YO/Prabhupada 0719 - Taking Sannyasa - Keep it Very Perfectly: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0719 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1976 Category:YO-Quotes - Le...")
 
m (Text replacement - "MAYAPUR clip" to "MAYAPUR_clip")
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0718 - Sons and Disciples Should Be Always Chastised|0718|YO/Prabhupada 0720 - Control Your Lusty Desire by Krishna Consciousness|0720}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>File:760205IN-MAYAPUR clip1.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/760205IN-MAYAPUR_clip1.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 11:25, 29 November 2017



Excerpt from Sannyasa Initiation of Viraha Prakasa Swami -- Mayapur, February 5, 1976

Śrī Caitanya Mahāprabhu gbe nibi teyin tin gba sannyasi yi. kini di fun sannyasi to gba? brahmana to se pataki loje, Nimai Pandita. Ilu yi, Navadvipa, ilu awon brahmana ton keeko gan lat'aye atijo. Beena Śrī Caitanya Mahāprabhu si je ikan ninu awon ebi brahmana, omo-okurin Jagannātha Miśra; baba agba re, Nīlāmbara Cakravartī. Awon eyan pataki. Ninu ebi yi lon bi si. O si lewa gan, nitorina lonsen pe ni Gaurasundara. Akeko pataki losi je, nitorina ni oruko imi fun je Nimai Pandita. Beena, ninu ile re osi ni iyawo to lewa gan, Visnupriya, iya to dara gan, eyan pataki loje. Eyin na mobe. Ni ijo kan soso, o ko awon eyan to ogorun egberun lati losi ile Kazi Bayi eyin na leri wipe eyan pataki loje. Eyan toni iru ipo bayi, iode tose gba sannyasa, to kuru ni ile? Dayitaye: lati fun awon elese ni ore-ofe ninu ile aye yi.

Beena o si fi aami sile wipe enikeni ton ba bi sinu orileede India,

bhārata-bhūmite manuṣya-janma haila yāra
janma sārthaka kari' kara para-upakāra
(CC Adi 9.41)

O si fi han basele se para-upakara, ise ore-ofe si awon eda, awon elese. sannyasa yi, itumo re niwipe eyin tele ilana Śrī Caitanya Mahāprabhu,

āmāra ājñāya guru hañā tara' ei deśa
yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa
(CC Madhya 7.128)

Awa o si fe ko jepe awon ara ilu India nikan lon ni ise yi, sugbon Śrī Caitanya Mahāprabhu, sowipe enikeni - pṛthivīte āche yata nagarādi grāma (CB Antya-khaṇḍa 4.126) - kon gba ise iwaasu yi. Mosi dupe lowo eyin omo-okurin at'obirin lati ilu America pe eti mu egbe imoye Krsna yi sokan, ni pataki. pelu ore-ofe Sri Caitanya Mahāprabhu imi ninu yin tin gba sannyasa. Ema se bayi lo lati ilu kan si ikeji, abule kan sikeji, nigbogbo agbaye, e pin egbe imoye Krsna yi kaa kiri ki inu gbogbo eyan bale dunsi. Awon eyan jiya gan. Nitoripe mudha ati oniranu niwon, won o mo biwn sele lo ara eda tonni. bhāgavata-dharma t'awan mu kakiri niyen. Ara eda eyan teni yi, ema fi d'aja, elede. E d'eyan pipe. Śuddhyet sattva. E so ile aye yin di mimo. Kilode teyin senni ibimo, iku, ojo arugbo, at'aisan? Nitoripe eyin o wa mimo. Nisin, teba le ya si mimo, gbogbo eto ibimo, iku, ojo arugbo at'aisan ma tan. Nkan ti Śrī Caitanya Mahāprabhu ati Krsna fun ara re so leleyi. Teba le ni oye nipa Krsna, ema di mimo ema bo lowo idoti ibimo, iku, ojo-arugbo at'aisan. Egbiyanju alti se waasu fun awon eyan, awon alakowe, awon elesin. Awa o se isasoto kankan. Enikeni le se papo pelu egbe wa, kosi ya si mimo. Janma sārthaka kari' kara para-upakāra (CC Adi 9.41). Inu mi si dun gan. Eti sise fun egbe yi. Nisin egba sannyasa ke sewaasu ninu gbogbo agbaye ki awon eyan ba le jeere. Ese pupo.

Olufokansi: Jaya Śrīla Prabhupāda.