YO/Prabhupada 0626 - If you want to Learn factually Things then You should Approach Acarya: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0626 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Pittsburgh]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Pittsburgh]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0625 - Necessities of Life are being Supplied by The Supreme Eternal, God|0625|YO/Prabhupada 0627 - Without Refreshness, One cannot Understand this Sublime Subject Matter|0627}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/720908BG-PIT_clip04.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/720908BG-PIT_clip04.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 27: Line 30:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
Beena eto igboran yi se pataki gan. Beena egbe imoye Krsna yi wa lati pin eto yi pe " E gboran lati awon olori, Krsna." Krsna ni Eledumare. Wonti gba ninu asiko tawayi ati asiko to koja. Lasiko to koja, awon eyan pataki bi Nārada, Vyāsa, Asita, Devala, awon alakowe giga, gbogbo won lon gba. Lasiko odun 1,500 seyin, awon acarya bi Śaṅkarācārya, Rāmānujācārya, Madhvācārya, Nimbārka... Awujo olugbe India, gbogbo wan lon sise lori oro awon acarya wanyi. wonde ti funwa ni itosona ninu Bhagavad-gita: ācāryopāsanam ([[Vanisource:BG 13.8|BG 13.8]]). teyin bafe keeko nipa awon nkan, eyin gbodo summon awon acarya. Ācāryavān puruṣo veda, "Eyan gbodo gba awon acarya, o mo awon nkan bonseje." Ācāryavān puruṣo veda. Beena awa ti gba imoye lati awon acarya. Krsna si sofun Arjuna, Arjuna soro si Vyasadeva. Arjuna kolo ba Vyasadeva soro, sugbon Vyasadeva lo gbo, Krsna lon soro, osi kosile ninu iwe re Mahābhārata. Bhagavad-gita yi wa ninu Mahābhārata. Beena awa ti gba awon olori bi Vyasa. lati Vyāsa, Madhvācārya; lati Madhvācārya, awon akeeko ton pejo, titi de Madhavendra Puri. Lehin Mādhavendra Purī si Īśvara Purī; lati Īśvara Purī si Oluwa Caitanyadeva; lati Lord Caitanyadeva si awon Gosvāmī mefa; lati awon Gosvāmī mefa si Kṛṣṇadāsa Kavirāja; lati Krsnadada Kaviraja si Śrīnivāsa Ācārya; lati Viśvanātha Cakravartī; si Jagannātha dāsa Bābājī; lehin naGaura Kiśora dāsa Bābājī; Bhaktivinoda Ṭhākura; ati oluko mimo mi. Nkankana, lawa na sin sewaasu fun. Imoye Krsna niyen. Kosin nkankan tuntun. Lati enito koko soro na, Krsna loti wa, lati ipejo awon akeeko. Beena awa sin ka ninu Bhagavad-gita. Konsepe moti da iwe mi sile ati pe mon sewaasu na. Rara. Mon sewaasu Bhagavad-gita. Bhagavad-gita kanna ton so ni alakoko bi odun aadota-oke lona ogoji seyin si orisa- orun wonde ti tunso bi odun egberun maarun seyin si Arjuna. Nkankana lon wa lati awon akeeko wanyi, nkankana lawa sin funyin nisin. Kosi ipaaro kankan.
Beena eto igboran yi se pataki gan. Beena egbe imoye Krsna yi wa lati pin eto yi pe " E gboran lati awon olori, Krsna." Krsna ni Eledumare. Wonti gba ninu asiko tawayi ati asiko to koja. Lasiko to koja, awon eyan pataki bi Nārada, Vyāsa, Asita, Devala, awon alakowe giga, gbogbo won lon gba. Lasiko odun 1,500 seyin, awon acarya bi Śaṅkarācārya, Rāmānujācārya, Madhvācārya, Nimbārka... Awujo olugbe India, gbogbo wan lon sise lori oro awon acarya wanyi. wonde ti funwa ni itosona ninu Bhagavad-gita: ācāryopāsanam ([[Vanisource:BG 13.8-12 (1972)|BG 13.8]]). teyin bafe keeko nipa awon nkan, eyin gbodo summon awon acarya. Ācāryavān puruṣo veda, "Eyan gbodo gba awon acarya, o mo awon nkan bonseje." Ācāryavān puruṣo veda. Beena awa ti gba imoye lati awon acarya. Krsna si sofun Arjuna, Arjuna soro si Vyasadeva. Arjuna kolo ba Vyasadeva soro, sugbon Vyasadeva lo gbo, Krsna lon soro, osi kosile ninu iwe re Mahābhārata. Bhagavad-gita yi wa ninu Mahābhārata. Beena awa ti gba awon olori bi Vyasa. lati Vyāsa, Madhvācārya; lati Madhvācārya, awon akeeko ton pejo, titi de Madhavendra Puri. Lehin Mādhavendra Purī si Īśvara Purī; lati Īśvara Purī si Oluwa Caitanyadeva; lati Lord Caitanyadeva si awon Gosvāmī mefa; lati awon Gosvāmī mefa si Kṛṣṇadāsa Kavirāja; lati Krsnadada Kaviraja si Śrīnivāsa Ācārya; lati Viśvanātha Cakravartī; si Jagannātha dāsa Bābājī; lehin naGaura Kiśora dāsa Bābājī; Bhaktivinoda Ṭhākura; ati oluko mimo mi. Nkankana, lawa na sin sewaasu fun. Imoye Krsna niyen. Kosin nkankan tuntun. Lati enito koko soro na, Krsna loti wa, lati ipejo awon akeeko. Beena awa sin ka ninu Bhagavad-gita. Konsepe moti da iwe mi sile ati pe mon sewaasu na. Rara. Mon sewaasu Bhagavad-gita. Bhagavad-gita kanna ton so ni alakoko bi odun aadota-oke lona ogoji seyin si orisa- orun wonde ti tunso bi odun egberun maarun seyin si Arjuna. Nkankana lon wa lati awon akeeko wanyi, nkankana lawa sin funyin nisin. Kosi ipaaro kankan.


