YO/Prabhupada 0443 - There is no Question of Impersonalism: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 French Pages with Videos Category:Prabhupada 0443 - in all Languages Category:FR-Quotes - 1968 Category:FR-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 1: Line 1:
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
[[Category:1080 French Pages with Videos]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0443 - in all Languages]]
[[Category:Prabhupada 0443 - in all Languages]]
[[Category:FR-Quotes - 1968]]
[[Category:YO-Quotes - 1968]]
[[Category:FR-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:FR-Quotes - in USA]]
[[Category:YO-Quotes - in USA]]
[[Category:FR-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0442 - In Christian Theology, one Prays to God, 'Give us our Daily Bread'|0442|YO/Prabhupada 0444 - Gopis Are Not Conditioned Souls. They Are Liberated Spirits|0444}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 15: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|MlHFEMpisvU|Il n’est pas question d’impersonalisme <br/>- Prabhupāda 0443}}
{{youtube_right|MlHFEMpisvU|There is no Question of Impersonalism <br/>- Prabhupāda 0443}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/681127BG.LA_clip9.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/681127BG.LA_clip9.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 31: Line 34:
Olufokasin: t'awa o ba ni iyato kankan, beena ki wa nidi fun Krsna lati salaye lori oro na titi de asiko ojoiwaju."
Olufokasin: t'awa o ba ni iyato kankan, beena ki wa nidi fun Krsna lati salaye lori oro na titi de asiko ojoiwaju."


Prabhupada: Beeni. O sowipe kosigba kankan t'awa o ni je eda ototo, kode sni si gba lojowaju tawa o ni wa looto. Nisin gbogbo si yato si ara wa. E mo bee. Beena nibo l'oro pe awa ba di ikan soso? Rara. Kolese se. Eto pe ikan ni gbogbo nkan aye yi, ona eka lati ma salaaye nipa awon orisirisi aye yi. Nkan tio da nipa eto yi niyen. Apa to da ko leleyi. Apa re to da niwipe, Krsna sowipe, tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti kaunteya ([[Vanisource:BG 4.9|BG 4.9]]). " Lehin igba teyin ba fi ile aye yi sile, e pada wa ba Mi." Fun apeere teba fi yara yi sile, egbo do wole sinu yara imi. Eyin o le sowipe lehin igbatin ba fi yara yi sile, ma lo gbe lori ofurufu." Beena, lehin igba teyin ba fi ile aye yi sile ema pada si Krsna ninu odo metalokan, esi ma wa besewa na, sugbon eyin ma ni ara mimo. Teba ni ara mimo yi, koni sejo isoro mo. gege bi ara yin se yato si ara awon eja. Awon eja ninu omi, kosi isoro kankan fun won nitoripe ara baaramu pel'omi na. Won le gbe ninu omi l'aalafia. Eyin o le gbe nibe. beena awon eja teba yo won kuro ninu omi, kole gbe mo . beena, nitoripe eyin je emi mimo, eyin o le gbe ninu aye yi l'alaafia. Ibi ajeji leleyi. Sugbon lesekese teyin ba wole si odo metalokan, ile aye yin ba wa tayeraye, pelu idunnu at'ogbon, at'alafia. Tyaktvā dehaṁ punar janma naiti ([[Vanisource:BG 4.9|BG 4.9]]). Krsna sowipe, " Lehin igba toba kuro ninu aye yi, kole pada si awon idamu aye yi." Mām eti, "A pada si Mi." ijoba re nitumo "Emi", awon oun elo re, awon akkabasepo re, gbogbo nkan. T'okurin olowo ba sowipe, " O da wa bami," Iyen o wipe ai seyna ko loje. T'oba ba sowipe, " Wa.. itumo re niwipe o ni ijoba re, osi ni awon onise re, Osi ni ile to da, pelu gbogbo nkan to da. Bawo lose je aimaseyan? Sugbon osowipe, " Wa bami." Itumo "emi" ni gbogbo nkan. Aimaseyan ko nitumo oro " emi" yi. Ati ni iroyin lati Brahma-samhita, lakṣmī-sahasra-śata-sambhrama-sevyamānaṁ... surabhīr abhipālayantam (Bs. 5.29). Beena eyan loje. Osin toju awon maalu, Pelu aimoye awon orisa ola, awon re re, awon ohun elo re, ijoba re, ile re, gbogbo nkan to ni wa n'be. beena kosejo aimaseyan.
Prabhupada: Beeni. O sowipe kosigba kankan t'awa o ni je eda ototo, kode sni si gba lojowaju tawa o ni wa looto. Nisin gbogbo si yato si ara wa. E mo bee. Beena nibo l'oro pe awa ba di ikan soso? Rara. Kolese se. Eto pe ikan ni gbogbo nkan aye yi, ona eka lati ma salaaye nipa awon orisirisi aye yi. Nkan tio da nipa eto yi niyen. Apa to da ko leleyi. Apa re to da niwipe, Krsna sowipe, tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti kaunteya ([[Vanisource:BG 4.9 (1972)|BG 4.9]]). " Lehin igba teyin ba fi ile aye yi sile, e pada wa ba Mi." Fun apeere teba fi yara yi sile, egbo do wole sinu yara imi. Eyin o le sowipe lehin igbatin ba fi yara yi sile, ma lo gbe lori ofurufu." Beena, lehin igba teyin ba fi ile aye yi sile ema pada si Krsna ninu odo metalokan, esi ma wa besewa na, sugbon eyin ma ni ara mimo. Teba ni ara mimo yi, koni sejo isoro mo. gege bi ara yin se yato si ara awon eja. Awon eja ninu omi, kosi isoro kankan fun won nitoripe ara baaramu pel'omi na. Won le gbe ninu omi l'aalafia. Eyin o le gbe nibe. beena awon eja teba yo won kuro ninu omi, kole gbe mo . beena, nitoripe eyin je emi mimo, eyin o le gbe ninu aye yi l'alaafia. Ibi ajeji leleyi. Sugbon lesekese teyin ba wole si odo metalokan, ile aye yin ba wa tayeraye, pelu idunnu at'ogbon, at'alafia. Tyaktvā dehaṁ punar janma naiti ([[Vanisource:BG 4.9 (1972)|BG 4.9]]). Krsna sowipe, " Lehin igba toba kuro ninu aye yi, kole pada si awon idamu aye yi." Mām eti, "A pada si Mi." ijoba re nitumo "Emi", awon oun elo re, awon akkabasepo re, gbogbo nkan. T'okurin olowo ba sowipe, " O da wa bami," Iyen o wipe ai seyna ko loje. T'oba ba sowipe, " Wa.. itumo re niwipe o ni ijoba re, osi ni awon onise re, Osi ni ile to da, pelu gbogbo nkan to da. Bawo lose je aimaseyan? Sugbon osowipe, " Wa bami." Itumo "emi" ni gbogbo nkan. Aimaseyan ko nitumo oro " emi" yi. Ati ni iroyin lati Brahma-samhita, lakṣmī-sahasra-śata-sambhrama-sevyamānaṁ... surabhīr abhipālayantam (Bs. 5.29). Beena eyan loje. Osin toju awon maalu, Pelu aimoye awon orisa ola, awon re re, awon ohun elo re, ijoba re, ile re, gbogbo nkan to ni wa n'be. beena kosejo aimaseyan.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:59, 13 June 2018



