YO/Prabhupada 1063 - Funwa ni irorun lati ise ati abajade ise wa: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1063 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1062 - Awa sin'iwa lati fe ni idari lori iseda aye yi|1062|YO/Prabhupada 1064 - Oluwa si wa ninu okan gbogbo awon eda|1064}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|Ni8_my_2jiM|Give us Relief from the Actions and Reactions of all Activities - Prabhupāda 1063}}
{{youtube_right|Ni8_my_2jiM|Fun wa ni irọrun ninu awọn isẹ ati iyọrisi wọn - Prabhupāda 1063}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660219BG-NEW_YORK_clip07.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660219BG-NEW_YORK_clip07.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Gege ninu aye tawa yi, awa n'gbadun ise wa, ijeere ise wa. Kasowipe onisowo nimi timo de ti sise gan pelu ogbon ori mi timo de ni owo to po ninu ile ifowo . Nisin emi ni onigbadun. Beena, hasowipe moti bere ise mi pelu owo to po, sugbon tin ba se ise ipadanu.. timo s'owo nu. Beena mon jiya. Beena, ni gbogbo ise aye yi awa sin gbadun, awa gbadun ijeere ise wa. Nkan ton pe ni karma niyen.  
Fun apẹẹrẹ ninu aye ti awa yi, awa n;gbadun ise wa, ijeere ise wa. ka gba pe onisowo ni mi mo si fi ọgbọn kara mọ isẹ gan ti mo si ti wa ko ọrọ nla jọ sinu ile ifowopamọ. Nigbana emi o si jẹ onigbadun. Bakanna, ka sowipe mo ti bere ise mi pelu owo to po, Sugbọn ka sọ pe mo ti padanu gbogbo owo mi sinu owo; Bákan náà, gbogbo iriri aye a o gbadun ere isẹ wa Eyi ni a npe ni karma, kadara.  


Beena awon nkan wanyi, isvara, jiva, prakrti, tabi Eledumare, tabi awon eda, ile aye yi, asiko tayeraye, ati awon ise orisirisi tani, wanti salaaye awon nkan wanyi ninu Bhagavad-gita. Nisn ninu awon nkan marun wanyi, awon eda, ile aye yi ati asiko, awon nkan merin wanyi wa tayeraye. Nisin ifarahan, ifarahan prakrti le wa fun igba die, sugbon eyin o wipe nkan eke loje. Awon alakowe ti sowipe ifarahan ile aye yi pe eke loje, sugbon imoye Bhagavad-gita sowipe, tabi imoye awon Vaisnava, won o gba ifarahan ile aye yi bi eke. Won gba pe gidi ni ile aye yi je, sugbon fub igba die lowa. gege bi sanmo sen kojo ti asiko omi ojo bafe bere, leyin igbati asiko omi ojo yi ba bere, awon ewe tuntun asi jade lori ibikibi, ale jerisi. Lesekese ti asiko omi ojo ba de tan, awon sanmo na ma paare. Nigbogbogba, ti awon ewe yi ba gbe tan, ile na ma yagan. Beena, fun asiko die ni ile aye yi wa. Toba ya o ma yewa, am mo, lati awon iwe Bhagavad-gita. Bhūtvā bhūtvā pralīyate ([[Vanisource:BG 8.19|BG 8.19]]). Iseda yi ma farahan fun igba die leyin na, asi paare. Ise prakrit niyen. Sugbon tayeraye lon sise, nitorina tayeraye ni prakrti wa. Nkan eke ko loje. Nitoripe Oluwa ti gba pe, mama prakrti, " Prakrti Mi." Apareyam itas tu viddhi me prakṛtiṁ parām ([[Vanisource:BG 7.5|BG 7.5]]). Bhinnā prakṛti, bhinnā prakṛti, aparā prakṛti. Agbara toya to imi t'Oluwa ni iseda aye yi je, ati awon eda, agbara Oluwa na lon je sugbon won wa paapo. Won wa paapo tayeraye. Beena Oluwa, awon eda, agbaye, iseda aye yi, ati asiko, tayeraye lon wa fun. Sugon nkan toku, karma, fun asiko die lo wa. Awon ibajade karma tabi ise wa le wa fun asiko to pe gan. Awa sin jiya tabi awa n'gbadun ibajade ise wa lati aimoye igba, sugbon a le jeki awon ibajade karma wa yika. Sugbon ogbon pipe niyen ma gba. Awa sin sise to po gan, sugbon oye ka mo iru ise wo loye ka se tole funwa ni irorun lati gbogbo ibajade ise wa. Wanti salaaye ninu Bhagavad-gita.  
