YO/Prabhupada 0169 - Kilo le lati foju ri Krishna: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0169 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1976 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in France]]
[[Category:YO-Quotes - in France]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0168 - Asa ton kowa basele resile|0168|YO/Prabhupada 0170 - Agbudo tele awon Gosvamis|0170}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->

<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 17:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|L4e-8r6o20g|Where is the Difficulty to See Kṛṣṇa? - Prabhupāda 0169}}
{{youtube_right|r_Re_QhBJcQ|Where is the Difficulty to See Kṛṣṇa? - Prabhupāda 0169}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/760804BG.NMR_clip4.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/760804BG.NMR_clip4.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 28: Line 31:
Yogeśvara: O sowipe nisin awa o ti ni ilosiwaju tole jeka ri Krsna gege bi eda to gaju, bawo lasefe gbokan le?  

Prabhupada: Seyin o le ri Krsna ninu ile-ajosin? (Erin) Nkan nkan lasan lawan s'adura si? Egbudo ri Krsna gege bi Krsna se so. Ni asiko tawayi .. gege bi Krsna se so raso 'ham apsu kaunteya ([[Vanisource:BG 7.8|BG 7.8]]). Krsna sowipe " Emi ni itọwo ninu omi." Teyin ba le ri Krsna bi itowo ninu omi. Gege bayi ele ni ilosiwaju. Krsna sowipe... " Emi ni itowo ninu omi." Teyin ba m'omi, kilode teyin o le ri Krsna. "Oh Krsna ni itwo yi." Raso 'ham apsu kaunteya prabhāsmi śaśi-sūryayoḥ. Teba ri orun ton ran, tabi Osupa. Ele ranti wipe Krsna sowipe " Emi ni ina Orun at'Osupa." Gege na ni owurọ teba ri Orun ton ran, ele ri Krsna ninu e.  
Prabhupāda: Seyin o le ri Krsna ninu ile-ajosin? (Erin) Nkan nkan lasan lawan s'adura si? Egbudo ri Krsna gege bi Krsna se so. Ni asiko tawayi .. gege bi Krsna se so raso 'ham apsu kaunteya ([[Vanisource:BG 7.8 (1972)|BG 7.8]]). Krsna sowipe " Emi ni itọwo ninu omi." Teyin ba le ri Krsna bi itowo ninu omi. Gege bayi ele ni ilosiwaju. Krsna sowipe... " Emi ni itowo ninu omi." Teyin ba m'omi, kilode teyin o le ri Krsna. "Oh Krsna ni itwo yi." Raso 'ham apsu kaunteya prabhāsmi śaśi-sūryayoḥ. Teba ri orun ton ran, tabi Osupa. Ele ranti wipe Krsna sowipe " Emi ni ina Orun at'Osupa." Gege na ni owurọ teba ri Orun ton ran, ele ri Krsna ninu e.  

Lesekese teba ri ina Osupa lale, eti ri Krsna niyen. Praṇavaḥ sarva-vedeṣu. Teba korin awon mantra lati Veda: om tad viṣṇu para, omkara yi nkankan na ni pelu Kṛṣṇa. "Paurusam visnu". ounkooun teyan ba se toju nkan afoju wo lasan, Krsna na niyen. Gege na egbudo ri Krsna bayi. Die die ema ri wipe Krsna a fi ara re han siyin. Kosi iyato laarin pe amo pe Krsna ni itowo omi ati pe eri Krsna s'oju, Kosiyato. gege besewa lema ri Krsna. die die eyin na ma ri soju. teba fe ri rasa lila Krsna lesekese, kolese se. Lesekese teba riwipe orun mu, egbudo mowipe ina wa n'idi re. Lesekese teba riwipe ẹfin wa, egbudo mo wipe ina wa, toba tiejepe eyin o le ri ina na. Sugbon oye wa pe, t'efin ba wa, ina gbudo wa labe re. Gege bayi loye ke ni imo nipa Krsna. Wanti salaaye ninu apa meje iwe mimo. Ele sewaadi.  