Lecture on BG 2.8-12 -- Los Angeles, November 27, 1968

Prabhupāda: tesiwaju.

Olufokasin: t'awa o ba ni iyato kankan, beena ki wa nidi fun Krsna lati salaye lori oro na titi de asiko ojoiwaju."

Prabhupada: Beeni. O sowipe kosigba kankan t'awa o ni je eda ototo, kode sni si gba lojowaju tawa o ni wa looto. Nisin gbogbo si yato si ara wa. E mo bee. Beena nibo l'oro pe awa ba di ikan soso? Rara. Kolese se. Eto pe ikan ni gbogbo nkan aye yi, ona eka lati ma salaaye nipa awon orisirisi aye yi. Nkan tio da nipa eto yi niyen. Apa to da ko leleyi. Apa re to da niwipe, Krsna sowipe, tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti kaunteya (BG 4.9). " Lehin igba teyin ba fi ile aye yi sile, e pada wa ba Mi." Fun apeere teba fi yara yi sile, egbo do wole sinu yara imi. Eyin o le sowipe lehin igbatin ba fi yara yi sile, ma lo gbe lori ofurufu." Beena, lehin igba teyin ba fi ile aye yi sile ema pada si Krsna ninu odo metalokan, esi ma wa besewa na, sugbon eyin ma ni ara mimo. Teba ni ara mimo yi, koni sejo isoro mo. gege bi ara yin se yato si ara awon eja. Awon eja ninu omi, kosi isoro kankan fun won nitoripe ara baaramu pel'omi na. Won le gbe ninu omi l'aalafia. Eyin o le gbe nibe. beena awon eja teba yo won kuro ninu omi, kole gbe mo . beena, nitoripe eyin je emi mimo, eyin o le gbe ninu aye yi l'alaafia. Ibi ajeji leleyi. Sugbon lesekese teyin ba wole si odo metalokan, ile aye yin ba wa tayeraye, pelu idunnu at'ogbon, at'alafia. Tyaktvā dehaṁ punar janma naiti (BG 4.9). Krsna sowipe, " Lehin igba toba kuro ninu aye yi, kole pada si awon idamu aye yi." Mām eti, "A pada si Mi." ijoba re nitumo "Emi", awon oun elo re, awon akkabasepo re, gbogbo nkan. T'okurin olowo ba sowipe, " O da wa bami," Iyen o wipe ai seyna ko loje. T'oba ba sowipe, " Wa.. itumo re niwipe o ni ijoba re, osi ni awon onise re, Osi ni ile to da, pelu gbogbo nkan to da. Bawo lose je aimaseyan? Sugbon osowipe, " Wa bami." Itumo "emi" ni gbogbo nkan. Aimaseyan ko nitumo oro " emi" yi. Ati ni iroyin lati Brahma-samhita, lakṣmī-sahasra-śata-sambhrama-sevyamānaṁ... surabhīr abhipālayantam (Bs. 5.29). Beena eyan loje. Osin toju awon maalu, Pelu aimoye awon orisa ola, awon re re, awon ohun elo re, ijoba re, ile re, gbogbo nkan to ni wa n'be. beena kosejo aimaseyan.