Bẹ awọn nkan wanyi, isvara, jiva, prakrti, tabi Eledumare, tabi awon eda, ile aye yi, akoko ayeraye, ati awon aṣayan iṣẹ-ṣiṣe, gbogbo wọn ti ni alaye ninu iwe mimọ Bhagavad Gita. Ninu awọn maarun wọnyi, Oluwa, awọn ẹda alaye, ìṣẹdà aye ati akoko awon mẹrin yi ni wọn jẹ ainipẹkun. Ifarahan ti prakriti le wa fun igba diẹ, sugbọn kii se ẹtan Awọn ọjọgbọn kan sọ pe awọn ifarahan ti ìṣẹdà aye jẹ ẹtan ṣugbọn gẹgẹ bi imoye Bhagavad Gita tabi gẹgẹ bi imoye ti awọn Vaiṣṇavas, won o gba ifarahan ile aye yi bi eke. Ifarahan ti aye ki se ohun ti a gba bi ẹtan; a ti gba bi ohun gidi, sugbọn o wa fun igba diẹ. A le fiwe awọsanma ti o nkọja loju ọrun, tabi ti igba ojo ba bẹrẹ leyin igbati asiko omi ojo yi ba bere, awon ewe tuntun asi jade lori ibikibi, ale jerisi. Ni kete bi igba ojo ba ti da ati ni gbara ti awọsanma ba ti kuro,. Nigbogbogba, gbogbo awọn irugbin ti ojo mu dagba ni wọn o gbẹ. Bákan náà, ifarahan isẹda yi nsẹlẹ ni akoko si akoko, Toba ya o ma yewa, a ma mo, lati inu awon iwe Bhagavad-gita. Bhūtvā bhūtvā pralīyate ([[Vanisource:BG 8.19 (1972)|BG 8.19]]). Bákan náà, ifarahan isẹda yi nsẹlẹ ni akoko si akoko, duro fun igba diẹ lẹhinna a si farasin. Bayi ni ise ti prakriti. Ṣugbọn ayipo yi nsisẹ titi ayeraye. Nitorina ni prakriti se jẹ ainipẹkun. Nkan eke ko loje. Nitoripe Oluwa ti gba pe, mama prakrti, " Prakrti Mi." Apareyam itas tu viddhi me prakṛtiṁ parām ([[Vanisource:BG 7.5 (1972)|BG 7.5]]). Bhinnā prakṛti, bhinnā prakṛti, aparā prakṛti. Iṣẹdà aye yi jẹ agbara Ọlọrun Ọba ti o ti pinya, bakanna si ni awọn ẹda alaye se jẹ agbara ti Ọlọrun Ọba na, won o pinya Wọn tan mọra titi ayeraye. Nitorina Oluwa, ẹda alaye, ìṣẹdà aye ati akoko gbogbo wọn ni wọn ni ibatan ti wọn si wa fun ayeraye. Sibẹsibẹ, ohun kan miiran wa, karma, ti ki ise fun ayeraye. Nitõtọ ipa karma ti le wa ko lọjọ lori. A njiya tabi a ngbádùn awọn ere isẹ ọwọ wa lati igba ainipẹkun, sugbọn a le se ayipada awọn iyọrisi karma wa tabi aṣayan iṣẹ wa, ayipada na si da lori asepe ti ìmọ wa. A nkopa ninu orisirisi akitiyan isẹ. Laisi-aniani a ko mọ iru akitiyan ti a le se ti o le fun wa ni irọrun ninu awọn isẹ ati iyọrisi wọn, Eyini na tun ni alaye ninu Bhagavad Gita.  


