YO/Prabhupada 1064 - Oluwa si wa ninu okan gbogbo awon eda

Revision as of 09:55, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1064 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Eda to daju ju, won ma salaaye ninu Bhagavad-gita ninu apa iwe ton salaye nipa iyato laarin awon jiva ati isvara. Kṣetra-kṣetra-jña. Wanti salaaye nipa kṣetra-jña yi, kṣetra-jña na l'Oluwa je, atio awon jiva, tabi awon eda, awon na daju. Sugbon iyato to wa niwipe awon eda o mo ju nkan ton sele ninu ara won, sugbon Oluwa mo nkan ton sele ninu gbogbo ara awon eda. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati (BG 18.61).

Oluwa n'be ninu okan gbogbo awon eda, nitorina o mo gbogbo ironu okan, ise, awon eda. Oye ka ranti. Won de ti salaaye wipe Paramatma, tabi Eledumara, wa ninu okan gbogbo awon eda bi isvara, ni oludari osin fun won ni itosona. Oun lon fun wn ni itosona. Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭhaḥ (BG 15.15). Owa ninu okan gbogbo eyan, oun lon fun won ni itosona lati huwa bon sefe si. Awon eda man gbagbe nkan toye kan se. Ni alakoko asi gbiyanju lati huwa bakanna, lehin na asi bosinu idimu awon ise ati ibajade karma re. Sugbon lehin igba toba farale, toba wole sinu ara eda imi... Gege b'eyan to ba bo aso kan, fun aso imi, beena, wanti salaaye ninu Bhagavd-gita pe vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya (BG 2.22). Gege b'eyan sen bo ewu orisirisi, beena ni awon eda sen bo ara orisirisi, Irin ajo emi, ati awon ibajade ounkoun toti se koja. Beena o le paaro awon ise wanyi ti eda na ba wa lori ipo iwa rere, tosi mo iru iwa wo toye ko se, toba de se beena, lehin na gbogbo ise ati ibajade awon nkan toti se seyin ma yipo. Nitorin fun igba die ni karma wa fun. Ninu awon nkan marun to ku - īśvara, jīva, prakṛti, kāla, ati karma— awon nkan merin wanyi ma wa tayeraye, sugbon karma, fun igba die lo ma wa.

Nisin isvara to daju, isvara to daju ju, ati iyato laarin isvara to daju ju at'Oluwa, ati awon eda ninu asiko tawayi, bose je niyen. Imoye, t'Oluwa ati awon eda, imoye yi wa ni pipe. Konsepe lati asepo pelu awon nkan aye yi ni imoye na ti jade. Asise towa ninu ironu yi niyen. Imoye to sowipe lati akojopo oawon nkan aye yi nii imoye wa ti jade Bhagavad-gita o gba iru awon nkan bayi. Kosi bonsele se. Idaabo aye yi le funwa ni imoye imi tio jo imoye ton tinu wa jade, gege bi ina ton jade lati inu igo, ina yi asi jo awo igo na. Beena, imoye Oluwa, ko ni nkankan se pelu ile aye yi. Oluwa, gege bi Krsna, O sowipe, mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ (BG 9.10). Nigbato ba sokalew wa sinu ile aye yio, imoy ere o ni nkankan pelu awon nkan aye yi. Toba jepe imoye re wa labe agbara ile aye yi, kosi bosele soro lori Bhagavad-gita. Kosi beyan sele soro lori agbaye to wa ni pipe lai bolowo idoti imoye aye yi. Beena Oluwa o ni idoti kankan. Sugbon imoye aye wa lasiko yi, si ni doti aye yi. Beena, gege bi Bhagavad-gita sen ko wa, agbodo ya imoye ile aye yi si mimo, ninu imoye mimo yi, lale sise na,. Nkan to ma jeki inu wa dun niyen. Kosi basele fi ipaari si ise wa. Agbodo ya ise wa si mimo. awon ise yi tati yasi mimo lon pe ni bhakti. Itumo Bhakti niwipe, won daabi ise lasan, sugbon ise idoti ko loje. Ise mimo loje. Beena awon eyan lasan le riwipe awon olufokansi n'sise bi awon eyan lasan na, sugbon eni tio l'ogbon, kole mo wipe awon ise t'olufokansi tabi ise Oluwa, kosi bonsele doti pelu oun ile aye yi, idoti awon guna meta, ipo iseda, sugbon imoye to gaju. Imoye wa ti kodoti ile aye yi, oye ka mo.