YO/Prabhupada 0531 - As we Understand from Vedic Literature, Krishna Has many Varieties of Potencies: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0531 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1971 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0530 - One Can be Out of Distress when he Approaches Vishnu|0530|YO/Prabhupada 0533 - Radharani is Hari-priya, Very Dear to Krishna|0533}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/710829RA.LON_Radhastami_clip4.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/710829RA.LON_Radhastami_clip4.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 28: Line 31:
sarva-gah ni oruko awon eda ole lo si ibikibi tobafe ni tumo Sarva-gah gege bi Narada Muni. Narada Muni le losi ibikitobafe, ninu aye yi tabi ninu ijoba orun eyin na lesebayi. O le sese. algbara yogi ni Durvāsā Muni je laarin odun kan ose irin ajo si gbogbo ibikibi ninu agbaye, osi losi Visnuloka otun pada. Awon iwe itan-akoole si ko si le. ilosiwaju aye leleyi. bawo lasele ni ilosiwaju bayi. Taba ni oye nipa Krsna. Yasmin vijñāte sarvam eva vijñātaṁ bhavanti. awon Upanisad sowipe, teba ni oe nipa Krsna, lehin na leleni oye nipa gbogbo nkan. nkan to daa gan ni imoye Krsna je.

Leni awa ma soro nipa Rādhāṣṭamī. Awa femo nipa agbara Krsna to gaju. agbara idunnu Krsna ni Rādhārāṇī je. gege bi awon iwe Veda se so, Krsna ni agbara orisirisi to po. Parāsya śaktir vividhaiva śruyate ([[Vanisource:CC Madhya 13.65|CC Madhya 13.65, purport]]). gege bi okurin toni awon alabasepo to po gan, koni lati sen nkankan fu ara re, pelu agbara re ni gbogbo nkan sen sele, gege na, Olorun sini orisiri agbarfa to po, wanden seto gbogbo nkan dada. gege bi agbara ile-aye yi. ile-aye yi tawan gbe yi.. nkan ton pe ni agbara ile-aye yi. Bahir-aṅga-śakti. Bahir-aṅga ni oruko re ni ede Sanskrit, agbara ita Krsna. seri bi gbogbo nkna sen lo dada ninu ile aye yi. wanti salaaye na ninu Bhagavad-gītā, mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram: ([[Vanisource:BG 9.10|BG 9.10]]) "labe itosona mi ni gbogbo agbara ile-aye yi n'sise". Agbara ile-aye yi o foju. Krsna wa lehin gbogbo e. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ ([[Vanisource:BG 9.10|BG 9.10]]) Agbara il-aye yi ni tumo Prakrti. Gege na... agbara ita niyen gege na osi l'agbara imi to wa, agbara inu. pelu agbara inu yi ni gbogbo ijoba orun sise. Parās tasmāt tu bhavaḥ anyaḥ ([[Vanisource:BG 8.20|BG 8.20]]). osi ni agbara imi, para to gaju, lati ijoba orun. gege bi ile-aye se wa labe agbara ita, gege na ni ijoba oorun se wa labe agbara inu. Rādhārāṇī agbara inu yi Eni ni ojo ifarahan Rādhārāṇī.
Leni awa ma soro nipa Rādhāṣṭamī. Awa femo nipa agbara Krsna to gaju. agbara idunnu Krsna ni Rādhārāṇī je. gege bi awon iwe Veda se so, Krsna ni agbara orisirisi to po. Parāsya śaktir vividhaiva śruyate ([[Vanisource:CC Madhya 13.65|CC Madhya 13.65, purport]]). gege bi okurin toni awon alabasepo to po gan, koni lati sen nkankan fu ara re, pelu agbara re ni gbogbo nkan sen sele, gege na, Olorun sini orisiri agbarfa to po, wanden seto gbogbo nkan dada. gege bi agbara ile-aye yi. ile-aye yi tawan gbe yi.. nkan ton pe ni agbara ile-aye yi. Bahir-aṅga-śakti. Bahir-aṅga ni oruko re ni ede Sanskrit, agbara ita Krsna. seri bi gbogbo nkna sen lo dada ninu ile aye yi. wanti salaaye na ninu Bhagavad-gītā, mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram: ([[Vanisource:BG 9.10 (1972)|BG 9.10]]) "labe itosona mi ni gbogbo agbara ile-aye yi n'sise". Agbara ile-aye yi o foju. Krsna wa lehin gbogbo e. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ ([[Vanisource:BG 9.10 (1972)|BG 9.10]]) Agbara il-aye yi ni tumo Prakrti. Gege na... agbara ita niyen gege na osi l'agbara imi to wa, agbara inu. pelu agbara inu yi ni gbogbo ijoba orun sise. Parās tasmāt tu bhavaḥ anyaḥ ([[Vanisource:BG 8.20 (1972)|BG 8.20]]). osi ni agbara imi, para to gaju, lati ijoba orun. gege bi ile-aye se wa labe agbara ita, gege na ni ijoba oorun se wa labe agbara inu. Rādhārāṇī agbara inu yi Eni ni ojo ifarahan Rādhārāṇī.

