YO/Prabhupada 0106 - E mu ero igbe ni soke ti bhakti lati pade Olorun ni taara: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0106 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Srimad-Bhagavatam]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Srimad-Bhagavatam]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0105 - Imo yi ti wa ni igboye nipase ijogun awon omo eleyin|0105|YO/Prabhupada 0107 - E ma tun gba ara aye yi miran|0107}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|GQ1WAbEwK4M|Take the Lift of Bhakti to Kṛṣṇa Directly<br />- Prabhupāda 0106}}
{{youtube_right|O5OtP3_rQ7I|Take the Lift of Bhakti to Kṛṣṇa Directly<br />- Prabhupāda 0106}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/721210BG.AHM_clip2.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/721210BG.AHM_clip2.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 26: Line 30:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Bee ni mama vartmānuvartante tumosi, gege bi lori oke ti, bi opolopo awon ile-oni-jala se wa ni Amerika. Ile-oni-jala ogorun le marun. Mo ro pe iyen lo se titun julo. Ka sowipe e ni lati lo si ori oke ijala t'oga julo. Atègun ilè wa nibe. Be ni gbogbo eniyan se ngbiyanju lati lo sibe. Sugbonenikan ti koja, so pe, ese mewa. Elomiran ti koja, boya ese àádọ́ta,. Elomiran ti gun ese ọgọ́rùn. Sugbon o ni lati pari, wipe, ẹgbẹrun meji ese. Be ni atègun ile na wa bakanna. . Mama vartmānuvartante. Nitori ilepa re ni lati lo si ori oke ijala ti o ga julo. Sugbon eni ti o ti koja ese mewa, o kere ju eni ti o ti koja àádọ́ta ese. ati eni ti o ti koja àádọ́ta ese tun kere ju eni ti o ti koja ọgọrun ese. Ni bakanna, awon ilana orisirisi lo wa. Sugbon gbogbo won ki se nkan kan naa. Won nfojusi ilepa kanna, karma, jñāna, yoga, bhakti, sugbon bhakti igbese to ga julo. Nitori nigbati e ba wa si ipo bhakti, igba na ni e le ni oye ohun ti Olorun je. Kii se nipase karma, jñāna, ati yoga. Iyen ko le see se. E ngbiyanju, e nlo si ona ti ifojusi na. sugbon Olorun so wipe, bhaktyā mām abhijānāti ([[Vanisource:BG 18.55|BG 18.55]]). Ko so wipe "nipase jnana, nipa karma, nipa yoga". Rara Iyen ko le ye yin. E le lo siwaju, awon igbese. Sugbon ti e ba fe mo Olorun, e f'okan si bhakti. Bhaktyā mām abhijānāti yāvān yaś cāsmi tattvataḥ ([[Vanisource:BG 18.55|BG 18.55]]). Ilana na ni yi. Nitorina mama vartmānuvartante tumosi "Gbogbo eniyan ngbiyanju lati si odo Mi, gege bi agbara won, agbara, sugbon eni ti o ba fe ni oye Mi ni gangan, ilana to rorun..." Bi itègun se wa nibe, sugbon ko si ni orilẹ-ede yi, ni awon orilẹ-ede, Amerika ati Europe, legbe legbe ni êrô ìgbé ni sókè. Be nipo ti o fi maa lo ni igbese kokan si ori ijala to gaju, e fi êrô ìgbé ni sókè yi se ranwo. Lesekese lo ma d'oke, laarin iseju kan. Ti e ba si mu êrô ìgbé ni sókè ti bhakti, lesekese na ni e ma pade Olorun ni taara. Nipo ti e ma fi lo ni igbese kokan. Kilode ti e o ni mu? Nitorina Olorun so wipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja: ([[Vanisource:BG 18.66|BG 18.66]]) Ki o kan jowo ara re fun Mi. Owo re ti pari." Kilode ti e ma se laala pupo pupo, nipa igbese kookan igbese kookan?
