YO/Prabhupada 0632 - If I Realize that I am Not this Body, then I Transcend the three Modes of Nature: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0632 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0631 - I am Eternal, the Body is not Eternal, This is the Fact|0631|YO/Prabhupada 0633 - We are just like the Shining Sparks of Krsna|0633}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:

<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/730830BG-LON_clip_03.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730830BG-LON_clip_03.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 26: Line 29:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
Nitorina ni Śaṅkarācārya se mu imoye re: brahma satyaṁ jagan mithyā. Itumo Brahman niwipe emi wa ni koko oro, nkan aye yi koloje. Iseda aye yi, o sowipe nkan eke ni. Awa sowipe nkan to daju ni sugbon igba die lo wa fun. Beena nkan tose pataki funwa niwipe fun igba die ko nimo wa fun. Ara mi lowa fun igbadie. Nisin mon sise fun ara mi. Itanraeni towa niyen. Ahaṁ mameti ([[Vanisource:SB 5.5.8|SB 5.5.8]]). Lehin na kini kokooro to wa? Otooro ro wa niwipe erunrun nkan mimo nimi, Krsna, tabi Olorun ni emi mimo yi ni pipe. Nitorina, bi nkankanna pelu Olorun ise mi nii lati sise fun Oluwa. Ile aye mimo leleyi, bhakti-yoga, Nkan ton pe ni svarūpa Nibo mi, Bhagavad-gita ti jeerisi pe sa guṇān samatītyaitān brahma-bhūyāya kalpate ([[Vanisource:BG 14.26|BG 14.26]]). Nigbati'n ba riwipe ara eda yi konimi, lehin na lesekese nimole koja awon ipo aye yi: sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa. Labe ipo ara eda yi, moti bosinu ikan ninu awon ipo aye yi mo sin sise.
Nitorina ni Śaṅkarācārya se mu imoye re: brahma satyaṁ jagan mithyā. Itumo Brahman niwipe emi wa ni koko oro, nkan aye yi koloje. Iseda aye yi, o sowipe nkan eke ni. Awa sowipe nkan to daju ni sugbon igba die lo wa fun. Beena nkan tose pataki funwa niwipe fun igba die ko nimo wa fun. Ara mi lowa fun igbadie. Nisin mon sise fun ara mi. Itanraeni towa niyen. Ahaṁ mameti ([[Vanisource:SB 5.5.8|SB 5.5.8]]). Lehin na kini kokooro to wa? Otooro ro wa niwipe erunrun nkan mimo nimi, Krsna, tabi Olorun ni emi mimo yi ni pipe. Nitorina, bi nkankanna pelu Olorun ise mi nii lati sise fun Oluwa. Ile aye mimo leleyi, bhakti-yoga, Nkan ton pe ni svarūpa Nibo mi, Bhagavad-gita ti jeerisi pe sa guṇān samatītyaitān brahma-bhūyāya kalpate ([[Vanisource:BG 14.26 (1972)|BG 14.26]]). Nigbati'n ba riwipe ara eda yi konimi, lehin na lesekese nimole koja awon ipo aye yi: sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa. Labe ipo ara eda yi, moti bosinu ikan ninu awon ipo aye yi mo sin sise.

Ninu Bhagavata na wan salaaye wipe: yayā sammohito jīva ātmānaṁ tri-guṇātmakaṁ manute anartham ([[Vanisource:SB 1.7.5|SB 1.7.5]]). Beena nitoripe moti gba ara eda yi ton sele awon ipo meta aye yi, mosin rowipe ara mi nimi, nitorina motii da anartha to po sile. Awon nkan t'awa o fe nitumo Anartha. Tat-kṛtaṁ cābhipadyate. lehin igba t'aba da awon ibasepo ara eda yi, awon nkan topo t'awa ofe, Mosin ronu pe, lati orile-ede bayi bayi ni moti wa. Nitorina nimo se ni ise lati se fun orile-ede na tabi awujo na, tabi ebi , tabi fun ara mi, tabi fun iyawo mi ati awon omo mi." Imoye Veda niyen, itanra-eni. Ahaṁ mameti ([[Vanisource:SB 5.5.8|SB 5.5.8]]). Janasya moho 'yam. Itanraeni nitumo Moha. Mosin da awon ipo yi ton funmi ni idimu to po. Bi ipo aye mi seri niyen. Sugbon afojusun pataki timo ni, ni bimosele jade kuro ninu itanraeni yi kin pada si imoye talakoko timo ni, Imoye Krsna, lehin na mole pada. Ara eda mimo nitumo imoye Krsna. Lesekese tinba sise lori ara eda mimo timo ni, igbala niyen. Nkan t'afe niyen. Lehin na mole wa dada tayeraye ninu imoye. Isoro timo ni leleyi. Sugbon awon eyan ti keeko nipa ara eda yi, wansi da isoro sile fun ara wan, lati le yonju awon isoro wanyi, wanti soopo ninu ni iwa ese. Gege bi laaro yi, asin soro nipa pipa omode ninu oyun iya re, oyun sise. Nitoripe awa o mope emi wa ninu ara eda omode yi.. Eyin o le fiku pa. Eyin o le fiku pa. Sugbon wanti salaaye wipe, enito ba mo wipe fun tayeraye l'emi eda wa fun, kole pa enikankan, kode si besele pa emi eda na. Sugbon awa sin da isoro sile. Nitoripe emi yi ti wole sinu ara eda imi beena awon onisayensi ologun ton sowipe ke fiku pa awon omo ton wa ninu oyun, won fe ko tun pada sinu idimu aye yi niyen. Eni ton fun won ni iru itosona bayi... Oye mi wipe okunrin kan ati iyawo re toje ologun man wa sibi lati toju awon obirin toloyun ni'se iyawo re. lati fun awon eyan ni itosona boya kon pa omo na tabi kon fisile. Ise tonse niyen.

