YO/Prabhupada 0454 - Very Risky Life If We Do Not Awaken Our Divya-Jnana: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0454 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1977 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0453 - Believe It! There Is No More Superior Authority Than Krishna|0453|YO/Prabhupada 0455 - Do Not Apply Your Poor Logic in The Matters Which is Inconceivable By You|0455}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/770401LE-BOM_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/770401LE-BOM_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 31: Line 34:
Alejo olugbe India: Prema-bhakti yāhā hoite, avidyā vināśa yāte, divya-jñāna hṛde prakāśito.
Alejo olugbe India: Prema-bhakti yāhā hoite, avidyā vināśa yāte, divya-jñāna hṛde prakāśito.


Prabhupāda: prema-bhakti ni nkan tose pataki. Prema-bhakti yāhā hoite, avidyā vināśa yāte, divya-jñāna. kini divya-jnana? Nkan tio kin se taaye yi nitumo Divya. Tapo divyam ([[Vanisource:SB 5.5.1|SB 5.5.1]]). Ipaarapo ohun aye yi at'emi nitumo Divyam. divya l'emi yi, mimo. Apareyam itas tu viddhi me prakṛtiṁ parā ([[Vanisource:BG 7.5|BG 7.5]]). para prakrti leleyi, eyi to gaju. ti awa ba ni idanimo to gaju... latini imoye ninu idanimo to gaju, oye ka ni imoye tio kin se taye yi. Divya-jñāna hṛde prakāśito. Beena ise guru leleyi, lati ji divya-jnana yi soke. Divya-jñāna. nitoripe guru le ji divya-jnaa yi soke, nitorina lasen s'adura fun. Nkan toye kase leleyi. maya leleyi. divya-jnana yi o le dede jisoke. won wa ninu okunkun adivya-jnana, itumo Adivya-jñāna ni " Ara mi nimi," " Olugbe India nimi" " Olugbe America nimi" " Hindu nimi, " " Musluman nimi", adivya-jnana leleyi. Dehātma-buddhiḥ. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri ([[Vanisource:SB 10.84.13|SB 10.84.13]]). Ara mi ko nimi.
Prabhupāda: prema-bhakti ni nkan tose pataki. Prema-bhakti yāhā hoite, avidyā vināśa yāte, divya-jñāna. kini divya-jnana? Nkan tio kin se taaye yi nitumo Divya. Tapo divyam ([[Vanisource:SB 5.5.1|SB 5.5.1]]). Ipaarapo ohun aye yi at'emi nitumo Divyam. divya l'emi yi, mimo. Apareyam itas tu viddhi me prakṛtiṁ parā ([[Vanisource:BG 7.5 (1972)|BG 7.5]]). para prakrti leleyi, eyi to gaju. ti awa ba ni idanimo to gaju... latini imoye ninu idanimo to gaju, oye ka ni imoye tio kin se taye yi. Divya-jñāna hṛde prakāśito. Beena ise guru leleyi, lati ji divya-jnana yi soke. Divya-jñāna. nitoripe guru le ji divya-jnaa yi soke, nitorina lasen s'adura fun. Nkan toye kase leleyi. maya leleyi. divya-jnana yi o le dede jisoke. won wa ninu okunkun adivya-jnana, itumo Adivya-jñāna ni " Ara mi nimi," " Olugbe India nimi" " Olugbe America nimi" " Hindu nimi, " " Musluman nimi", adivya-jnana leleyi. Dehātma-buddhiḥ. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri ([[Vanisource:SB 10.84.13|SB 10.84.13]]). Ara mi ko nimi.


