YO/Prabhupada 0312 - Man is Rational Animal

Revision as of 12:03, 21 September 2017 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Morning Walk -- April 1, 1975, Mayapur

Prabhupāda: fun emi nisin, egbe imoye Krsna wa yi ju nkan oro lasan lo. nkan tose se. Mole fun yin ni ona abayo fun gbogbo isoro teni.

Puṣṭa Kṛṣṇa: awon eyan nisin wwan o fe se nkankan to ma funwa ni inira.

Prabhupada: Hm?

Puṣṭa Kṛṣṇa: awon eyan wan yi yoole.

Prabhupada: Lehin na wan gbudo jiya lati aisan yi. teyin ba ni aisan lara, egbudo jiya.. Kini inira na? Nibo ni inir ayi wa?

Puṣṭa Kṛṣṇa: Tawa eyna yi o ba gba ogun yi, kosi bon sel ni iwosan.

Prabhupada: Wan gbudo jiya. Okurin to ni aisan laara tio ofe gba ogun bawo lara re se feya? Ogbudo jiya na. Nibo ni iwosan wa fun?

Pancadravida: Wan sowipe awa la ni aisan lara.

Prabhupada: Eh?

Pancadravida: Wan sowipe awwa la ni aisan lara. wan sowipe gbogbo wa lani aisan lara, awon ko.

Prabhupada: Beeni. Awon ton diti rowipe gbogbo eyan na diti. (Erin) Itumo iyen ni wipe eyan ko lonje. Eranko. dipo kon joko ko waadi " se awa la ni aisan yi tabi eyin leni" ejoko ka soro. Iyen gan awon eyan yi o fe. Lehin an? Kileyan lese pelu awon eranko?

Pancadravida: wan sowipe a wa o laju. Awon osi fe dawa laamu mo.

Prabhupada: Kilode teyin sen tiraka nipa awon isoro wanyi na? Kilode teyin se tiraka pelu awon isoro awujo yi? O da yin lamu, sugbon kos'ona abayo fun yin. Nigbogbo agbaye gbogbo awon iwe iroyin kun fun isoro.

Visnujan: Śrīla Prabhupāda, seyin le je kon d'eyan pataki? Toba jepe oniranu ni wan, agbudo wa basele..

Prabhupada: Awon eyan yi o logbon. Gbogbo awon eda wanyi o logbon. Wan sowipe, " Eranko tole rori wo ni Okurin je." Itumo re niwipe ti opolo a o ba sin be, ernako si loje.

Pancadravida: ki leyan lese pelu awon eranko.

Prabhupada: nkan to rorun gan ni. Ara mi ni moje. Mo sin wa idunnu. Kilode ti monse wa idunnu? teyin ba wo oro na, ema riwipe Okurin logbon. Kilode ti monse wa idunnu? Nibo ni idaaun na wa? Oto oro niyen. Gbogbo wa lan wa idunnu. Kilode tasen wa idunnu? Kini idaaun?

Pancadravida: Nitoripe isoro po ninu aye awon eyan yi

Prabhupada:Itumo odikeji niyen.

Kirtanananda: Nitoripe iwa loje funmi pe ki inumi dun.

Prabhupada: Beeni. Iwa mi niwipe, inu mi gbudo dunsi. Talo ni idunnu na. Se ara mi abi emi mi?

Pusta Krsna: Rara, emi.

Prabhupada: Ta lofe idunnu yi? Mofe tojo ara mi - Kilode? Nitoripe mo wa ninu ara yi. Tin ba de kuroo ninu ara yi talo ma wa idunnu na? Ogbon ori leleyi, sugbon awon eyan yi o logbon. Kilode tin mosen wa idunnu yi? Mo sin bo ara mi ki otutu ba ma mu. Kilode tin mosen wa idunnu latyi oru ati otutu? Nitoripe mo wa niny ara yi. Tinba jade koni seejo oru abi otutu. teba fe ju oju titi, ninu oru tabi otutu, kosi nkan to ma sele. talo n'wa idunnu yi na? Awa eyan o mo. FUn talon sise bayi? Awon eyan yi o mo. gege bi ologbo at'aja.

Pusta Krsna: Sugbon wan rowipe awon o ni asiko kankan lati korin oruko Olorun.

Prabhupada: Hm?

Pusta Krsna: Imoye wa niwipe toba fe kini inu re dun egbudo sise lataaaro daale.

Prabhupada: Hm. Imoye wan niyen. Asiwere ni yin, se awa o sise. Seyi o le se bawa sen se? Awan gbadun aye wa.