gege na agbudo gbiyanju lati monipa awon amuye Rādhārāṇī. Rādhārāṇī ni agbara igbadun, hlādinī-śakti. Ānandamayo 'bhyāsāt (Vedānta-sūtra 1.1.12). Ninu Vedānta-sūtra, wanti juwe otito yi bi ānandamaya, agbara igbadun. ānandamaya, agbara igbadun yi... gege bi ananda. Teba fe ananda nkan igbadun, kosi besele ri ounikan gba. kosi beyin nikan sele gbadun. Teba wa laarin awon ore yin, tabi ebi yin tabi awon alabasepo yin, ele ri igbadun yi. gege bi mo sen soro. Oro siso dun so ti awon eyan ba po nibi. Kosi bi mosefe ba ara mi soro. Ananda koniyen Mole soro nibi lale, nigbati gbogbo eyan ti lo. sugbon Ananda koniyen. Awon gbudo wanbi itumo ananda niyen.

<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:09, 14 June 2018

Radhastami, Srimati Radharani's Appearance Day -- London, August 29, 1971

sarva-gah ni oruko awon eda ole lo si ibikibi tobafe ni tumo Sarva-gah gege bi Narada Muni. Narada Muni le losi ibikitobafe, ninu aye yi tabi ninu ijoba orun eyin na lesebayi. O le sese. algbara yogi ni Durvāsā Muni je laarin odun kan ose irin ajo si gbogbo ibikibi ninu agbaye, osi losi Visnuloka otun pada. Awon iwe itan-akoole si ko si le. ilosiwaju aye leleyi. bawo lasele ni ilosiwaju bayi. Taba ni oye nipa Krsna. Yasmin vijñāte sarvam eva vijñātaṁ bhavanti. awon Upanisad sowipe, teba ni oe nipa Krsna, lehin na leleni oye nipa gbogbo nkan. nkan to daa gan ni imoye Krsna je.

Leni awa ma soro nipa Rādhāṣṭamī. Awa femo nipa agbara Krsna to gaju. agbara idunnu Krsna ni Rādhārāṇī je. gege bi awon iwe Veda se so, Krsna ni agbara orisirisi to po. Parāsya śaktir vividhaiva śruyate (CC Madhya 13.65, purport). gege bi okurin toni awon alabasepo to po gan, koni lati sen nkankan fu ara re, pelu agbara re ni gbogbo nkan sen sele, gege na, Olorun sini orisiri agbarfa to po, wanden seto gbogbo nkan dada. gege bi agbara ile-aye yi. ile-aye yi tawan gbe yi.. nkan ton pe ni agbara ile-aye yi. Bahir-aṅga-śakti. Bahir-aṅga ni oruko re ni ede Sanskrit, agbara ita Krsna. seri bi gbogbo nkna sen lo dada ninu ile aye yi. wanti salaaye na ninu Bhagavad-gītā, mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram: (BG 9.10) "labe itosona mi ni gbogbo agbara ile-aye yi n'sise". Agbara ile-aye yi o foju. Krsna wa lehin gbogbo e. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ (BG 9.10) Agbara il-aye yi ni tumo Prakrti. Gege na... agbara ita niyen gege na osi l'agbara imi to wa, agbara inu. pelu agbara inu yi ni gbogbo ijoba orun sise. Parās tasmāt tu bhavaḥ anyaḥ (BG 8.20). osi ni agbara imi, para to gaju, lati ijoba orun. gege bi ile-aye se wa labe agbara ita, gege na ni ijoba oorun se wa labe agbara inu. Rādhārāṇī agbara inu yi Eni ni ojo ifarahan Rādhārāṇī.