Bee ni mama vartmānuvartante tumosi, gege bi lori oke ti, bi opolopo awon ile-oni-jala se wa ni Amerika. Ile-oni-jala ogorun le marun. Mo ro pe iyen lo se titun julo. Ka sowipe e ni lati lo si ori oke ijala t'oga julo. Atègun ilè wa nibe. Be ni gbogbo eniyan se ngbiyanju lati lo sibe. Sugbonenikan ti koja, so pe, ese mewa. Elomiran ti koja, boya ese àádọ́ta,. Elomiran ti gun ese ọgọ́rùn. Sugbon o ni lati pari, wipe, ẹgbẹrun meji ese. Be ni atègun ile na wa bakanna. . Mama vartmānuvartante. Nitori ilepa re ni lati lo si ori oke ijala ti o ga julo. Sugbon eni ti o ti koja ese mewa, o kere ju eni ti o ti koja àádọ́ta ese. ati eni ti o ti koja àádọ́ta ese tun kere ju eni ti o ti koja ọgọrun ese. Ni bakanna, awon ilana orisirisi lo wa. Sugbon gbogbo won ki se nkan kan naa. Won nfojusi ilepa kanna, karma, jñāna, yoga, bhakti, sugbon bhakti igbese to ga julo. Nitori nigbati e ba wa si ipo bhakti, igba na ni e le ni oye ohun ti Olorun je. Kii se nipase karma, jñāna, ati yoga. Iyen ko le see se. E ngbiyanju, e nlo si ona ti ifojusi na. sugbon Olorun so wipe, bhaktyā mām abhijānāti ([[Vanisource:BG 18.55 (1972)|BG 18.55]]). Ko so wipe "nipase jnana, nipa karma, nipa yoga". Rara Iyen ko le ye yin. E le lo siwaju, awon igbese. Sugbon ti e ba fe mo Olorun, e f'okan si bhakti. Bhaktyā mām abhijānāti yāvān yaś cāsmi tattvataḥ ([[Vanisource:BG 18.55 (1972)|BG 18.55]]). Ilana na ni yi. Nitorina mama vartmānuvartante tumosi "Gbogbo eniyan ngbiyanju lati si odo Mi, gege bi agbara won, agbara, sugbon eni ti o ba fe ni oye Mi ni gangan, ilana to rorun..." Bi itègun se wa nibe, sugbon ko si ni orilẹ-ede yi, ni awon orilẹ-ede, Amerika ati Europe, legbe legbe ni êrô ìgbé ni sókè. Be nipo ti o fi maa lo ni igbese kokan si ori ijala to gaju, e fi êrô ìgbé ni sókè yi se ranwo. Lesekese lo ma d'oke, laarin iseju kan. Ti e ba si mu êrô ìgbé ni sókè ti bhakti, lesekese na ni e ma pade Olorun ni taara. Nipo ti e ma fi lo ni igbese kokan. Kilode ti e o ni mu? Nitorina Olorun so wipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja: ([[Vanisource:BG 18.66 (1972)|BG 18.66]]) Ki o kan jowo ara re fun Mi. Owo re ti pari." Kilode ti e ma se laala pupo pupo, nipa igbese kookan igbese kookan?
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 18:57, 14 October 2018



Lecture on BG 18.67 -- Ahmedabad, December 10, 1972

Bee ni mama vartmānuvartante tumosi, gege bi lori oke ti, bi opolopo awon ile-oni-jala se wa ni Amerika. Ile-oni-jala ogorun le marun. Mo ro pe iyen lo se titun julo. Ka sowipe e ni lati lo si ori oke ijala t'oga julo. Atègun ilè wa nibe. Be ni gbogbo eniyan se ngbiyanju lati lo sibe. Sugbonenikan ti koja, so pe, ese mewa. Elomiran ti koja, boya ese àádọ́ta,. Elomiran ti gun ese ọgọ́rùn. Sugbon o ni lati pari, wipe, ẹgbẹrun meji ese. Be ni atègun ile na wa bakanna. . Mama vartmānuvartante. Nitori ilepa re ni lati lo si ori oke ijala ti o ga julo. Sugbon eni ti o ti koja ese mewa, o kere ju eni ti o ti koja àádọ́ta ese. ati eni ti o ti koja àádọ́ta ese tun kere ju eni ti o ti koja ọgọrun ese. Ni bakanna, awon ilana orisirisi lo wa. Sugbon gbogbo won ki se nkan kan naa. Won nfojusi ilepa kanna, karma, jñāna, yoga, bhakti, sugbon bhakti igbese to ga julo. Nitori nigbati e ba wa si ipo bhakti, igba na ni e le ni oye ohun ti Olorun je. Kii se nipase karma, jñāna, ati yoga. Iyen ko le see se. E ngbiyanju, e nlo si ona ti ifojusi na. sugbon Olorun so wipe, bhaktyā mām abhijānāti (BG 18.55). Ko so wipe "nipase jnana, nipa karma, nipa yoga". Rara Iyen ko le ye yin. E le lo siwaju, awon igbese. Sugbon ti e ba fe mo Olorun, e f'okan si bhakti. Bhaktyā mām abhijānāti yāvān yaś cāsmi tattvataḥ (BG 18.55). Ilana na ni yi. Nitorina mama vartmānuvartante tumosi "Gbogbo eniyan ngbiyanju lati si odo Mi, gege bi agbara won, agbara, sugbon eni ti o ba fe ni oye Mi ni gangan, ilana to rorun..." Bi itègun se wa nibe, sugbon ko si ni orilẹ-ede yi, ni awon orilẹ-ede, Amerika ati Europe, legbe legbe ni êrô ìgbé ni sókè. Be nipo ti o fi maa lo ni igbese kokan si ori ijala to gaju, e fi êrô ìgbé ni sókè yi se ranwo. Lesekese lo ma d'oke, laarin iseju kan. Ti e ba si mu êrô ìgbé ni sókè ti bhakti, lesekese na ni e ma pade Olorun ni taara. Nipo ti e ma fi lo ni igbese kokan. Kilode ti e o ni mu? Nitorina Olorun so wipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja: (BG 18.66) Ki o kan jowo ara re fun Mi. Owo re ti pari." Kilode ti e ma se laala pupo pupo, nipa igbese kookan igbese kookan?