YO/Prabhupada 0628 - We don't Accept such things as 'Perhaps,' 'Maybe.' No. We Accept what is Fact: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0628 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Pittsburgh]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Pittsburgh]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0627 - Without Refreshness, One cannot Understand this Sublime Subject Matter|0627|YO/Prabhupada 0629 - We are Different Sons of God in Different Dresses|0629}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:

<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/720908BG-PIT_clip06.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/720908BG-PIT_clip06.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 33: Line 36:
:tathā dehāntara-prāptir
:tathā dehāntara-prāptir
:dhīras tatra na muhyati
:dhīras tatra na muhyati
:([[Vanisource:BG 2.13|BG 2.13]])
:([[Vanisource:BG 2.13 (1972)|BG 2.13]])

Dehinaḥ, emi eda, ara na lon paaro. Beena, leyin to ba ku, leyin iku yi... Nitoripe kos'iku. Leyin ti ara eda yi o ba sise mo, emi re ma wole sinu ara imi. oro tawa ti ko lati Bhagavad-gita niyen. T'awa ba si gba awon oro wanyi, " Oto-oro loje, leyin na ile aye wa ma bere. laini oye yi, kosejo imoye mimo. Kosi nkankan tole daju, irori lasan ni gbogbo e maje, " boya," awon onisayensi ati awon alamodaju lon so awon isokuso wanyi. sugbon awa o le gba awon oro bi " boya," "o da biwipe". Rara. Otooro nikan lawa n'feti si. Kon sejo igbagbo, otooro lawan'wa. Beena otooro towa niyen. Nisin, bawo ni emi yi sen paaro awon ara eda? Kasowipe leyin ile aye yi, moni ile aye to daju bayi lo.

Latest revision as of 00:19, 14 June 2018

Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

Beena nibi, Krsna ti juwe imoye to daju yi:

dehino 'smin yathā dehe
kaumāraṁ yauvanaṁ jarā
tathā dehāntara-prāptir
dhīras tatra na muhyati
(BG 2.13)

Dehinaḥ, emi eda, ara na lon paaro. Beena, leyin to ba ku, leyin iku yi... Nitoripe kos'iku. Leyin ti ara eda yi o ba sise mo, emi re ma wole sinu ara imi. oro tawa ti ko lati Bhagavad-gita niyen. T'awa ba si gba awon oro wanyi, " Oto-oro loje, leyin na ile aye wa ma bere. laini oye yi, kosejo imoye mimo. Kosi nkankan tole daju, irori lasan ni gbogbo e maje, " boya," awon onisayensi ati awon alamodaju lon so awon isokuso wanyi. sugbon awa o le gba awon oro bi " boya," "o da biwipe". Rara. Otooro nikan lawa n'feti si. Kon sejo igbagbo, otooro lawan'wa. Beena otooro towa niyen. Nisin, bawo ni emi yi sen paaro awon ara eda? Kasowipe leyin ile aye yi, moni ile aye to daju bayi lo.

sugbon tinba ni aye tio da, lehin kilo faa? Kasowipe ninu aye to kan mo ni ara ologbo tabi aja tabi maalu. Kasowipe eyin ti ni ibimo ni America. sugbon teyin ba paaro ara yin, gbogbo nkan to tele na ma yi. Awon eda eyan ni idaabo lati ijoba, sugbon lesekese teyin ba ni ara imi bi igi tabi eranko, bonse ma huwa siyin ma yato. won ko awon eranko losi ile -iperan, won ge awon igi danu. Koseni ton gbeja won. Beena ipo ile aye yi niyen. Nigbami eyin leni ipo aye to da, nigbami eyin le bosinu ipo aye to kere. Ko daju. Lori iru ise mi niyen wa. oun to daju niyen. ninu aye yi, teyin ba keeko, ojo waaju yin ma da. Teyin o ba keeko, lehin na ojo waju yin o ni da. Beena, ara eda eyan yi, awa le lo lati fi ipaari si iyika ninu ibimo ati iku yi. ise kan soso ti awon eda eyan ni niyen, basele jade kuro ninu ipo aye yi: ibimo, iku, ojo arugbo ati aisan. Ale wa ona abayo fun. imoye Krsna ni ona abayo yi. Lesekese t'awa ba ni imoye Krsna... Itumo imoye Krsna ni Krsna, Eledumare, Oluwa. Nkankana laje pelu Krsna. Imoye Krsna leleyi. Egbiyanju lati ni oye re.. gege bi eyin se mo nipa baba yin, ati awon aburo yi at'eyin na. Omo baba yin ni gbogbo yin je. Beena ko le lati ni oye na. Oluwa lon toju gbogbo agbaye bi baba wa, Oni awon omo to po gan, awon eda, oun lon toju gbogbo won, gbogbo ebi yi. Kini isoro towa nibe? Lehin ise to ku ni wupe agbodo ji imoye wa soke. Gege bi omo-okurin to da, toba ti rowipe " Baba mi ti se nkan to da funmi. Mogbo do se nkan fun lati dupe fun nkan tose funmi," iru ironu yi lonpe ni imoye Krsna