye fun Manu, Manu na salaaye fun omo-okurin re. bayi ni imoye yi se wa lat'oke de le. gege na taba soro nipa jñāna, agbudo gbo latenu eyan. Ninu imoye Otitio to gaju Bhagavān ni oro to kehin, Osi soro ninu Bhagavad-gītā.  


bhagavān uvāca ni nkan ti Vyāsadeva feso nibe Kosi sowipe kṛṣṇa uvāca, nitoripe nigbami awon asiwere le ka itumo toyato si nkan ti Kṛṣṇa ba so. Itumo bhagavān uvāca niwipe ounkoun to baso kole si asise nibe. Awon eyan lasan bi tawa, ani alebu merin:: bhrama pramāda vipralipsā kara-ṇāpāṭava. Sugbon Olorun Krsna, tabi awon iranse Krsna ton ni oye nipa Krsna, fun awon eyan bayi kolesejo alebu. Gbogbo wan lon daju. Nitorina ni Krsna se fun wa ni ilanani yi,  
bhagavān uvāca ni nkan ti Vyāsadeva feso nibe Kosi sowipe kṛṣṇa uvāca, nitoripe nigbami awon asiwere le ka itumo toyato si nkan ti Kṛṣṇa ba so. Itumo bhagavān uvāca niwipe ounkoun to baso kole si asise nibe. Awon eyan lasan bi tawa, ani alebu merin:: bhrama pramāda vipralipsā kara-ṇāpāṭava. Sugbon Olorun Krsna, tabi awon iranse Krsna ton ni oye nipa Krsna, fun awon eyan bayi kolesejo alebu. Gbogbo wan lon daju. Nitorina ni Krsna se fun wa ni ilanani yi,  
Line 34: Line 38:
:upadekṣyanti tad jñānaṁ
:upadekṣyanti tad jñānaṁ
:jñāninas tattva-darśinaḥ
:jñāninas tattva-darśinaḥ
:([[Vanisource:BG 4.34|BG 4.34]])  
:([[Vanisource:BG 4.34 (1972)|BG 4.34]])  


Egbudo gba imoye lowo awon eyan tonti ri otito yi Agbudo sunmo awon eyan bayi. Bibeko, taba sunmo awon eyan ton so isokuso, kosi basele ri imoye gidi gba Awon onisokuso bayi, kosi bonsele ni oye Olorun. Nitorina niwonsen sowipe " Bayi ni Olorun se ri", tabi " Bayiko ni Olorun se ri". "Ko s'Olorun", " Olorun o leni Irisi". Iranu ni gbogbo awon nkan ton so yi, nitoripe koseyi ninu wan to laari. Nitorina ni Bhagavān se sowipe, avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritāḥ ([[Vanisource:BG 9.11|BG 9.11]]). Nitori wa ni Olorun sen wa ni irisi eyan, sugbon awon asiwere wanyi rope eyan lasan loje. Ti Bhagavān ba sowipe ahaṁ bīja-pradaḥ pitā ([[Vanisource:BG 14.4|BG 14.4]]), " Emini Baba gbogbo agbaye", gbogbo lamo wipe eyan ni baba wa, baba re eyan na loje kilode teyin wa rope eyan koni Olorun je? Kilode? Agbudo ko lodo Bhagavan, eda to logbon ju. Iwe mimo Bhagavad-gītā si je iwe to kunfun imoye nipa Olorun. Kosi basele yi oro towa ninu Bhagavad-gītā. Iranu niyen. Awan tele ofin yi ninu egbe imoye Krsna wayi. Awa o lee da nkan wa sile. Ati pin oro Olorun nise tawa ni. Adeti bere sini sise na.
Egbudo gba imoye lowo awon eyan tonti ri otito yi Agbudo sunmo awon eyan bayi. Bibeko, taba sunmo awon eyan ton so isokuso, kosi basele ri imoye gidi gba Awon onisokuso bayi, kosi bonsele ni oye Olorun. Nitorina niwonsen sowipe " Bayi ni Olorun se ri", tabi " Bayiko ni Olorun se ri". "Ko s'Olorun", " Olorun o leni Irisi". Iranu ni gbogbo awon nkan ton so yi, nitoripe koseyi ninu wan to laari. Nitorina ni Bhagavān se sowipe, avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritāḥ ([[Vanisource:BG 9.11 (1972)|BG 9.11]]). Nitori wa ni Olorun sen wa ni irisi eyan, sugbon awon asiwere wanyi rope eyan lasan loje. Ti Bhagavān ba sowipe ahaṁ bīja-pradaḥ pitā ([[Vanisource:BG 14.4 (1972)|BG 14.4]]), " Emini Baba gbogbo agbaye", gbogbo lamo wipe eyan ni baba wa, baba re eyan na loje kilode teyin wa rope eyan koni Olorun je? Kilode? Agbudo ko lodo Bhagavan, eda to logbon ju. Iwe mimo Bhagavad-gītā si je iwe to kunfun imoye nipa Olorun. Kosi basele yi oro towa ninu Bhagavad-gītā. Iranu niyen. Awan tele ofin yi ninu egbe imoye Krsna wayi. Awa o lee da nkan wa sile. Ati pin oro Olorun nise tawa ni. Adeti bere sini sise na.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 19:02, 14 October 2018



