YO/Prabhupada 0348 - If for Fifty Years One Chants Simply Hare Krishna, He is Sure to Become Perfect: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0348 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1969 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in Germany]]
[[Category:YO-Quotes - in Germany]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0347 - First of all you Take your Birth where Krishna is now Present|0347|YO/Prabhupada 0349 - I Simply Believed what was Spoken by My Guru Maharaja|0349}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/690908BG.HAM_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/690908BG.HAM_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 28: Line 31:
Omo-okurin Geesi: So daju pe eyan le pada s;orun laye tawayi? Seyan le yipada?
Omo-okurin Geesi: So daju pe eyan le pada s;orun laye tawayi? Seyan le yipada?


Prabhupada: O daju ni aye ikeji toba mu ni pataki. Ko le rara. Kṛṣṇa-bhakti... Bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate: ([[Vanisource:BG 7.19|BG 7.19]]) lehin aimoye ibimo, teyan ba logobn, asi teriba funmi, nkan ti Krsna soniyen. Gege na tin ba logbon moma ri be " toba jewipe, lehin aimoye ibimo loma koja keyan to teriba fun Krsna, se ko daju ka se nisin lesekese?" Ogbon nkiyen. Oto oro niwipe eyan gbudo wa sori ipo yi, lehin ibimo to po gan. kilode teyin o sele gba lesekese? KIlode toye kin duro fun aimoye ibimo, oto oro niyen? Egbudo lo ogbon die. Kosidi fun aimoye ibimo wanyi, sugbon agbudo lo ogbon die. teba gba imoye Krsna yi ni pataki, gbogbo awon isoro teni ma tan. teyin o ba gba, oya ejeka rori wo nigbana. Ele jiyan besefe, awo to po gan wa> Eje ko dayin loju. E le ka awon iwe na. gbogbo idaaun wa ninu Bhagavad-gita. Ele gbiyanju lati ni oye re lati awon ijiyan yi. Owan sisi (Isinmi) Gege bi Arjuna, wan ko ni Bhagavad-gita, fun asiko melo? to ko wakati kan. Nitoripe eyan to logbon loje. Awon eyan agbaye yi wan ka Bhagavad-gita. Awon alakowe gan ka Bhagavad-gita. Wan fe mo nipa awon isotunmo orisirisi. Orisirisi isotunmo lowa. sugbon logbon gan, osi ni oye re ni wakati kan. Egbudo logbon na. gbogbo nkan aye yi ibantan. Ofin awon nkan ibatan. sayensi leleyi. Ofin Alamodaju Einstein? Ofin Ibatan? Gege na awon aye yi ibatan na loje. Eyan le ni imoye Krsna ni isenju kan, eyan o de le ni imoye Krsna yi afi lehin aimoye ibimo. Eto ibatan nani. teyin ba logbon to ye, ele gba lesekese. T'ogbon yin o bato, a si gba igba die. Eyin o le sowipe " A sese leyin odun bayi bayi," Eyin o le sobe. Nkan ibatan loje. Nkan ibatan ni gbogbo aye yi. Fun eda eyan ibi soun, ese kan pere; fun kokoro kekere, oda bi maili mewa fun. ibatan ni gbogbo nkan je. Bi ile aye yi se ri niyen. Kosejo pe " eyan le ni imoye Krsna leyin odun bayi bayi." rara. Kosi iru nkan bayi. Eyan le ma ni imoye Krsna lehin aimoye ibimo, osi leni imoye yi laarin iseju die. Sugbon ni apa kan, ale di pipe ninu imoye Krsna taba mu ni pataki. nipataki eyin omo-okurin. Awa si rowipe a le gbe fun aadota odun. Asiko to po gan niyen. Otie ti po ju. teyan ba korin Hare Krsna fun aadota odun, oma di pipe. Kosejo kankan. Toba korin mantra yi, Hare Krsna.Kosejo kankan.
Prabhupada: O daju ni aye ikeji toba mu ni pataki. Ko le rara. Kṛṣṇa-bhakti... Bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate: ([[Vanisource:BG 7.19 (1972)|BG 7.19]]) lehin aimoye ibimo, teyan ba logobn, asi teriba funmi, nkan ti Krsna soniyen. Gege na tin ba logbon moma ri be " toba jewipe, lehin aimoye ibimo loma koja keyan to teriba fun Krsna, se ko daju ka se nisin lesekese?" Ogbon nkiyen. Oto oro niwipe eyan gbudo wa sori ipo yi, lehin ibimo to po gan. kilode teyin o sele gba lesekese? KIlode toye kin duro fun aimoye ibimo, oto oro niyen? Egbudo lo ogbon die. Kosidi fun aimoye ibimo wanyi, sugbon agbudo lo ogbon die. teba gba imoye Krsna yi ni pataki, gbogbo awon isoro teni ma tan. teyin o ba gba, oya ejeka rori wo nigbana. Ele jiyan besefe, awo to po gan wa> Eje ko dayin loju. E le ka awon iwe na. gbogbo idaaun wa ninu Bhagavad-gita. Ele gbiyanju lati ni oye re lati awon ijiyan yi. Owan sisi (Isinmi) Gege bi Arjuna, wan ko ni Bhagavad-gita, fun asiko melo? to ko wakati kan. Nitoripe eyan to logbon loje. Awon eyan agbaye yi wan ka Bhagavad-gita. Awon alakowe gan ka Bhagavad-gita. Wan fe mo nipa awon isotunmo orisirisi. Orisirisi isotunmo lowa. sugbon logbon gan, osi ni oye re ni wakati kan. Egbudo logbon na. gbogbo nkan aye yi ibantan. Ofin awon nkan ibatan. sayensi leleyi. Ofin Alamodaju Einstein? Ofin Ibatan? Gege na awon aye yi ibatan na loje. Eyan le ni imoye Krsna ni isenju kan, eyan o de le ni imoye Krsna yi afi lehin aimoye ibimo. Eto ibatan nani. teyin ba logbon to ye, ele gba lesekese. T'ogbon yin o bato, a si gba igba die. Eyin o le sowipe " A sese leyin odun bayi bayi," Eyin o le sobe. Nkan ibatan loje. Nkan ibatan ni gbogbo aye yi. Fun eda eyan ibi soun, ese kan pere; fun kokoro kekere, oda bi maili mewa fun. ibatan ni gbogbo nkan je. Bi ile aye yi se ri niyen. Kosejo pe " eyan le ni imoye Krsna leyin odun bayi bayi." rara. Kosi iru nkan bayi. Eyan le ma ni imoye Krsna lehin aimoye ibimo, osi leni imoye yi laarin iseju die. Sugbon ni apa kan, ale di pipe ninu imoye Krsna taba mu ni pataki. nipataki eyin omo-okurin. Awa si rowipe a le gbe fun aadota odun. Asiko to po gan niyen. Otie ti po ju. teyan ba korin Hare Krsna fun aadota odun, oma di pipe. Kosejo kankan. Toba korin mantra yi, Hare Krsna.Kosejo kankan.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:52, 13 June 2018