Beena awon olori ti sowipe,
Beena awon olori ti sowipe,
Line 35: Line 38:
:tathā dehāntara-prāptir
:tathā dehāntara-prāptir
:dhīras tatra na muhyati
:dhīras tatra na muhyati
:([[Vanisource:BG 2.13|BG 2.13]])
:([[Vanisource:BG 2.13 (1972)|BG 2.13]])


Beena awa sin bere lowo awon eyan kon gba imoye yi lati awon olori wanyi, kesi gbiynaju lati ni oye re pel'ogbon yin. Konsepe eyin o ni rori mo, ke kon gba lai yeewo Rara. Eda eyan niwa, asi logbon. Eranko ko niwa pe won ma ti wa lati ni oye nkan. Rara. Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā ([[Vanisource:BG 4.34|BG 4.34]]). Ninu Bhagavad-gita eyin ma ri nibe. E gbiyanju lati ni oye re, tad viddhi. Egbiyanu lati ni oye re nitumo Viddhi. Praṇipāta. iteriba nitumo Praṇipātena, pelu ija ko. Akeeko gbodo gboran si Oluko mimo re lenu. Bibeko, o ma daloju. Ogbodo gboran si lenu.
Beena awa sin bere lowo awon eyan kon gba imoye yi lati awon olori wanyi, kesi gbiynaju lati ni oye re pel'ogbon yin. Konsepe eyin o ni rori mo, ke kon gba lai yeewo Rara. Eda eyan niwa, asi logbon. Eranko ko niwa pe won ma ti wa lati ni oye nkan. Rara. Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā ([[Vanisource:BG 4.34 (1972)|BG 4.34]]). Ninu Bhagavad-gita eyin ma ri nibe. E gbiyanju lati ni oye re, tad viddhi. Egbiyanu lati ni oye re nitumo Viddhi. Praṇipāta. iteriba nitumo Praṇipātena, pelu ija ko. Akeeko gbodo gboran si Oluko mimo re lenu. Bibeko, o ma daloju. Ogbodo gboran si lenu.