Nisin, imoye toje pipe ni ipo isvara. Ipo isvara, tabi Eledumare, imoye to gaju loje. awon jiva, tabi awon eda, tonje nkankan na pelu Eledumare, awon na daju. Awon eda daju. Prakrti ni awon eda yi je, agbara, won de ti salaaye wipe iseda aye yi pe prakrti na loje, sugbon laarin awon meejeji, prakrti kan, awon jiva, won daju. Prakrti keji o daju. Iyato to wa niyen. Nitorina ni jiva prakrti se gaju nitoripe won ni iru imoye t'Oluwa. Oluwa loni imoye to gaju. Awon eyan o gbodo fi awon eda lasan fi we Oluwa Rara. Awon eda aye yi kosi bonsele logbon to wa ni pipe ju ninu igbese aye won. Imoye iranu leleyi, Imoye iranu. Sugbon o daju. Otan. Sugbon oun ko lo daju ju.  
Imoye ti o gaju ni ipo ti īśvara, Ọlọrun Ọba. Ipo isvara, tabi Eledumare, imoye to gaju loje. Awọn jīvas, tabi awọn ẹda alãye, bi wọn se jẹ ẹya ara Ọlọrun Ọba, awọn na tun ni imọ sinu ara wọn awọn na tun ni imọ sinu ara wọn. Ẹda alãye ati isẹda aye awọn mejeji ni wọn ti tumọ si prakriti, ṣugbọn ọkan ninu awọn mejeji, jiva, ni o ni imọ sinu. Ikeji Prakriti ko ni imọ sinu. Eyini ni iyatọ. Nitorina ni a se npe jiva-prakriti bi eyi ti o gaju nitori awọn jiva ni imoye ti o jẹ irukanna pẹlu ti Oluwa. Ti Oluwa ni imọye ti o gaju lọ, sibẹsibẹ, ko si ẹni ti o gbọdọ ro wipe jiva, awọn ẹda alãye, na jẹ onimọ-ye to gaju lọ. Rara. Ẹda alãye ko le fi igba kan di onimọ to gaju lọ ni ipo kipo asepe rẹ, ati idamọran wipe o le jẹ bẹ jẹ ero isinilọna. Ka nimọ sinu o le jẹ bẹ, sugbọn ki ise ni pipe tabi mimọ to ga julọ.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:29, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Fun apẹẹrẹ ninu aye ti awa yi, awa n;gbadun ise wa, ijeere ise wa. ka gba pe onisowo ni mi mo si fi ọgbọn kara mọ isẹ gan ti mo si ti wa ko ọrọ nla jọ sinu ile ifowopamọ. Nigbana emi o si jẹ onigbadun. Bakanna, ka sowipe mo ti bere ise mi pelu owo to po, Sugbọn ka sọ pe mo ti padanu gbogbo owo mi sinu owo; Bákan náà, ní gbogbo iriri aye a o gbadun ere isẹ wa Eyi ni a npe ni karma, kadara.

