YO/Prabhupada 1065 - Eyan gbodo ko ni alakoko pe ara eda yi ko loje

Revision as of 10:04, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1065 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Nisin ati bosinu idimu aye yi. Ipo idimu. igberaga wa... imoye eke.. Nitori imoye eke taani lasen rowipe " Lati awon nkan aye yi ni moti jade." Imoye eke niyen. Gbogbo ise wanyi, yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke (SB 10.84.13). Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke, eyan toba wa ninu ironu ara eda yi. Nisin, Oluwa ti salaaye gbogbo Bhagavvad-gita nitoripe Arjuna ti f'ara re si ipo aye yi. Beena eyan gbodo bo lowo ipo aye yi. Ise talakoko wa niyen fun enito bafe bolowo gbogbo awon nkan wanyi. Ni alakoko ogbodo ko wipe ara eda yi ko loje. Taba de ti bo lowo imoye ile aye yi, nkan ton pe ni mukti niyen. Teyan bati bolowo imoye ile aye yi itumo Mukti niyen. Ninu Śrīmad-Bhāgavata isotunmo igbala wa n'be: muktir hitvānyathā rūpaṁ svarūpeṇa vyavasthitiḥ (SB 2.10.6). Svarūpeṇa vyavasthitiḥ. Igbala lowoo imoye iranu ile aye yi nitumo Mukti, kasi bosinu imoye pipe. gbogbo itosona Bhagavad-gita, wa lati ji imoye yi soke. Awa ma ri ninu apa to keyin ninu itosona lati Bhagavad-gita pe Krsna sin bere lowo Arjuna pe boya imoye re ti yasi mimo. Boya imoye re ti yasi mimo. Lati sise b'Oluwa se fe nitumo imoye mimo yi. Imoye mimo niyen. Koko oro imoye mimo niyen. Imoye yi ti wa nibe, sugbon nitoripe awa si je nkankanna, nitorina losen da wa laamu. O daju pe a le ni isoro lati awon ipo ile aye yi. Sugbon Oluwa Eda to Gaju, kosi bi awon nkan bayi sele dalaamu. Oti koja iru idamu bayi. Iyato laarin Oluwa ati...

Kini imoye yi? Imoye eto pe 'Emi ni." Tani mi? Ninu ile aye yi itumo "Emi ni" niwipe " Emi l'olori gbogbo nkan ti mon wo." Imoye idoti niyen. Emi ni "Onigbadun." Gbogbo awon eda ninu aye yi, won rowipe " Emi l'Oluwa ati Eleda gbogbo agbaye yi." Apa meji ni imoye yi ni. Ikan ni wipe "Emi ni Eleda, " Ikeji niwipe " Emi ni onigbadun." Beena Oluwa ni Eleda to daju ati onigbadun to daju. ati awon eda, ton je nkankana pelu Oluwa, eleda tabi onigbadun ko loje, sugbon oni ranlowo loje. Gege bi ero odindin. Awon apa kekere ero na lon fun ero na ni iranlowo. Tabi t'aba keeko nipa bi ara eda se ri. Nisin, ninu ara eda yi, owo wa, ese wa, oju wa, gbogbo awon nkan wanyi lon sise, sugbon apa kekere ara ni gbogbo awon nkan wanyi, awon ko lon gbadun. Ikun lon gbadun. Ese wa sin rin kaakiri Owo wa lon s'ounje, eyin wa lon jeun, ati gbogbo apa ara eda, lon sise lati jeki ikun wa ni itelorun nitoripe ikun wa lo gaju ninu eto ara eda. a gbodo fun ikun wa ni gbogbo nkan. Prāṇopahārāc ca yathendriyāṇām (SB 4.31.14). Gege bi teyin ba d'omi si gbongbo igi. Tabi ele l'ara to wa laalafia.. Awon apa ara eda - owo, ese, oju, eti, ika owo - gbogbo won lon ma wa laalafia ton ba sise pelu ikun dada. Beena, eda to gajum Oluwa, oun ni onigbadun. Oun ni onigbadun, ati eleda. bi iranlowo si, ni awon eda aye yi je, agbodo sise pelu Re. Ibasepeo yi ma ranwalowo. Fun apeere, teyin ba f'owo bu ounje. Ti ika owo ba bere sini rowipe "kilode toje kin fun ikun ni ounje yi? Eje ka da nikan gbadun e." Asise niyen. Kosi bi ika owo sefe gbadun. Ti ika owo bafe gbadun ijeere ounje na, won gbodo fi ounje na sinu ikun.