Line 36: Line 39:
:praṇavaḥ sarva-vedeṣu  
:praṇavaḥ sarva-vedeṣu  
:(śabdaḥ khe pauruṣaṁ nṛṣu)  
:(śabdaḥ khe pauruṣaṁ nṛṣu)  
:([[Vanisource:BG 7.8|BG 7.8]]).  
:([[Vanisource:BG 7.8 (1972)|BG 7.8]]).  

jayatrtha: Meje mejo: Arjuna, omo Kunti, emi ni itowo omi, ati ina lati orun at'osupa, oro tonpe ni " oṁ" ninu awon mantra Veda; emi ni ohun ninu ofurufu at'agbara to wa ninu Okurin.  
Jayatrtha: Meje mejo: Arjuna, omo Kunti, emi ni itowo omi, ati ina lati orun at'osupa, oro tonpe ni " oṁ" ninu awon mantra Veda; emi ni ohun ninu ofurufu at'agbara to wa ninu Okurin.  

Prabhupāda: Gege bayi ele ri Krsna. Kini isoro to wan'be? Talo se ibeere yi? Kini isoro to wa lati ri Krsna? Se isoro kankan wa n'be? Eri Krsna. Man-manā bhava mad-bhakto, Kṛṣṇa sowipe: " E ronu nipa mi nigba gbogbo." gege na,lesekese teba m'omi oyeke ranti pe " Ah Krsna wa nin u omi yi; Man-manā bhava mad-bhakto. Kini isoro to wa n'be? Kosi isoro kankan. Gbogbo nkan lowa n'be. uh? Kilo le nibe?  

Line 44: Line 47:
Abhinanda: Soyeka gbiyanju lati ranti pe Olorun ni Krsna je?  

Prabhupada: Kilode tose ronu nipa re na? (Gbogbo eyan rerin) (Ede Bengali) Odabi enito ka gbogbo Rāmāyaṇa tan, ton beere tani baba Sītā-devī? (Erin) Tani baba Sītā-devī? ( Erin to pariwo) Bi ibeere re si rin niyen. (Erin posi)  
Prabhupāda: Kilode tose ronu nipa re na? (Gbogbo eyan rerin) (Ede Bengali) Odabi enito ka gbogbo Rāmāyaṇa tan, ton beere tani baba Sītā-devī? (Erin) Tani baba Sītā-devī? ( Erin to pariwo) Bi ibeere re si rin niyen. (Erin posi)  

Abhinanda: Nitoripe l'odun to koja ni ilu Mayapura, Srila Prabhupada, esofun wa wipe kama gbagbe pe Olorun ni Krsna je. ọpọlọpọ igba le sofun wa.  

Prabhupada: Beeni, kilode to sen gbagbe? ( Awon elesin rerin) Ki leleyi? Elesin: Ti ti elesin ba kuro ninu esin ati ise ifarasi oluwa,  
Prabhupāda: Beeni, kilode to sen gbagbe? ( Awon elesin rerin) Ki leleyi?
 
Elesin: Ti ti elesin ba kuro ninu esin ati ise ifarasi oluwa,  

(Charanambuja sofun Jayantakrit: Oye ko se isotunmo si gbogbo ejo yi.)  

Latest revision as of 19:08, 14 October 2018

Lecture on BG 4.24 -- August 4, 1976, New Mayapur (French farm)

Yogeśvara: O sowipe nisin awa o ti ni ilosiwaju tole jeka ri Krsna gege bi eda to gaju, bawo lasefe gbokan le?

Prabhupāda: Seyin o le ri Krsna ninu ile-ajosin? (Erin) Nkan nkan lasan lawan s'adura si? Egbudo ri Krsna gege bi Krsna se so. Ni asiko tawayi .. gege bi Krsna se so raso 'ham apsu kaunteya (BG 7.8). Krsna sowipe " Emi ni itọwo ninu omi." Teyin ba le ri Krsna bi itowo ninu omi. Gege bayi ele ni ilosiwaju. Krsna sowipe... " Emi ni itowo ninu omi." Teyin ba m'omi, kilode teyin o le ri Krsna. "Oh Krsna ni itwo yi." Raso 'ham apsu kaunteya prabhāsmi śaśi-sūryayoḥ. Teba ri orun ton ran, tabi Osupa. Ele ranti wipe Krsna sowipe " Emi ni ina Orun at'Osupa." Gege na ni owurọ teba ri Orun ton ran, ele ri Krsna ninu e.