Bẹ awọn nkan wanyi, isvara, jiva, prakrti, tabi Eledumare, tabi awon eda, ile aye yi, akoko ayeraye, ati awon aṣayan iṣẹ-ṣiṣe, gbogbo wọn ti ni alaye ninu iwe mimọ Bhagavad Gita. Ninu awọn maarun wọnyi, Oluwa, awọn ẹda alaye, ìṣẹdà aye ati akoko awon mẹrin yi ni wọn jẹ ainipẹkun. Ifarahan ti prakriti le wa fun igba diẹ, sugbọn kii se ẹtan Awọn ọjọgbọn kan sọ pe awọn ifarahan ti ìṣẹdà aye jẹ ẹtan ṣugbọn gẹgẹ bi imoye Bhagavad Gita tabi gẹgẹ bi imoye ti awọn Vaiṣṇavas, won o gba ifarahan ile aye yi bi eke. Ifarahan ti aye ki se ohun ti a gba bi ẹtan; a ti gba bi ohun gidi, sugbọn o wa fun igba diẹ. A le fiwe awọsanma ti o nkọja loju ọrun, tabi ti igba ojo ba bẹrẹ leyin igbati asiko omi ojo yi ba bere, awon ewe tuntun asi jade lori ibikibi, ale jerisi. Ni kete bi igba ojo ba ti da ati ni gbara ti awọsanma ba ti kuro,. Nigbogbogba, gbogbo awọn irugbin ti ojo mu dagba ni wọn o gbẹ. Bákan náà, ifarahan isẹda yi nsẹlẹ ni akoko si akoko, Toba ya o ma yewa, a ma mo, lati inu awon iwe Bhagavad-gita. Bhūtvā bhūtvā pralīyate (BG 8.19). Bákan náà, ifarahan isẹda yi nsẹlẹ ni akoko si akoko, duro fun igba diẹ lẹhinna a si farasin. Bayi ni ise ti prakriti. Ṣugbọn ayipo yi nsisẹ titi ayeraye. Nitorina ni prakriti se jẹ ainipẹkun. Nkan eke ko loje. Nitoripe Oluwa ti gba pe, mama prakrti, " Prakrti Mi." Apareyam itas tu viddhi me prakṛtiṁ parām (BG 7.5). Bhinnā prakṛti, bhinnā prakṛti, aparā prakṛti. Iṣẹdà aye yi jẹ agbara Ọlọrun Ọba ti o ti pinya, bakanna si ni awọn ẹda alaye se jẹ agbara ti Ọlọrun Ọba na, won o pinya Wọn tan mọra titi ayeraye. Nitorina Oluwa, ẹda alaye, ìṣẹdà aye ati akoko gbogbo wọn ni wọn ni ibatan ti wọn si wa fun ayeraye. Sibẹsibẹ, ohun kan miiran wa, karma, ti ki ise fun ayeraye. Nitõtọ ipa karma ti le wa ko lọjọ lori. A njiya tabi a ngbádùn awọn ere isẹ ọwọ wa lati igba ainipẹkun, sugbọn a le se ayipada awọn iyọrisi karma wa tabi aṣayan iṣẹ wa, ayipada na si da lori asepe ti ìmọ wa. A nkopa ninu orisirisi akitiyan isẹ. Laisi-aniani a ko mọ iru akitiyan ti a le se ti o le fun wa ni irọrun ninu awọn isẹ ati iyọrisi wọn, Eyini na tun ni alaye ninu Bhagavad Gita.

Imoye ti o gaju ni ipo ti īśvara, Ọlọrun Ọba. Ipo isvara, tabi Eledumare, imoye to gaju loje. Awọn jīvas, tabi awọn ẹda alãye, bi wọn se jẹ ẹya ara Ọlọrun Ọba, awọn na tun ni imọ sinu ara wọn awọn na tun ni imọ sinu ara wọn. Ẹda alãye ati isẹda aye awọn mejeji ni wọn ti tumọ si prakriti, ṣugbọn ọkan ninu awọn mejeji, jiva, ni o ni imọ sinu. Ikeji Prakriti ko ni imọ sinu. Eyini ni iyatọ. Nitorina ni a se npe jiva-prakriti bi eyi ti o gaju nitori awọn jiva ni imoye ti o jẹ irukanna pẹlu ti Oluwa. Ti Oluwa ni imọye ti o gaju lọ, sibẹsibẹ, ko si ẹni ti o gbọdọ ro wipe jiva, awọn ẹda alãye, na jẹ onimọ-ye to gaju lọ. Rara. Ẹda alãye ko le fi igba kan di onimọ to gaju lọ ni ipo kipo asepe rẹ, ati idamọran wipe o le jẹ bẹ jẹ ero isinilọna. Ka nimọ sinu o le jẹ bẹ, sugbọn ki ise ni pipe tabi mimọ to ga julọ.