YO/Prabhupada 0009 - Ole todi Elesin: Difference between revisions
YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0009 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...") |
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version) |
||
Line 9: | Line 9: | ||
[[Category:Yoruba Language]] | [[Category:Yoruba Language]] | ||
<!-- END CATEGORY LIST --> | <!-- END CATEGORY LIST --> | ||
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE --> | |||
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0008 - Krishna sowipe "baba gbogbo agbaye nimi"|0008|YO/Prabhupada 0010 - Ema farawe Krishna|0010}} | |||
<!-- END NAVIGATION BAR --> | |||
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | <!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | ||
<div class="center"> | <div class="center"> | ||
Line 17: | Line 20: | ||
<!-- BEGIN VIDEO LINK --> | <!-- BEGIN VIDEO LINK --> | ||
{{youtube_right| | {{youtube_right|DUic5g1KInI|The Thief Who Became A Devotee - Prabhupāda 0009}} | ||
<!-- END VIDEO LINK --> | <!-- END VIDEO LINK --> | ||
<!-- BEGIN AUDIO LINK --> | <!-- BEGIN AUDIO LINK --> | ||
<mp3player> | <mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/720815SB.LA_clip.mp3</mp3player> | ||
<!-- END AUDIO LINK --> | <!-- END AUDIO LINK --> | ||
Line 29: | Line 32: | ||
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT --> | <!-- BEGIN TRANSLATED TEXT --> | ||
Olorun, Krishna, so ninu iwe mimô Bhagavad-Gita ([[Vanisource:BG 7.25|BG 7.25]]) nāhaṁ prakāśaḥ sarvasya yoga-māyā-samāvṛtaḥ "Kiise gbogbo eniyan ni Emi nfara han. Yogamāyā, yogamāyā imôlè ati ofurufu mi nbo won loju." Nitorina bawo ni è se le ri Olorun? Sugbon ise jaguda yi nlô kaa kiri, ti won wipe "Se iwô le fi Olorun han mi" Se o ti ri Olorun? Olorun wa di bi nkan isere. "Olorun ni yi. Oun ni Olorun to sô ka lè wa." ([[Vanisource:BG 7.15|BG 7.15]]) Na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ prapadyante narādhamāḥ Elèsè ni won, jaguda, omugô ati awon ti ipin won kere julô laarin awon ômô èda ni won. Won beere bayi "Se o le fi Olorun han mi?" Ki ni ipo ti o ni ti iwô fi le ri Olorun? Ipo naa ni yi. Ki ni nkan na? Tac chraddadhānā munayaḥ. Ni akôkô a gbôdô je onigbagbô ododo. Igbagbô ododo. Śraddadhānāḥ. O gbôdô ni ôyaya lati ri Oluwa, ni tootô. Ko nse ni pa ti igberaga, tabi nkan ta fi iyèwu, "Se o le fi Olorun han mi." Majik, tabi wipe Olorun je majik. Rara. O gbodo je eniti o ni ironu: "Beeni, ti Olorun ba wa... A ti ri, won ti se ijise Olorun fun wa. Nitorina mo gbodo rii" | Olorun, Krishna, so ninu iwe mimô Bhagavad-Gita ([[Vanisource:BG 7.25 (1972)|BG 7.25]]) nāhaṁ prakāśaḥ sarvasya yoga-māyā-samāvṛtaḥ "Kiise gbogbo eniyan ni Emi nfara han. Yogamāyā, yogamāyā imôlè ati ofurufu mi nbo won loju." Nitorina bawo ni è se le ri Olorun? Sugbon ise jaguda yi nlô kaa kiri, ti won wipe "Se iwô le fi Olorun han mi" Se o ti ri Olorun? Olorun wa di bi nkan isere. "Olorun ni yi. Oun ni Olorun to sô ka lè wa." ([[Vanisource:BG 7.15 (1972)|BG 7.15]]) Na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ prapadyante narādhamāḥ Elèsè