YO/Prabhupada 0333 - Educating Everyone to Become Divine

Revision as of 23:50, 13 June 2018 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture on BG 16.6 -- Hawaii, February 2, 1975

Evaṁ paramparā-prāptam imaṁ rājarṣayo viduḥ (BG 4.2). gege bayi lose ri. nibi orun je ikan ninu awon iseda Olorun. Orun sini ina to lagbara gan ton fin fun gbogbo agbaye ni orun. Kosi besele paati. Ipo orun niyen. aimoye orun to wa, awon imi de tobi ju awon imi lo. Orun wa lo kere ju, awon to tobi ju lo wa. Gege na awon ina lati ara re le ye wa. Kosi nkankan to le nibe. awon na lati ara Krsna lon pe ni Brahman. Yasya prabhā prabhavato jagad-aṇḍa-koṭi-koṭiṣu vasudhādi-vibhūti-bhinnam, tad brahma: (Bs. 5.40) " Brahman niyen, prabha."

Gege na Krsna wa ninu okan gbogbo eyan kosi ifara kankan ninu irisi yi. gege bi ina orun se je si orun ina Brahman je apa Olorun tio ni irisi kankan latinu ina yi lon wa ibikibi ninu agbaye, aṇḍāntara-stha-paramāṇu-cayāntara-stham... (Bs. 5.35). o wa ninu agbaye yi, owa ni okan yin, owa ninu okan mi. Owa ninu gbogbo nkan. " ninu atom gan, paramanu. Irisi re bi Paramatma niyen. sugbon eyi to se pataki ju ninu Krsna ni ara re Sac-cid-ānanda-vigrahaḥ. Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ sac-cid-ānanda-vigrahaḥ (Bs. 5.1).

Irisi nitumo Vigraha. Irisi o jo tawa. sat, cit, ananda loje. ara re na ni nkan meta. ayeraye nitumo Sat. Gege na ara re yato si tawa. Ara wa fubn igba die loma wa. Ti iya wa ati baba wa bati biwa, ibere wa niyen. Ti ara na ba tan, ipaari re niyen. Ounkooun to ba ni ojo ori, itan akoole loje. Sugbon bayi ko ni Krsna se ri. Anadi. Kosi besefe siro ibere ara Krsna. Anadi. Adi, leyokan si adi. Oun ni ibere gbogbo wa. Anadi. Oun gan ni anadi; koseni to le wa ijo to wa s'aaye. O ju awon itan akole l. gege na oun ni ibere gbogbo wa. gege bi baba mi seje ibere ara mi. Baba mi lo da ibere ara mi Nitorina, oun o ni ibere kankan, koni baba kankan, sugbon oun ni baba gbogbo wa. Ilana to wa niyen, ilan awon Kristiani: Olorun ni Baba to gaju. Otot oro loje, nitoripe oun ni ibere gbogbo wa. Janmādy asya yataḥ: (SB 1.1.1) " ounkoun to wa laye yi, lati Krsna loti wa." Wanto salaaye ninu Bhagavad-gita. Aham ādir hi devānām (BG 10.2). Awon devatas.. brahmanda yi ni iseda Brahma. Ikan ninu awon orisa loje. Gege na Krsna sowipe, aham ādir hi devānām, " Emi ni ibere awon devatas, orisas." Teyin ba ko nipa Krsna bayi eyin na ma di daiva, mimo. Mimo.

Lati ko awon eyan lati di mimo nidi fun egbe imoye Krsna yi Ise wa niyen. Kini iwulo pe afe di mimo? Wanti salaaye ni ese iwe tokoja. Daivī sampad vimokṣāya (BG 16.5). teyin ba ya si mimo tesi ni awon iwa mimo, abhayaṁ sattva-saṁśuddhiḥ jñāna-yoga-vyavasthitiḥ... Ati salaaye tele. teyin ba ya si mimo... Kosi isoro kankan lati yasi mimo. Gege na egbudo se ikeko fun ipo na. gege bi gbogbo eyan le di adajo. gbogbo eyan na ledi Olori ilu America. Kosi isoro kankan. Sugbon egbudo ni awon amuye na. teyin ba ni amuye na... eledi di ounko teba fe. gege na teyin ba fe di daiva, mimo egbudo ni awon amuye na. Bawo lasele yasi mimo? Wanto salaye.

Teyin ba ni awon amuye lati yasi mimo, kini ijeere to wan'be? Daivī sampad vimokṣāya. Mokṣa. Igbala nitumo Mokṣa. teyin ba ni awon amuye to yasi mimo, eyin na leni igbala. Kini igbala yi? Igbala lati ibimo ati iku. Ijiya wa niyen. awon eyan laye isin o mo nkan ti ijiya yi je. Wan o mo. Kosi akeeko kankan. Kosi Sayensi kankan. Wan rowipe, ile aye kekere yi kasowipe odun aadota, odun ogota, tbai odun ogorin...toba poju taba ni iyawo to da, ile to da, oko to da, ton sare gan, pelu oti whiskey... Pipe aye fun niyen. Sugbon vimoksaya ko niyen. Vimoksa gidi ni gbala, aisi ibimi, iku, ojo-arugbo ati aisan. Vimoksa niyen. Sugbon aawon eyna yi o mo