<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:19, 14 June 2018

Lecture on BG 2.28 -- London, August 30, 1973

Nitorina ni Śaṅkarācārya se mu imoye re: brahma satyaṁ jagan mithyā. Itumo Brahman niwipe emi wa ni koko oro, nkan aye yi koloje. Iseda aye yi, o sowipe nkan eke ni. Awa sowipe nkan to daju ni sugbon igba die lo wa fun. Beena nkan tose pataki funwa niwipe fun igba die ko nimo wa fun. Ara mi lowa fun igbadie. Nisin mon sise fun ara mi. Itanraeni towa niyen. Ahaṁ mameti (SB 5.5.8). Lehin na kini kokooro to wa? Otooro ro wa niwipe erunrun nkan mimo nimi, Krsna, tabi Olorun ni emi mimo yi ni pipe. Nitorina, bi nkankanna pelu Olorun ise mi nii lati sise fun Oluwa. Ile aye mimo leleyi, bhakti-yoga, Nkan ton pe ni svarūpa Nibo mi, Bhagavad-gita ti jeerisi pe sa guṇān samatītyaitān brahma-bhūyāya kalpate (BG 14.26). Nigbati'n ba riwipe ara eda yi konimi, lehin na lesekese nimole koja awon ipo aye yi: sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa. Labe ipo ara eda yi, moti bosinu ikan ninu awon ipo aye yi mo sin sise.

Ninu Bhagavata na wan salaaye wipe: yayā sammohito jīva ātmānaṁ tri-guṇātmakaṁ manute anartham (SB 1.7.5). Beena nitoripe moti gba ara eda yi ton sele awon ipo meta aye yi, mosin rowipe ara mi nimi, nitorina motii da anartha to po sile. Awon nkan t'awa o fe nitumo Anartha. Tat-kṛtaṁ cābhipadyate. lehin igba t'aba da awon ibasepo ara eda yi, awon nkan topo t'awa ofe, Mosin ronu pe, lati orile-ede bayi bayi ni moti wa. Nitorina nimo se ni ise lati se fun orile-ede na tabi awujo na, tabi ebi , tabi fun ara mi, tabi fun iyawo mi ati awon omo mi." Imoye Veda niyen, itanra-eni. Ahaṁ mameti (SB 5.5.8). Janasya moho 'yam. Itanraeni nitumo Moha. Mosin da awon ipo yi ton funmi ni idimu to po. Bi ipo aye mi seri niyen. Sugbon afojusun pataki timo ni, ni bimosele jade kuro ninu itanraeni yi kin pada si imoye talakoko timo ni, Imoye Krsna, lehin na mole pada. Ara eda mimo nitumo imoye Krsna. Lesekese tinba sise lori ara eda mimo timo ni, igbala niyen. Nkan t'afe niyen. Lehin na mole wa dada tayeraye ninu imoye. Isoro timo ni leleyi. Sugbon awon eyan ti keeko nipa ara eda yi, wansi da isoro sile fun ara wan, lati le yonju awon isoro wanyi, wanti soopo ninu ni iwa ese. Gege bi laaro yi, asin soro nipa pipa omode ninu oyun iya re, oyun sise. Nitoripe awa o mope emi wa ninu ara eda omode yi.. Eyin o le fiku pa. Eyin o le fiku pa. Sugbon wanti salaaye wipe, enito ba mo wipe fun tayeraye l'emi eda wa fun, kole pa enikankan, kode si besele pa emi eda na. Sugbon awa sin da isoro sile. Nitoripe emi yi ti wole sinu ara eda imi beena awon onisayensi ologun ton sowipe ke fiku pa awon omo ton wa ninu oyun, won fe ko tun pada sinu idimu aye yi niyen. Eni ton fun won ni iru itosona bayi... Oye mi wipe okunrin kan ati iyawo re toje ologun man wa sibi lati toju awon obirin toloyun ni'se iyawo re. lati fun awon eyan ni itosona boya kon pa omo na tabi kon fisile. Ise tonse niyen.