ni won, jaguda, omugô ati awon ti ipin won kere julô laarin awon ômô èda ni won. Won beere bayi "Se o le fi Olorun han mi?" Ki ni ipo ti o ni ti iwô fi le ri Olorun? Ipo naa ni yi. Ki ni nkan na? Tac chraddadhānā munayaḥ. Ni akôkô a gbôdô je onigbagbô ododo. Igbagbô ododo. Śraddadhānāḥ. O gbôdô ni ôyaya lati ri Oluwa, ni tootô. Ko nse ni pa ti igberaga, tabi nkan ta fi iyèwu, "Se o le fi Olorun han mi." Majik, tabi wipe Olorun je majik. Rara. O gbodo je eniti o ni ironu: "Beeni, ti Olorun ba wa... A ti ri, won ti se ijise Olorun fun wa. Nitorina mo gbodo rii" | ||
Itan kan wa ni pa oro yi. O ni ipolopo nkan lati ko wa; e feti sile Akewe kan ba nkewe nipa iwe mimo Bhagavata, o ba si nse alaye ni pa Krishina, bi o se wo awon ileke ti o jjo ju, Won ran lati lo se oluso awon malu ni epa-odan. O wa se le wi pe ole kan wa ni ibi ipade yi O wa ronu wipe " Kilode ti mi o ni lo si Vrndavan lati lo ji awon nkan omo odo yi? O wa ninu igbo pelu awon ileke to joju. Mo le lo si be lati lo ko lona, ati ji gbogbo awon ileke re." Ero inu okan re ni yi. Nitorina, o ni ironu gidi wipe 'Mo gbodo ri odomokunri naa Beena ni, loru ojo kan ma di olowo oloro nla opolopo ileke. Rara." Bo se lo si be ni yen, sugbon ipo re ni wipe, "Mo gbodo ri Krishna, Mo gbodo ri Krishna" Aibale okan naa, itaara naa, ran lowo lati ri Krishna nigbati o de vrndavan O ri Krishna gege bi akewe Bhagavata se s'alaye fun. Nigba to wa ri, " Ah ha omo odokunrin to lewa, Krishna" O ba si bere si ponle ni ponle ti o de nu. O ro wipe nipa "Iponle asa yi, emi a ra ye ati ko awon ileke re" Ni gbati o si wa so ero okan re gidi, " Nitori na se mo le mu ninu awon ileke orun re? Ola re po gan" " Rara , rara rara. Iwo... Mama mi o binu. E mi o le se..." Krishna bi omode. Bee ni itaara re di pupo si fun Kishna. Bee na ni.... Ni pa ibalopo re pelu Krishna, o ti di eniti a ya si mimo. Leyin na, ni a ba jade, Krishna so wipe, "O dara, o le mu" Bee ni arakunrin ole yi se d'omo eleyin, lese kan na. Nito ri nipa ti ibaralo po pelu Krishna... | Itan kan wa ni pa oro yi. O ni ipolopo nkan lati ko wa; e feti sile Akewe kan ba nkewe nipa iwe mimo Bhagavata, o ba si nse alaye ni pa Krishina, bi o se wo awon ileke ti o jjo ju, Won ran lati lo se oluso awon malu ni epa-odan. O wa se le wi pe ole kan wa ni ibi ipade yi O wa ronu wipe " Kilode ti mi o ni lo si Vrndavan lati lo ji awon nkan omo odo yi? O wa ninu igbo pelu awon ileke to joju. Mo le lo si be lati lo ko lona, ati ji gbogbo awon ileke re." Ero inu okan re ni yi. Nitorina, o ni ironu gidi wipe 'Mo gbodo ri odomokunri naa Beena ni, loru ojo kan ma di olowo oloro nla opolopo ileke. Rara." Bo se lo si be ni yen, sugbon ipo re ni wipe, "Mo gbodo ri Krishna, Mo gbodo ri Krishna" Aibale okan naa, itaara naa, ran lowo lati ri Krishna nigbati o de vrndavan O ri Krishna gege bi akewe Bhagavata se s'alaye fun. Nigba to wa ri, " Ah ha omo odokunrin to lewa, Krishna" O ba si bere si ponle ni ponle ti o de nu. O ro wipe nipa "Iponle asa yi, emi a ra ye ati ko awon ileke re" Ni gbati o si wa so ero okan re gidi, " Nitori na se mo le mu ninu awon ileke orun re? Ola re po gan" " Rara , rara rara. Iwo... Mama mi o binu. E mi o le se..." Krishna bi omode. Bee ni itaara re di pupo si fun Kishna. Bee na ni.... Ni pa ibalopo re pelu Krishna, o ti di eniti a ya si mimo. Leyin na, ni a ba jade, Krishna so wipe, "O dara, o le mu" Bee ni arakunrin ole yi se d'omo eleyin, lese kan na. Nito ri nipa ti ibaralo po pelu Krishna... |
