YO/Prabhupada 0300 - Eda t'alakoko si wa laaye

Revision as of 23:48, 13 June 2018 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Prabhupāda: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

Elesin: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

Prabhupāda: eto wa ni lati yin Oluwa, Govinda logo imoye krsna niyen, lati mo eda toje Orisun gbogbo nkan gbogbo eyan losi fe mo nipa eyan to je eda alakoko ni ebi wan awon eyan toje orisun Orile-ede, tabi awujo eda, elema ri ipaari sugbon teba lewa eda orisun lateni ti gbogbonkan tiwa , Brahman ni enina je Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Vedanta sutra si sowipe, Brahman ni oun to je Orisun si gbogbo nkan. tumo yi si rorun Tani Olorun, kini Otito to gaju, o rorun gan.

Itumo imoye Krsna yi ni lati ko basele sumo eyan to je orisun gbogbo wa. Eni yi si wa laaye nitoripe lati eyana to gaju ni gbogbo nkan ti wa, awon nkan sin sise dada Orun ran, Osupa njade, awon akoko sin yipa Ale wa, Ojo wa, awon nkan si to dada gege ise ti Olorun daale sin sise dada bawo lesele sowipe Olorun ti ku? gege bi ara eyan, ti dokita bafe mo bi okan yin sise dada asi ye ara yin wo lati mo koni sowipe " okurin bai bai ti ku" sugbon asowipe " Osi wa laaye" gege na teba logbon to, eyin na lemo boya ile-aye yilemi tabi rara osin sise dada. Bawo lesele sowipe Olorun ti ku? Olorun o le Ku. awon asiwere lo da iranu yi , pe Olorun ti ku awon eyan ti wan o mo bi wan sele mo iyato wan si gba eyan tosi mo bosele so iyato laarin nkan toti ku ati nkan to walaaye kole sowipe Olorun ti ku Nitorina ninu Bhagavad-Gita janma karma me divyaṁ yo jānāti tattvataḥ: (BG 4.9) enikeni toba logbon le ni oye na, bimo se ni ibimo, ati bimo sen sise, janma karma efoju si oro yi; janma Kosowipe Janma- mrtyu. Iku ni itumo Mrtyu Gbogbo nkan to walaaye a ku nijokan koseni ton bi tioni ku ara si ni ibimo, nitorina oye ko ku Iku ti wanbe latigba tin bimi bi mo sen dagbasi, itumo re niwipe mon ku die die sugbon ese-iwe Bhagavad-gita si sowipe janma karma, sugbon ko daruko Iku kosibi Iku sefesele. Alainiopin ni OLorun je ateyin na, eyin na oni ku. mosi le gba ara-imi. oye ko ye wa sayensi pataki ni sayensi Imoye Krsna nkan tuntun ko loje, wan si salaaye ninu Bhagavad gita.. Opolopo ninu yin lomo nipa iwe-mimo Bhagavad-gita Bhagavad-gita si sowipe lehin igbati ara yi ba ku.. lehin igbati ara wa ba farahan tabi toba paare Na hanyate. Kosi basele ku itumo Na hanyate niwipe " kole ku" lehin igbati arawa ba ni ipaari.