YO/Prabhupada 0382 - The Purport to Dasavatara Stotra

Revision as of 12:14, 21 September 2017 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Purport to Sri Dasavatara Stotra -- Los Angeles, February 18, 1970

Vamana ni eda, arara to kan Olorun Vamana si farahan si Bali Maharaja. Itanje imi tun leleyi. Bali Mahārāja si ni idari lori gbogbo agbaye, awon orisa gan beru E. Vamanadeva si loba Bali Maharaja, pe " E funmi l'ebun. Brahmana nimi. Moti wa toro lowo yin " Bali Mahraja sowipe, " Beeni ma funyin." osi fe ile to tobi to ese meta soso. Pelu ese kan, o si bo gbogbo agbaye yi, apa oke, pelu ese keji, idaji to ku si tan. Pelu ese keta Bali Maharaja sowipe, " Beeni, nisin nibo ni mole gbe ese keta si. E daakun e gbe ese yin sori mi. Ori mi si wa nibi." Inu Vamanadeva si dun gan pelu iwa Bali Maharaja. Osi fi gbogbo nkan sile fun Olorun. Gege na oun ni ikan ninu awon oludari wanyi. Ninu oludari mejila, Bali Maharaja je ikan ninu wan, nitoripe o fun Olorun nigbogbo nkan lati fun Olorun nitelorun. Iyi to kan ni Parasurama. Parasurama, fun igba mokanlelogun lo wa lati pa awon oba ksatriya wanyi. Awon oba ksatriya nigbayen o ni oto kankan lenu, gege na osi wa lati pa wan fun igba mokanlelogun. Wansi saloo. lati itan-akoole Mahabharata o yewa pe, awon ksatriya kan si salo si awon orile-ede Europu. awon ara ilu indo-Europu lati awon ksatriya yi lonti wa. Itan akoole lleyi, itan-akoole lati Mahabharata. eda to kan ni Olorun Rama. O si ba Ravana ja, to l'ori mewa. eda to kan ni Balarama. Balarama l'egbon Krsna. Edan toni irisi re lati Sankarsana, eda to kan lehin Krsna. Gege na osi l'ara funfun, osi wo aso bulu, pelu ero itule, osi binu si odo Yamuna, osi fe la omi odo Yamuna gbe. Wanti salaaye yi nibi. pelu iberu Yamuna si jade wa dauun si Balarama. Eda to kan ni Olorun Buddha. OLorun Buddha, oun lo yi awon eyan pada lati ofi Veda. Nitorina ale juwe re bi alainigbagbo. Enikeni tio ba gba awon ofin Veda, alainigbagbo loje. gege bi awon ti wan o ni'gbagbo ninu bibeli, awon keferi, bee na, awon eyan ti ba gba ofin awon Veda, alainigbagbi lon pe wan. Gege na Olorun Buddha botilejepe lati irisi Krsna loti wa, O sowipe " Mio ni'gbagbo ninu awon Veda." Kini idi fun eleyi? Lati toju awon eranko. L'asiko yi awon eyan sin fiku pa awon eranko nitoripe wan s'ebo. Awon eda pelu iwa esu, si feran lati se isekuse labe idaabo awon olori. gege bi awon adajo man lo awon iwe-ofin lati fi yi awon ofin pada. gege bayi, awon esu wanyi sin lo awon iwe mimo lati fi se isekuse. Awon nkan wanyi sele. Labe oruko pe wan s'ebo wan fiku a awon eranko bonsefe. Gege na Olorun si l'aanu fun awon ernako wanyi, osi farahan bi Olorun Buddha, imoye to si wa kowa ni alaafia. Imoye awon alainigbagbo losi sewaasu fun nitorina lose sowipe " Ko s'Olorun. Teba ko awon oun elo aye yi paapo, ele da nkan sile, teba si tu wan ka, koni si nkankan mo, kode ni si ejo igbadun tabi ilera. Nirvana niyen, ipinnu aye yi." Imoye to muwa niyen. Sugbon niotooro, ise towa se ni bosele fi ipaari si pipa awon eranko, lati fi ipaari si gbogbo awon ese ti awon eyan da. Beena wansi gbadura si Oorun Buddha nibi. Asi ya awon eyan lenu, pe alainigbagbo ni Buddha je, awon Vaisnava sin gbadura si Visnu (Buddha). Kilode? Nitoripe awon Vaisnava mo wipe Olorun sise fun awon ise orisirisi ti awon eyan o mo. Avatar to tele ni Kalki. Koi ti de. Kalki avatara ma wa ni ipaari asiko tawayi, Kali-yuga. iye akoko asiko Kali-yuga yi, Ni odun ogun-oke Ni ipaari Kali, lasiko to keyin, lehin odun ogun-oke, eda Kali ma farahan. Wanti se asotele yi ninu awon iwe Veda, gege bi asotele ifarahan Buddha se wa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. wansi ko iwe Śrīmad-Bhāgavatam yi ni odun egbeedogbon to koja, Olorun Buddha si farahan ni odun orundinlegbetala tokoja. Beena oye wa pe asotele fun Buddha wa pe ni ibeere asiko Kali-yuga Olorun Buddha ma farahan. Asotele to wa niyen, o dee ti sele. Gege na, asotele na wa nipa Kalki avatara, iyen na asi sele. Nigbana, lati fiku pa awon ni ise Kalki ma je. Koni si ilana kankan. Olorun Krsna ti fun wa ni awon ilana ninu iwe Bhagavad-gita. Sugbon nipaari Kali-yuga, awon eyan ma woo le tojepe koni si oro pe eyin fe fun wan ni ilana kankan. Kole ye wan. Nigbana lati pa wan nikan lo ye. Awon eyan t'Olorun ba pa, wansi ni igbala. Ore-ofe Olorun niyen. Ijeere kanna lowa toba pa awon eyan tabi toba fun wan laabo. asiko to keyin ninu Kali-yuga niyen maj je, Lehin na asiko esin ma bere, Satya-yuga. awon oro Veda leleyi.