Lecture with Translator -- Sanand, December 25, 1975

Olorun ni tumo Bhagavān. Lona meta: brahmeti paramātmeti bhagavān iti śabdyate (SB 1.2.11). leyan le mo Otito to daju ju laye yi Eyan leni imoye Otito yi ni alakoko bi Brahman, Kini ipo awon jñānī, ikeji ni Paramātmā, eleyi ni ipo awon yogi iketa je imoye Olorun ni ona to daju gan, oye Olorun bi eyan. Olorun ni eto tose pataki ju Tabefe mo nipa Oorun, Olorun si wanbe bi sūrya-nārāyaṇa, tabi Olori isogbe-Oorun. Wansi ti funwa ni oruko re ni Bhagavad-gītā - Vivasvān. Olorun si soro ninu iwe kerin, imaṁ vivasvate yogaṁ proktavān aham avyayam: (BG 4.1) Niibere mosalaaye gbogbo sayensi Bhagavad-gītā, si orisa-oorun, Vivasvān," Vivasvān manave prāhur manur ikṣvākave 'bravīt. orisa-oorun si salaaye fun Manu, Manu na salaaye fun omo-okurin re. bayi ni imoye yi se wa lat'oke de le. gege na taba soro nipa jñāna, agbudo gbo latenu eyan. Ninu imoye Otitio to gaju Bhagavān ni oro to kehin, Osi soro ninu Bhagavad-gītā.

bhagavān uvāca ni nkan ti Vyāsadeva feso nibe Kosi sowipe kṛṣṇa uvāca, nitoripe nigbami awon asiwere le ka itumo toyato si nkan ti Kṛṣṇa ba so. Itumo bhagavān uvāca niwipe ounkoun to baso kole si asise nibe. Awon eyan lasan bi tawa, ani alebu merin:: bhrama pramāda vipralipsā kara-ṇāpāṭava. Sugbon Olorun Krsna, tabi awon iranse Krsna ton ni oye nipa Krsna, fun awon eyan bayi kolesejo alebu. Gbogbo wan lon daju. Nitorina ni Krsna se fun wa ni ilanani yi,

tad viddhi praṇipātena
paripraśnena sevayā
upadekṣyanti tad jñānaṁ
jñāninas tattva-darśinaḥ
(BG 4.34)

Egbudo gba imoye lowo awon eyan tonti ri otito yi Agbudo sunmo awon eyan bayi. Bibeko, taba sunmo awon eyan ton so isokuso, kosi basele ri imoye gidi gba Awon onisokuso bayi, kosi bonsele ni oye Olorun. Nitorina niwonsen sowipe " Bayi ni Olorun se ri", tabi " Bayiko ni Olorun se ri". "Ko s'Olorun", " Olorun o leni Irisi". Iranu ni gbogbo awon nkan ton so yi, nitoripe koseyi ninu wan to laari. Nitorina ni Bhagavān se sowipe, avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritāḥ (BG 9.11). Nitori wa ni Olorun sen wa ni irisi eyan, sugbon awon asiwere wanyi rope eyan lasan loje. Ti Bhagavān ba sowipe ahaṁ bīja-pradaḥ pitā (BG 14.4), " Emini Baba gbogbo agbaye", gbogbo lamo wipe eyan ni baba wa, baba re eyan na loje kilode teyin wa rope eyan koni Olorun je? Kilode? Agbudo ko lodo Bhagavan, eda to logbon ju. Iwe mimo Bhagavad-gītā si je iwe to kunfun imoye nipa Olorun. Kosi basele yi oro towa ninu Bhagavad-gītā. Iranu niyen. Awan tele ofin yi ninu egbe imoye Krsna wayi. Awa o lee da nkan wa sile. Ati pin oro Olorun nise tawa ni. Adeti bere sini sise na.