YO/Prabhupada 0624 - The God is also Eternal and We are also Eternal: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0624 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Pittsburgh]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Pittsburgh]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0623 - The Soul is Transmigrating from One Body to Another|0623|YO/Prabhupada 0625 - Necessities of Life are being Supplied by The Supreme Eternal, God|0625}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:

<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/720908BG-PIT_clip02.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/720908BG-PIT_clip02.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 27: Line 30:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
Beena agbodo gba imoye yi lati awon olori. Krsna lon soro nibi. Oun l'olori. Awa ti gba Krsna: Eledumare. Imoye re wa ni pipe. O mo oun toti sele seyin, nisin ati l'ojowaju. Nitorina, oun lon ko Arjuna, "Arjuna mi, emi towa ninu ara eda yi ma wa tayeraye." Otooro niyen. gege bose yemi, Mowa teletele, mowa nisin, beena mosi mawa loojowaju. Awon asiko akoko meta towa leleyi, asiko toti koja, isin, ati ojo waju. Nibomi ati ka ninu Bhagavad-gita wipe, na jāyate na mriyate vā kadācit. Awon eda o le ni ibimo; kode le ku. Itumo Na jāyate niwipe kole ni ibimo. Na jāyate na mriyate, kode le ku. Nityaṁ śāśvato 'yam, na hanyate hanyamāne śarīre ([[Vanisource:BG 2.20|BG 2.20]]). O ma wa tayeraye, śāśvata. Na hanyate hanyamāne śarīre ([[Vanisource:BG 2.20|BG 2.20]]). Ti ara eda yi ba pari gan, emi wa o le ku. Awon Upanisads, Veda ti jeerisi: nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Oluwa wa tayeraye, awa na wa tayeraye. Nkankanna laje pelu Oluwa. Gege bi wura ati erunrun wura; wura ni awon mejeeji na. Botilejepe erunrun nimi, erunrun wura tabi emi, emi nimi. Beena awa ti ni imoye yi pe Olorun ati awa na, awon eda, awa tayeraye. Nityo nityānām, tayeraye nitumo nitya.
Beena agbodo gba imoye yi lati awon olori. Krsna lon soro nibi. Oun l'olori. Awa ti gba Krsna: Eledumare. Imoye re wa ni pipe. O mo oun toti sele seyin, nisin ati l'ojowaju. Nitorina, oun lon ko Arjuna, "Arjuna mi, emi towa ninu ara eda yi ma wa tayeraye." Otooro niyen. gege bose yemi, Mowa teletele, mowa nisin, beena mosi mawa loojowaju. Awon asiko akoko meta towa leleyi, asiko toti koja, isin, ati ojo waju. Nibomi ati ka ninu Bhagavad-gita wipe, na jāyate na mriyate vā kadācit. Awon eda o le ni ibimo; kode le ku. Itumo Na jāyate niwipe kole ni ibimo. Na jāyate na mriyate, kode le ku. Nityaṁ śāśvato 'yam, na hanyate hanyamāne śarīre ([[Vanisource:BG 2.20 (1972)|BG 2.20]]). O ma wa tayeraye, śāśvata. Na hanyate hanyamāne śarīre ([[Vanisource:BG 2.20 (1972)|BG 2.20]]). Ti ara eda yi ba pari gan, emi wa o le ku. Awon Upanisads, Veda ti jeerisi: nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Oluwa wa tayeraye, awa na wa tayeraye. Nkankanna laje pelu Oluwa. Gege bi wura ati erunrun wura; wura ni awon mejeeji na. Botilejepe erunrun nimi, erunrun wura tabi emi, emi nimi. Beena awa ti ni imoye yi pe Olorun ati awa na, awon eda, awa tayeraye. Nityo nityānām, tayeraye nitumo nitya.

Beena awon oro meji towa niyen. Ikan je eleyo, nitya, tayeraye, ikeji ju ikan lo, nityanam. Beena awa na ju ikan lo. Awon oonka tonju ikan lo won wa tayeraye. Awa o mo nkan t'agbara won eda laye yi je. Wanti juwe won bi asankhya. lai siro iye won nitumo Asaṅkhya. Aimoye. Kini iyato laarin awon ookan eleyo ati opolopo? Awon onka opolopo farale awon onka eleyo. Eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Onka eleyo yi lon fun onka opolop yi ni gbogbo nkan tofe, awon eda. Otooro niyen, ati yeewo pelu ogbon wa. NInu awon iye 8,400,000 eda orisirisi towa, awon eda eyan awa la kere ju. sugbon awo iyoku, won poju wa lo. Gege bi omi. Jalajā nava-lakṣāṇi. eda 900,000 lowa ninu omi. Sthāvarā lakṣa-viṁśati; ati 2,000,000 irisi orisirisi ninu ijoba awon ewe, igi at'eso. Jalajā nava-lakṣāṇi sthāvarā lakṣa-viṁśati, kṛmayo rudra-saṅkhyayaḥ. Ati awon kokoro, won to 1,100,000 eda orisirisi. Kṛmayo rudra-saṅkhyayaḥ pakṣīṇāṁ daśa-lakṣaṇam. ati awon eye, won pe 1,000,000 eda Awon eranko, paśavas triṁśa-lakṣāṇi, 3,000,000 orisirisi eranko pel'ese merin. catur-lakṣāṇi mānuṣaḥ, awon eda eyan won to 400,000. Ninu won, opolopo niwon o laju.

<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:18, 14 June 2018

Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

Beena agbodo gba imoye yi lati awon olori. Krsna lon soro nibi. Oun l'olori. Awa ti gba Krsna: Eledumare. Imoye re wa ni pipe. O mo oun toti sele seyin, nisin ati l'ojowaju. Nitorina, oun lon ko Arjuna, "Arjuna mi, emi towa ninu ara eda yi ma wa tayeraye." Otooro niyen. gege bose yemi, Mowa teletele, mowa nisin, beena mosi mawa loojowaju. Awon asiko akoko meta towa leleyi, asiko toti koja, isin, ati ojo waju. Nibomi ati ka ninu Bhagavad-gita wipe, na jāyate na mriyate vā kadācit. Awon eda o le ni ibimo; kode le ku. Itumo Na jāyate niwipe kole ni ibimo. Na jāyate na mriyate, kode le ku. Nityaṁ śāśvato 'yam, na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). O ma wa tayeraye, śāśvata. Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Ti ara eda yi ba pari gan, emi wa o le ku. Awon Upanisads, Veda ti jeerisi: nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Oluwa wa tayeraye, awa na wa tayeraye. Nkankanna laje pelu Oluwa. Gege bi wura ati erunrun wura; wura ni awon mejeeji na. Botilejepe erunrun nimi, erunrun wura tabi emi, emi nimi. Beena awa ti ni imoye yi pe Olorun ati awa na, awon eda, awa tayeraye. Nityo nityānām, tayeraye nitumo nitya.