Beena ibeere divya-jnana yi wa taba ni oye wipe " Ara mi konimi. Oun to gaju nimi, emi nimi. Eleyi kere si. Beena kilode toye kin wa ninu imoye to kere yi?" Awa ogbod joko sibe... okunkun nitumo imoye kekere yi. Tamasi mā. Itosona awon Veda niwipe awa ogbodo duro sinu okunkun." Jyotir gamah: " Ewa sinu imoye to gaju." asi s'adura si guru nitoripe oun lon funwa ni imoye to gaju. konse imoye - lati jeun, lati sun, lati ni imo ako ati abo ati igbeja ara wa. Awon olori oniselu gbogbo won loni iru imoye bayi - lati jeun, lati sun, lati ni imo ako ati abo, lati gbeja ara eni. Guru o ni nkankan se pelu gbogbo eleyi. divya-jnana loje, imoye to gaju. Nkan tafe niyen. Ara eda eya yi wa lati ji dviya-jnana hrde prakasito yi soke. toba si wa ninu okunkun nipa divya-jnana, agbodo fun leeko, base jeun, base sun, base ni imo ako ati abo, lehin na ile aye re ma tan. Ipadanu gidi gan leleyi je. Mṛtyu-saṁsāra-vartmani. Aprāpya māṁ nivartante mṛtyu-saṁsāra-vartmani ([[Vanisource:BG 9.3|BG 9.3]]). Alebu nla loje t'awa o ba gbiyanju lati ji divya-jnana wa soke. Agbodo ranti eleyi. atun wole sinu ìrúmiìgbì omiìbilù-omi ibimo ati'ku, awa o mo ibi tan lo. Nkan pataki leleyi. divya-jnana yi imoye Krsna loje. Imoye lasan ko. oye ki gbogbo awon eyan gbiyanju lati ni imoye nipa divya-jnana yi. Daivīṁ prakṛtim āśritam. Nitorina eni toba femo nipa divya-jnana yi, won pe ni daivīṁ prakṛtim āśritam.lati daivi, ni oro Sanskrit ti wa.
Beena ibeere divya-jnana yi wa taba ni oye wipe " Ara mi konimi. Oun to gaju nimi, emi nimi. Eleyi kere si. Beena kilode toye kin wa ninu imoye to kere yi?" Awa ogbod joko sibe... okunkun nitumo imoye kekere yi. Tamasi mā. Itosona awon Veda niwipe awa ogbodo duro sinu okunkun." Jyotir gamah: " Ewa sinu imoye to gaju." asi s'adura si guru nitoripe oun lon funwa ni imoye to gaju. konse imoye - lati jeun, lati sun, lati ni imo ako ati abo ati igbeja ara wa. Awon olori oniselu gbogbo won loni iru imoye bayi - lati jeun, lati sun, lati ni imo ako ati abo, lati gbeja ara eni. Guru o ni nkankan se pelu gbogbo eleyi. divya-jnana loje, imoye to gaju. Nkan tafe niyen. Ara eda eya yi wa lati ji dviya-jnana hrde prakasito yi soke. toba si wa ninu okunkun nipa divya-jnana, agbodo fun leeko, base jeun, base sun, base ni imo ako ati abo, lehin na ile aye re ma tan. Ipadanu gidi gan leleyi je. Mṛtyu-saṁsāra-vartmani. Aprāpya māṁ nivartante mṛtyu-saṁsāra-vartmani ([[Vanisource:BG 9.3 (1972)|BG 9.3]]). Alebu nla loje t'awa o ba gbiyanju lati ji divya-jnana wa soke. Agbodo ranti eleyi. atun wole sinu ìrúmiìgbì omiìbilù-omi ibimo ati'ku, awa o mo ibi tan lo. Nkan pataki leleyi. divya-jnana yi imoye Krsna loje. Imoye lasan ko. oye ki gbogbo awon eyan gbiyanju lati ni imoye nipa divya-jnana yi. Daivīṁ prakṛtim āśritam. Nitorina eni toba femo nipa divya-jnana yi, won pe ni daivīṁ prakṛtim āśritam.lati daivi, ni oro Sanskrit ti wa.