Latest revision as of 18:41, 14 October 2018
Lecture on SB 1.2.12 -- Los Angeles, August 15, 1972
Olorun, Krishna, so ninu iwe mimô Bhagavad-Gita (BG 7.25) nāhaṁ prakāśaḥ sarvasya yoga-māyā-samāvṛtaḥ "Kiise gbogbo eniyan ni Emi nfara han. Yogamāyā, yogamāyā imôlè ati ofurufu mi nbo won loju." Nitorina bawo ni è se le ri Olorun? Sugbon ise jaguda yi nlô kaa kiri, ti won wipe "Se iwô le fi Olorun han mi" Se o ti ri Olorun? Olorun wa di bi nkan isere. "Olorun ni yi. Oun ni Olorun to sô ka lè wa." (BG 7.15) Na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ prapadyante narādhamāḥ Elèsè ni won, jaguda, omugô ati awon ti ipin won kere julô laarin awon ômô èda ni won. Won beere bayi "Se o le fi Olorun han mi?" Ki ni ipo ti o ni ti iwô fi le ri Olorun? Ipo naa ni yi. Ki ni nkan na? Tac chraddadhānā munayaḥ. Ni akôkô a gbôdô je onigbagbô ododo. Igbagbô ododo. Śraddadhānāḥ. O gbôdô ni ôyaya lati ri Oluwa, ni tootô. Ko nse ni pa ti igberaga, tabi nkan ta fi iyèwu, "Se o le fi Olorun han mi." Majik, tabi wipe Olorun je majik. Rara. O gbodo je eniti o ni ironu: "Beeni, ti Olorun ba wa... A ti ri, won ti se ijise Olorun fun wa. Nitorina mo gbodo rii"
Itan kan wa ni pa oro yi. O ni ipolopo nkan lati ko wa; e feti sile Akewe kan ba nkewe nipa iwe mimo Bhagavata, o ba si nse alaye ni pa Krishina, bi o se wo awon ileke ti o jjo ju, Won ran lati lo se oluso awon malu ni epa-odan. O wa se le wi pe ole kan wa ni ibi ipade yi O wa ronu wipe " Kilode ti mi o ni lo si Vrndavan lati lo ji awon nkan omo odo yi? O wa ninu igbo pelu awon ileke to joju. Mo le lo si be lati lo ko lona, ati ji gbogbo awon ileke re." Ero inu okan re ni yi. Nitorina, o ni ironu gidi wipe 'Mo gbodo ri odomokunri naa Beena ni, loru ojo kan ma di olowo oloro nla opolopo ileke. Rara." Bo se lo si be ni yen, sugbon ipo re ni wipe, "Mo gbodo ri Krishna, Mo gbodo ri Krishna" Aibale okan naa, itaara naa, ran lowo lati ri Krishna nigbati o de vrndavan O ri Krishna gege bi akewe Bhagavata se s'alaye fun. Nigba to wa ri, " Ah ha omo odokunrin to lewa, Krishna" O ba si bere si ponle ni ponle ti o de nu. O ro wipe nipa "Iponle asa yi, emi a ra ye ati ko awon ileke re" Ni gbati o si wa so ero okan re gidi, " Nitori na se mo le mu ninu awon ileke orun re? Ola re po gan" " Rara , rara rara. Iwo... Mama mi o binu. E mi o le se..." Krishna bi omode. Bee ni itaara re di pupo si fun Kishna. Bee na ni.... Ni pa ibalopo re pelu Krishna, o ti di eniti a ya si mimo. Leyin na, ni a ba jade, Krishna so wipe, "O dara, o le mu" Bee ni arakunrin ole yi se d'omo eleyin, lese kan na. Nito ri nipa ti ibaralo po pelu Krishna...
Bee na ni ona kan tabi imiran, agbodo sumo Olorun. Ni ona kan tabi imiran. Nigba na ni a o si di mimo.