YO/Prabhupada 0396 - The Purport to Prayers of King Kulasekhara: Difference between revisions

 
No edit summary
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Purports to Songs]]
[[Category:YO-Quotes - Purports to Songs]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0395 - The Purport to Parama Koruna|0395|YO/Prabhupada 0397 - The Purport to Radha-Krsna Bol|0397}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 17: Line 20:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:C14_06_prayers_of_king_kulasekhara_purport.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/purports_and_songs/C14_06_prayers_of_king_kulasekhara_purport.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 18:07, 16 February 2019



Purport to Prayers of King Kulasekhara, CD 14

latinu ese-iwe Mukunda-mālā-stotra ni adura yi tiwa. Oba Kulaśekhara lo gba'dura yi. Oba pataki ati olufokansi pipe loje. Apeere to po gan si wa ninu awon iwe Veda olufokansi ni awon Oba nigbayen je, wan sin pe won ni rājarṣīs. Itumo Rājarṣīs niwipe botilejepe wan lori ijoba, sugbon eyan mimo lon sije. Kulaśekhara, Oba Kulaśekhara, sin gbadura si Krsna pe "Krsna mi, igi ese re le di okan mi mu. Nitoripe lasiko iku, awon nkan meta ton jeki ara wa sise, ikunmu, omi ida ounje, ati ategun, won ma papo, nitorina ohun eyan na ma fun, beena mio ni le daaruko mimo re lasiko iku mi." won ti salaaye pelu ifiwera, siwani funfun, ibikibi toba ri idodo to daa, asi losibe lati sere ninu omi, tiba ya asi sopo mo igi idodo na. beena Oba Kulaśekhara okan ati ara re loopo nisin t'ara re si le, pelu ese idodo t'Olorun, kosi ku lesekese. oye towa niwipe agbudo gba imoye Krsna yi s'okan, nisin ti ara wa at'okan si wa ni pipe. Ema duro de asiko tema ku. E gbiyanju ke sise imoye Krsna yi nisin t'ara yin at'okan yin si wa ni ipe, t'asiko iku na bade, ele ranti Krsna ati awon akoko idaraya ya re lesekese na ele pada si odo metalokan.