Lesekese teba ri ina Osupa lale, eti ri Krsna niyen. Praṇavaḥ sarva-vedeṣu. Teba korin awon mantra lati Veda: om tad viṣṇu para, omkara yi nkankan na ni pelu Kṛṣṇa. "Paurusam visnu". ounkooun teyan ba se toju nkan afoju wo lasan, Krsna na niyen. Gege na egbudo ri Krsna bayi. Die die ema ri wipe Krsna a fi ara re han siyin. Kosi iyato laarin pe amo pe Krsna ni itowo omi ati pe eri Krsna s'oju, Kosiyato. gege besewa lema ri Krsna. die die eyin na ma ri soju. teba fe ri rasa lila Krsna lesekese, kolese se. Lesekese teba riwipe orun mu, egbudo mowipe ina wa n'idi re. Lesekese teba riwipe ẹfin wa, egbudo mo wipe ina wa, toba tiejepe eyin o le ri ina na. Sugbon oye wa pe, t'efin ba wa, ina gbudo wa labe re. Gege bayi loye ke ni imo nipa Krsna. Wanti salaaye ninu apa meje iwe mimo. Ele sewaadi.

raso 'ham apsu kaunteya
prabhāsmi śaśi-sūryayoḥ
praṇavaḥ sarva-vedeṣu
(śabdaḥ khe pauruṣaṁ nṛṣu)
(BG 7.8).

Jayatrtha: Meje mejo: Arjuna, omo Kunti, emi ni itowo omi, ati ina lati orun at'osupa, oro tonpe ni " oṁ" ninu awon mantra Veda; emi ni ohun ninu ofurufu at'agbara to wa ninu Okurin.

Prabhupāda: Gege bayi ele ri Krsna. Kini isoro to wan'be? Talo se ibeere yi? Kini isoro to wa lati ri Krsna? Se isoro kankan wa n'be? Eri Krsna. Man-manā bhava mad-bhakto, Kṛṣṇa sowipe: " E ronu nipa mi nigba gbogbo." gege na,lesekese teba m'omi oyeke ranti pe " Ah Krsna wa nin u omi yi; Man-manā bhava mad-bhakto. Kini isoro to wa n'be? Kosi isoro kankan. Gbogbo nkan lowa n'be. uh? Kilo le nibe?

Abhinanda: Soyeka gbiyanju lati ranti pe Olorun ni Krsna je?

Prabhupāda: Kilode tose ronu nipa re na? (Gbogbo eyan rerin) (Ede Bengali) Odabi enito ka gbogbo Rāmāyaṇa tan, ton beere tani baba Sītā-devī? (Erin) Tani baba Sītā-devī? ( Erin to pariwo) Bi ibeere re si rin niyen. (Erin posi)

Abhinanda: Nitoripe l'odun to koja ni ilu Mayapura, Srila Prabhupada, esofun wa wipe kama gbagbe pe Olorun ni Krsna je. ọpọlọpọ igba le sofun wa.

Prabhupāda: Beeni, kilode to sen gbagbe? ( Awon elesin rerin) Ki leleyi?

Elesin: Ti ti elesin ba kuro ninu esin ati ise ifarasi oluwa,

(Charanambuja sofun Jayantakrit: Oye ko se isotunmo si gbogbo ejo yi.)

Elesin: Se elesin na ma lo si orun-apadi bon se salaaye ninu Bhāgavatam?

Prabhupāda: Kosi b'elesin se fe wo lule. (Awon eyan erin)

Elesin: Jaya! Jaya Śrīla Prabhupāda!