Oro Sanskrit, lati daivi, daivya, õrõ àpéjúwe beena mahātmānas tu māṁ pārtha daivīṁ prakṛtim āśritāḥ ([[Vanisource:BG 9.13|BG 9.13]]). enikeni toba ti gba ilana divya-jnana yi, oun ni mahatma. Mahatma, o kin se fun awon eyan ton fe ko lati jeun, lati sun, lati ni imoako ati abo. isotunmo to wa ninu sastra ko niyen. Sa mahātmā su-durlabhaḥ.
Oro Sanskrit, lati daivi, daivya, õrõ àpéjúwe beena mahātmānas tu māṁ pārtha daivīṁ prakṛtim āśritāḥ ([[Vanisource:BG 9.13 (1972)|BG 9.13]]). enikeni toba ti gba ilana divya-jnana yi, oun ni mahatma. Mahatma, o kin se fun awon eyan ton fe ko lati jeun, lati sun, lati ni imoako ati abo. isotunmo to wa ninu sastra ko niyen. Sa mahātmā su-durlabhaḥ.


:bahūnāṁ janmanām ante
:bahūnāṁ janmanām ante
Line 41: Line 44:
:vāsudevaḥ sarvam iti
:vāsudevaḥ sarvam iti
:sa mahātmā...
:sa mahātmā...
:([[Vanisource:BG 7.19|BG 7.19]])
:([[Vanisource:BG 7.19 (1972)|BG 7.19]])


Eni to ba ni divya-jñāna, vāsudevaḥ sarvam iti sa mahātmā, mahatma niyen. sugbon iyen na soro lati ri. Bibeko, awon mahatma bayi won wa loju tit. ise won niyen. Beena egbodo ranti oro yi, divya-jñāna hṛde prakāśito. nitoripe oluko wa lon ji divya-jnana wa yi soke, nitorina lasen dupe si. Yasya prasādād bhagavat-prasādo yasya prasādān na gatiḥ kuto 'pi. Beena guru-puja yi se oataki. bi adura si awon irisi Olorun se wa pataki.. kon se adura lasan. Ona lati fi ji divya-jnana wa soke.
Eni to ba ni divya-jñāna, vāsudevaḥ sarvam iti sa mahātmā, mahatma niyen. sugbon iyen na soro lati ri. Bibeko, awon mahatma bayi won wa loju tit. ise won niyen. Beena egbodo ranti oro yi, divya-jñāna hṛde prakāśito. nitoripe oluko wa lon ji divya-jnana wa yi soke, nitorina lasen dupe si. Yasya prasādād bhagavat-prasādo yasya prasādān na gatiḥ kuto 'pi. Beena guru-puja yi se oataki. bi adura si awon irisi Olorun se wa pataki.. kon se adura lasan. Ona lati fi ji divya-jnana wa soke.

Latest revision as of 00:00, 14 June 2018



Lecture -- Bombay, April 1, 1977

Prabhupāda: Beena kini ese iwe na? Divya-jñāna hṛde prakāśito. Ase se ka tan. ( Awon olugbe India tunka) eyi to siwaju re.

Alejo olugbe India: Prema-bhakti yāhā hoite, avidyā vināśa yāte, divya-jñāna hṛde prakāśito.

Prabhupāda: prema-bhakti ni nkan tose pataki. Prema-bhakti yāhā hoite, avidyā vināśa yāte, divya-jñāna. kini divya-jnana? Nkan tio kin se taaye yi nitumo Divya. Tapo divyam (SB 5.5.1). Ipaarapo ohun aye yi at'emi nitumo Divyam. divya l'emi yi, mimo. Apareyam itas tu viddhi me prakṛtiṁ parā (BG 7.5). para prakrti leleyi, eyi to gaju. ti awa ba ni idanimo to gaju... latini imoye ninu idanimo to gaju, oye ka ni imoye tio kin se taye yi. Divya-jñāna hṛde prakāśito. Beena ise guru leleyi, lati ji divya-jnana yi soke. Divya-jñāna. nitoripe guru le ji divya-jnaa yi soke, nitorina lasen s'adura fun. Nkan toye kase leleyi. maya leleyi. divya-jnana yi o le dede jisoke. won wa ninu okunkun adivya-jnana, itumo Adivya-jñāna ni " Ara mi nimi," " Olugbe India nimi" " Olugbe America nimi" " Hindu nimi, " " Musluman nimi", adivya-jnana leleyi. Dehātma-buddhiḥ. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri (SB 10.84.13). Ara mi ko nimi.

