YO/Prabhupada 1061 - Ninu Bhagavad-gita, lati ni oye nipa ooto oro marun orisirisi ni koko oro re je

Revision as of 09:26, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1061 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Beena Oluwa Krsna, tio soka le wa, yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati (BG 4.7), lati da ipinnu aye gidi. Ti awon eda eyan ba gbagbe ipinnu aye yi, ipinnu gidi aye eda eyan, lehin na dharmasya glanih loje, idamu fun ise eda eyan. Beena ninu aimoye eda eyan, eyan toba ji emi imoye nipa ipo re so ke, fun eyan bayi lon se s'oro Bhagavad-gita. Okunkun aye yi ti gbe wa mi bi ekun, Olorun si ni ore-ofe to po gan fun awon eda aye yi, nipataki fun awon eda eyan, Oti salaye lori Bhagavad-gita, tosi so ore re Arjuna di akeeko re.

Arjuna toje alabasepo ti Krsna si gaju gbogbo awon alaimokan ninu aye yi. Sugbon Arjuna si wa ninu aimokan lori ile ogun Kuruksetra lati le bi Olorun nipa awon isoro aye yi beena Olorun le salaaye fun ijeere awon iran ojoowaju eda eyan, lati le seto igbese aye re gege na ki ipinnu aye re bale wa ni pipe.

Beena ninu Bhagavad-gita otoo oro marun orisirisi lowa ninu re. Otooro talakoko niwipe, Ta l'oloorun je. Ipo talakoko ninu ikeeko nipa sayensi Olorun. Beena wanti salaaye nipa sayensi Olorun nibi. Eyi to kan, ni ipo awon eda aye yi, jiva. Isvara ati jiva. Olorun, Eledumare, isvara loruko re je. Oludari nitumo Isvara, ati jiva, awon eda aye yi.. Awon eda o kin se isvara tabi oludari. Awon lon wa labe idari Oluwa. Tin ba rowipe "koseni toni idari lori mi, mole se bi mosefe," iwa eyan to logbon ko niyen. Gbogbo awon eda lon wa labe idari nkan Ninu aye yi, o wa labe idari nkan. Beena ninu Bhagavad-gita koko oro to wa ni eto isvara, oludari to gaju, ati awon eda ton wa labe idari re, ati prakrti, iseda aye yi, ile aye yi. aasiko, tabi igbese aye wa ninu ile aye yi, tabi iseda gbogbo agbaye, ati iye asiko, tabi asiko taye raye. ati karma. Ise nitumo Karma. Gbogbo nkan, gbogbo agbaye yi lo kun fun orisirisi ise. Awon eda nipataki, gbogbo won lon sise orisirisi. Beena agbodo keeko lati Bhagavad-gita, isvara, eni t'olorun je, jiva, tani awon eda wanyi, ati prakrti, nkan ti ile aye yi je, ati bi asiko se ni idari lori re, ati iru ise wo ni awon ise wanyi?

Nisin ninu awon eto marun wanyi, ninu Bhagavad-gita wanti daale pe, Olorun, tabi Krsna tabi Brahman tabi Paramatma... Ele pe ni ounkoun teba fe. Sugbon Olori to gaju. Oni olori to gaju gbogbo wa to wa. Beena olori to gaju yi lo lagbara ju. Awon eda aye yi sini iwa bi oludari to gaju. gege bi oludari to gaju, Olorun, Oun loni idari lori agbaye, lori ile aye yi, Wan ma salaaye ninu awo apa iwe ti Bhagavad-gita pe iseda aye yi kole danikan wa. On sise labe itosona Olorun. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram (BG 9.10). "Ile aye yi n'sise labe itosona mi, "mayādhyakṣeṇa, "labe itosona ijoba mi."