YO/Prabhupada 0201 - Besele fi ipaari si Iku

Revision as of 23:36, 13 June 2018 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture on CC Madhya-lila 20.102 -- Baltimore, July 7, 1976

Gbogbo eda n'gbekele imo Ohun, sugbon oni awon nkon ti oole ye wa. Gege bi Sanatana Goswami fi ye wa kpelu iwa re kpe agbodo gba laaye Oluko mimo ka si wi pe bi oro re " emi naa mo jiya bayi" Eyan kpataki le je, ko de si oro kpe oun jiya. O de ni aye to dara Gege bi o ti fi ye wa kpe grāmya-vyavahāre paṇḍita, tāi satya kari māni. Ibeere ti mi O ni idhaun fun si kpo. Ko de si ono abayo Sugbon awon eyan wi pe eniyan kikoo ni mo je - Emi na si gbabe bi eyan ti o logbon Kosenikeni to le so wi kpe eniyan kikoo l'oun je afi to ba lo ba Oluko. Tad-vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12). Nitorina iwe mimo Veda fi ye wa kpe ta ba fe di eniyan kikoo agbudo lo ba Oluko, Oluko to julowo, kii se Oluko a se da.

tad viddhi praṇipātena
paripraśnena sevayā
upadekṣyanti te jñānaṁ
jñāninas tattva-darśinaḥ
(BG 4.34)

Itumo Oluko ni eniyan ti oti ri Otito to gbehin. Eyan ba yii ni Oluko Tattva-darśinaḥ, Itumo tattva ni Otito to gbehin be na itumo darśinaḥ ni eniyan to ti ri. Gege ba yii la se bere ẹgbẹ wa ta wan kpe ni ẹgbẹ imo ohun Olorun (Krsna) lati fi Otito gbehin hon awon eyan. lati ni oye Otito to gbehin, lati mo awọn isoro ti aye, ati bawo lati se kan abayo nkan wonyi ni koko-ọrọ Koko-ọrọ ti awa gbekele kon se awon ohun ti aye bakan tabi awon kan eyan ra ọkọ ayọkẹlẹ, tabi ko ni ile to dara, tabi ko ni iyawo to dara, lẹhinna gbogbo isoro wa ti yonju. Rara. Eleyi ko le fun wa ni abayo fun isoro wa. Isoro gidi ta wa ni, je ba wo la le fi ipari si Iku. Eleyi ni isoro pataki Sugbon ni tori wipe koko-oro to soro ni eyi je, koseni to fe fowo kan. Ah Iku- Je ka kú ni alaafia. Sugbon ko si eniti o ku ni alaafia Ti mo ma mu ọbẹ nla kin si wipe " ni isiyi ogbudo ku ni alaafia" (Erin) Ko le si Alaafia mo ni ibi. Eni eyan no ma sukun. ọrọ isọkusọ lo ma je ti eyan ba wipe " Mo ma ku ni alaafia." kosenikeni to le ku ni alaafia. Ele yi ko ṣee ṣe. Nitorina isoro aye ni Iku je, isoro na ni ibimo. Kosenikeni to ni alaafia ninu ile-ọmọ iya. O si kun ninu ibe, ko de si afẹfẹ ninu be, ati lasiko tawayi ewu pe won le kpa eniyan ninu be si po. Nitorina ko alaafia o le ni itumo, ibimo ati Iku. Lehin naa atijo ojo ori. gege bi mo se je arugbo, isoro ti mo ni si po. be naa atijo ojo ori ati aarun, gbogbo eni eyan lo ti ni iriri, orififo gon ti to lati fun o ni isoro. Isoro gidi ta ni laye ni : Ibimo, Iku, atijo ori-ojo ati aisun Eleyi ni gbólóhùn ti Olurun (krsna) fun wa anma-mṛtyu-jarā-vyādhi duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). Ti eni eyan ba ni oye, agbudo mu isoro merin ta ni laye bi awon ikan to l'ewu.

Sugbon nitoripe awon eni eyan o ni imo ohun, Nitorina lon se yago fun awon ibeere yi. Sugbon awa si mu awon ibeere yi ni pataki. Eleyi ni iyato ninu awon egbe 'mi ati egbe imo ohun Olorun (krsna) Egbe ta wa gbiyonju lati wa ono-abayo si awon isoro wonyi.