YO/Prabhupada 0380 - The Purport to Dasavatara Stotra
Purport to Dasavatara Stotra, CD 8
eda to tele ni Vamanadeva. Arara ni Vamanadeva je, O si lo ba Bali Maharaja lati bere ile ese meta pere, sugbon oluko (guru) re, Sukracarya, si sofun koma gba nitoripe Visnu loje. Sugbon inu Bali Maharaja si dun gan pe o le fun Visnu ni nkan, O si fi guru re sile, nitoripe ko gba lati je ko sise fun Visnu. Nitorina ni Bali Maharaja se je ikan ninu awon mahajanas. Koseni tole da esin Visnu duro. teni kankan ba fe da esin yi duro, ko baa je baba, tabi ebi seyan, egbudo fi sile, lesekese. Nitorina ni Bali Maharaja se je mahajana. Osi f'apeere han wa: nitoripe guru re si fi isoro sori ona esin re s'Olorun Visnu, o si fi guru re sile. Bayi lose toro lowo re, sugbon itanje leleyi je sugbon Bali Maharaja si gba lati je ji Olorun tanje. Aami awon elesin niyen. Oukoun t'Olorun base awon elesin ma gba, Bali Maharaja si riwipe Olorun fe tanje. Osi beere fun ile to tobito ese meta, sugbon o gba gbogbo agbaye lowo re. pelu ese meji asi bo gbogbo agbaye lat'oke delee. Vamanadeva si beere lowo re pe nibo lole fi ese keta si? Bali Mahraja si gba, " Olorun mi E le fi sori mi, mosi l'ara mi." Bayi lose ra Olorun Visnu, Vamanadeva, Vamanadeva si di olusona fun Bali Maharaja. nitoripe osi fun gbogbo nkna toni, sarvatma snapane bali, o fun Olorun ni gbogbo nkan to ni, bayi lose ra Olorun fun ara re. Olorun si duru bi olusona Bali Maharaja. Bee na, chalayasi vikramane balim adbhuta-vamana pada-nakha-nira-janita-jana-pavana, nigbati Vamadeva si naa ese re soke, ika ese re fi'ho sinu idaabo agbaye yi, latinu iho yi ni omi Ganges tin wa lati Vaikuntha. Pada-nakha-nira-janita, Ganges yi sin san ninu agbaye wa, osi ya gbogbo agbaye yi si mimo, ibikibi t'omi Ganges ba wa Pada-nakha-nira-janita-jana-pavana. Eda to kan ni Bhrgupati, Parasurama. saktyavesa avatara ni Parasurama je. fun igba mokanlelogun lowa lati pa awon ksatriyas. Pelu iberu Parasurama, gbogbo awon ksatriya si salo si Europu, wansi salaaye ninu itan-akole , Mahabharata. Fun igba mokanlelogun lo fiku a awon ksatriyas. Wan se isekuse, nitorina lose pa wan, Osi ni agba-omi nla ni Kuruksetra ton fi gbogbo eje awon eyan si. Leyin na gbogbo eje yi si d'omi. bee na ksatriya-rudhira, lati fun ile agbaye yi ni ifokanbale, Osi fi eje awon ksatriya wanyi fi re ile na, snapayasi payasi samita-bhava-tapam. Vitarasi diksu rane dik-pati-kamaniyam dasa-mukha-mauli-balim ramaniyam. Eda to kan ni Ramacandra. Bee na Ravana yi sini ori mewa, osi peja s'Olorun, Olorun Ramacandra si daaun si ipeaja re, leyin na o fi ku pa. vahasi vapusi visade vasanam jaladabham hala-hati-bhiti-milita-yamunabham. nigbati Baladeva fe ki Yamuna wa ba, ti o ko lati wa. Nitorin o si pin ile aye yi si meji pelu ero itule re, nigbana ni Yamuna daaun, osi wa ba Olorun. Hala-hati-bhiti-yamuna, hala-hati-bhiti-milita-yamunabham, Olorun Baladeva si fiyaje Yamuna. Kesava dhrta-haladhara-rupa, hala, ero-itule nitumo haladhara haladhara-rupa jaya jagadisa hare. Leyin na, Buddha, Olorun Buddha. Nindasi yajna-vidher ahaha sruti-jatam. Olorun Buddha si koawon eyan lati keyin si awon iwe mimo Veda, nitoripe ise re ni lati fi ipaari si pipa awon eranko. ninu awon Veda, ninu awon ebo kan, wan le p'eran. Bee na, awon ton pe'ra wan ni elesin ofin Veda, wansi fe fi ipaari si ise Buddhadeva to wa lati fi ipari si pipa won eranko, nitorina ti awon eyan ba fe yo awon ijerisi lati Veda, wipe, ninu Veda ni apa bayi bayi wanso wuipe a le p'eran fi sebo, kilode teyin se fe fi ipaari si? nindasi, osi yiwan pada. Sugbon nitoripe o yi awon oro Veda, nitorina ni imoye Buddha o se wulo ni orile-ede India. Nastika, enikeni toba sowipe awon Veda o daju, nastika loje, alanigbagbo. Eyan o le se koma teriba fun awon Veda. Beena, lati toju awon eranko, Olorun Buddha si yi awon oro Veda. Kesava dhrta buddha-sarira jaya jagadisa. Eda to kan ni Kalki. Asin duro de, leyin odun ogun-oke lati isin, Kalki avatara yi ma wa, asi mu ada lori esin, bi Oba, Asi fi ku pa gbogbo awon alainigbagbo wanyi, awon eda tio beru Olorun. Koni si iwaasu kankan mo. Nitoripe eda to wa lati sewaasu ti koja, nigbati Kalki ba ma wa gbogbo awon eyan aye yi ati fe d'eranko tan, koni s'agbara lati monipa Olorun mo, tabi nkan t'esin je. O ti bere na, asiko Kali-yuga yi. Sugbon o ma po si. Awon eyan o ni le mo nipa imoye Olorun mo, imoye Olorun. Nigbana koni s'ona mi afi kon fiku pa gbogbo wan, ki asiko Satya-yuga imi le bere. Bi ona.. ( ko see gbo).