Beena ibeere divya-jnana yi wa taba ni oye wipe " Ara mi konimi. Oun to gaju nimi, emi nimi. Eleyi kere si. Beena kilode toye kin wa ninu imoye to kere yi?" Awa ogbod joko sibe... okunkun nitumo imoye kekere yi. Tamasi mā. Itosona awon Veda niwipe awa ogbodo duro sinu okunkun." Jyotir gamah: " Ewa sinu imoye to gaju." asi s'adura si guru nitoripe oun lon funwa ni imoye to gaju. konse imoye - lati jeun, lati sun, lati ni imo ako ati abo ati igbeja ara wa. Awon olori oniselu gbogbo won loni iru imoye bayi - lati jeun, lati sun, lati ni imo ako ati abo, lati gbeja ara eni. Guru o ni nkankan se pelu gbogbo eleyi. divya-jnana loje, imoye to gaju. Nkan tafe niyen. Ara eda eya yi wa lati ji dviya-jnana hrde prakasito yi soke. toba si wa ninu okunkun nipa divya-jnana, agbodo fun leeko, base jeun, base sun, base ni imo ako ati abo, lehin na ile aye re ma tan. Ipadanu gidi gan leleyi je. Mṛtyu-saṁsāra-vartmani. Aprāpya māṁ nivartante mṛtyu-saṁsāra-vartmani (BG 9.3). Alebu nla loje t'awa o ba gbiyanju lati ji divya-jnana wa soke. Agbodo ranti eleyi. atun wole sinu ìrúmiìgbì omiìbilù-omi ibimo ati'ku, awa o mo ibi tan lo. Nkan pataki leleyi. divya-jnana yi imoye Krsna loje. Imoye lasan ko. oye ki gbogbo awon eyan gbiyanju lati ni imoye nipa divya-jnana yi. Daivīṁ prakṛtim āśritam. Nitorina eni toba femo nipa divya-jnana yi, won pe ni daivīṁ prakṛtim āśritam.lati daivi, ni oro Sanskrit ti wa.

Oro Sanskrit, lati daivi, daivya, õrõ àpéjúwe beena mahātmānas tu māṁ pārtha daivīṁ prakṛtim āśritāḥ (BG 9.13). enikeni toba ti gba ilana divya-jnana yi, oun ni mahatma. Mahatma, o kin se fun awon eyan ton fe ko lati jeun, lati sun, lati ni imoako ati abo. isotunmo to wa ninu sastra ko niyen. Sa mahātmā su-durlabhaḥ.

bahūnāṁ janmanām ante
jñānavān māṁ prapadyante
vāsudevaḥ sarvam iti
sa mahātmā...
(BG 7.19)

Eni to ba ni divya-jñāna, vāsudevaḥ sarvam iti sa mahātmā, mahatma niyen. sugbon iyen na soro lati ri. Bibeko, awon mahatma bayi won wa loju tit. ise won niyen. Beena egbodo ranti oro yi, divya-jñāna hṛde prakāśito. nitoripe oluko wa lon ji divya-jnana wa yi soke, nitorina lasen dupe si. Yasya prasādād bhagavat-prasādo yasya prasādān na gatiḥ kuto 'pi. Beena guru-puja yi se oataki. bi adura si awon irisi Olorun se wa pataki.. kon se adura lasan. Ona lati fi ji divya-jnana wa soke.

Ese pupo.

Ajo: Jaya Prabhupada.