Lecture on BG 7.14 -- Hamburg, September 8, 1969

Omo-okurin Geesi: So daju pe eyan le pada s;orun laye tawayi? Seyan le yipada?

Prabhupada: O daju ni aye ikeji toba mu ni pataki. Ko le rara. Kṛṣṇa-bhakti... Bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate: (BG 7.19) lehin aimoye ibimo, teyan ba logobn, asi teriba funmi, nkan ti Krsna soniyen. Gege na tin ba logbon moma ri be " toba jewipe, lehin aimoye ibimo loma koja keyan to teriba fun Krsna, se ko daju ka se nisin lesekese?" Ogbon nkiyen. Oto oro niwipe eyan gbudo wa sori ipo yi, lehin ibimo to po gan. kilode teyin o sele gba lesekese? KIlode toye kin duro fun aimoye ibimo, oto oro niyen? Egbudo lo ogbon die. Kosidi fun aimoye ibimo wanyi, sugbon agbudo lo ogbon die. teba gba imoye Krsna yi ni pataki, gbogbo awon isoro teni ma tan. teyin o ba gba, oya ejeka rori wo nigbana. Ele jiyan besefe, awo to po gan wa> Eje ko dayin loju. E le ka awon iwe na. gbogbo idaaun wa ninu Bhagavad-gita. Ele gbiyanju lati ni oye re lati awon ijiyan yi. Owan sisi (Isinmi) Gege bi Arjuna, wan ko ni Bhagavad-gita, fun asiko melo? to ko wakati kan. Nitoripe eyan to logbon loje. Awon eyan agbaye yi wan ka Bhagavad-gita. Awon alakowe gan ka Bhagavad-gita. Wan fe mo nipa awon isotunmo orisirisi. Orisirisi isotunmo lowa. sugbon logbon gan, osi ni oye re ni wakati kan. Egbudo logbon na. gbogbo nkan aye yi ibantan. Ofin awon nkan ibatan. sayensi leleyi. Ofin Alamodaju Einstein? Ofin Ibatan? Gege na awon aye yi ibatan na loje. Eyan le ni imoye Krsna ni isenju kan, eyan o de le ni imoye Krsna yi afi lehin aimoye ibimo. Eto ibatan nani. teyin ba logbon to ye, ele gba lesekese. T'ogbon yin o bato, a si gba igba die. Eyin o le sowipe " A sese leyin odun bayi bayi," Eyin o le sobe. Nkan ibatan loje. Nkan ibatan ni gbogbo aye yi. Fun eda eyan ibi soun, ese kan pere; fun kokoro kekere, oda bi maili mewa fun. ibatan ni gbogbo nkan je. Bi ile aye yi se ri niyen. Kosejo pe " eyan le ni imoye Krsna leyin odun bayi bayi." rara. Kosi iru nkan bayi. Eyan le ma ni imoye Krsna lehin aimoye ibimo, osi leni imoye yi laarin iseju die. Sugbon ni apa kan, ale di pipe ninu imoye Krsna taba mu ni pataki. nipataki eyin omo-okurin. Awa si rowipe a le gbe fun aadota odun. Asiko to po gan niyen. Otie ti po ju. teyan ba korin Hare Krsna fun aadota odun, oma di pipe. Kosejo kankan. Toba korin mantra yi, Hare Krsna.Kosejo kankan.