:tasmād guruṁ prapadyeta
:tasmād guruṁ prapadyeta

Latest revision as of 00:18, 14 June 2018



Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

Beena eto igboran yi se pataki gan. Beena egbe imoye Krsna yi wa lati pin eto yi pe " E gboran lati awon olori, Krsna." Krsna ni Eledumare. Wonti gba ninu asiko tawayi ati asiko to koja. Lasiko to koja, awon eyan pataki bi Nārada, Vyāsa, Asita, Devala, awon alakowe giga, gbogbo won lon gba. Lasiko odun 1,500 seyin, awon acarya bi Śaṅkarācārya, Rāmānujācārya, Madhvācārya, Nimbārka... Awujo olugbe India, gbogbo wan lon sise lori oro awon acarya wanyi. wonde ti funwa ni itosona ninu Bhagavad-gita: ācāryopāsanam (BG 13.8). teyin bafe keeko nipa awon nkan, eyin gbodo summon awon acarya. Ācāryavān puruṣo veda, "Eyan gbodo gba awon acarya, o mo awon nkan bonseje." Ācāryavān puruṣo veda. Beena awa ti gba imoye lati awon acarya. Krsna si sofun Arjuna, Arjuna soro si Vyasadeva. Arjuna kolo ba Vyasadeva soro, sugbon Vyasadeva lo gbo, Krsna lon soro, osi kosile ninu iwe re Mahābhārata. Bhagavad-gita yi wa ninu Mahābhārata. Beena awa ti gba awon olori bi Vyasa. lati Vyāsa, Madhvācārya; lati Madhvācārya, awon akeeko ton pejo, titi de Madhavendra Puri. Lehin Mādhavendra Purī si Īśvara Purī; lati Īśvara Purī si Oluwa Caitanyadeva; lati Lord Caitanyadeva si awon Gosvāmī mefa; lati awon Gosvāmī mefa si Kṛṣṇadāsa Kavirāja; lati Krsnadada Kaviraja si Śrīnivāsa Ācārya; lati Viśvanātha Cakravartī; si Jagannātha dāsa Bābājī; lehin naGaura Kiśora dāsa Bābājī; Bhaktivinoda Ṭhākura; ati oluko mimo mi. Nkankana, lawa na sin sewaasu fun. Imoye Krsna niyen. Kosin nkankan tuntun. Lati enito koko soro na, Krsna loti wa, lati ipejo awon akeeko. Beena awa sin ka ninu Bhagavad-gita. Konsepe moti da iwe mi sile ati pe mon sewaasu na. Rara. Mon sewaasu Bhagavad-gita. Bhagavad-gita kanna ton so ni alakoko bi odun aadota-oke lona ogoji seyin si orisa- orun wonde ti tunso bi odun egberun maarun seyin si Arjuna. Nkankana lon wa lati awon akeeko wanyi, nkankana lawa sin funyin nisin. Kosi ipaaro kankan.

Beena awon olori ti sowipe,

dehino 'smin yathā dehe
kaumāraṁ yauvanaṁ jarā
tathā dehāntara-prāptir
dhīras tatra na muhyati
(BG 2.13)

Beena awa sin bere lowo awon eyan kon gba imoye yi lati awon olori wanyi, kesi gbiynaju lati ni oye re pel'ogbon yin. Konsepe eyin o ni rori mo, ke kon gba lai yeewo Rara. Eda eyan niwa, asi logbon. Eranko ko niwa pe won ma ti wa lati ni oye nkan. Rara. Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā (BG 4.34). Ninu Bhagavad-gita eyin ma ri nibe. E gbiyanju lati ni oye re, tad viddhi. Egbiyanu lati ni oye re nitumo Viddhi. Praṇipāta. iteriba nitumo Praṇipātena, pelu ija ko. Akeeko gbodo gboran si Oluko mimo re lenu. Bibeko, o ma daloju. Ogbodo gboran si lenu.

tasmād guruṁ prapadyeta
jijñāsuḥ śreya uttamam
śābde pare ca niṣṇātaṁ
brahmaṇy upaśamāśrayam
(SB 11.3.21)

Ilana to wa niyen, Veda. Teyin bafe mo awon nkan tokoja ogbon yin lo, to koja irori ogbon yin, lehin na egbodo summo oluko mimo.