YO/Prabhupada 1070 - Ise ifarasi Oluwa l'esin tayeraye fun awon eda aye yi: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1070 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1069 - Awon esin aye isin man soro nipa igbagbo. Igbagbo awon eyan le yipo - sugbon Sanatana dharma o le yipo|1069|YO/Prabhupada 1071 - T'aba ni asepo pelu Oluwa, ta ba sise fun, lehin na inu wa ma dun|1071}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|jf8XlK47ihQ|Rendering of Service is the Eternal Religion of the Living Being - Prabhupāda 1070}}
{{youtube_right|jf8XlK47ihQ|Ise ifarasi Oluwa l'esin tayeraye fun awon eda aye yi - Prabhupāda 1070}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip14.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip14.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Taba tun pada si itumo sanatana-dharma, A le gbiyanju lati ni oye nipa itumo esin lati itumo orisun oro dharma ni ede Sanskrit. Itumo re ni wipe oun to wa nigbogbogba pelu nkan. gege base so tele, taba soro nipa ina lesekese na o yewa pe oru ati ina wa pelu ina yi. lais'oru ati ina, kosi tumo kankan si oro ina. Beena, agbodo sewaadi lati mo nkan to wa pelu awon eda aye yi nigbogbogba. Nkan to wa pelu awon eda nigbogbo'gba ni amuye re tayeraye, nkan tosi wa tayeraye ninu amuye eda ni esin tayeraye re. Nigbati Sanatana Gosvami beere lowo Śrī Caitanya Mahāprabhu nipa svarupa - ati salaaye tele nia svarupa to wa ninu gbogbo eda - svarupa tabi ipo talakoko gbogbo eda, Oluwa si daaun, pe ipo talakoko ti awon eda ni lati sise fun Oluwa. Sugbon t'aba tun oro Oluwa Caitanya yi wo, a le riwipe gbogbo awon eda wa ninu ise lati sise fun elomi. Awon eda sin sise fun elomi lori orisirisi ona, beena eda wanyi sin gbadun aye won. Awon eranko n'sise fun eda eyan, oniranse n'sise fun oga re, A ma sise fun oga B, B ma sise fun oga C, C ma sise fun oga D ati bayi bayi lo. Ninu awon nkan bayi, a le ri wipe ore kan le sise fun ore keji, iya le sise fun omo re, iyawo le sise fun oko rek tabi ki oko sise fun iyawo. Taba sewaadi ninu emi yi, a le riwipe kos'ayafi kankan ninu awujo awon eda nibo l'awa le wo tio si'se kankan. Awon oselu ma wa siwaju awon aawujo eda Lati danwon loju nipa ise tole se fun won. Awon eyan ton dibo na ma dibo fun nitoripe won reti pe oselu na ma sise fun awujo yi. Eni ton t'aja n'sise fun onibara, awon onise n'sise fun ijoba. Ijioba na n'sise fun ebi re, awon ebi na n'sise fun olori ile. Bayi a le riwipe koseni tio wa ninu iyika yi lati sise fun elomi, nitorina a le ri wipe ise ni nkan to wa pelu awon eda fun gbogbo'gba, beena a le sowipe ise sise fun awon eda ni esi tayeraye fun won eda. T'okurin ba sowipe oun wa ninu esin kan lat'asiko ati ibi ton bi si, imi atun sowipe, Hindu lojem tabi Musluman, tabi Kristeni, tabi Buddhist tabi elesin imi, awon esin bayi o paraapo pelu sanātana-dharma. Eni toje Hindu le paaro igbagbo re kodi Musluman, tabi ki Musluiman paaro igbagbo re kodi Hindu tabi Kristeni, ati bayi bayi lo, sugbon ninu gbogbo awon ipaaro igbagbo wanyi iyen o wipe onitoun na ti paaro ise tonse fun awon eyan. Boya Hindu, Musluman tabi Kristeni, ni gbogbo'gba, iranse eni kan loje, beena lati gbe igbagbo kan sori , sanatana-dharma ko niyen, sugbon nkan ton tele awon eda n'isw tonse, sanatana-dharma niyen. Beena looto gbogbo wa ni asepo pel'Oluwa ninu ise tanse. Onigbadun l'Oluwa je, awon eda agbodo sise fun. Fun igbadun re lase wa laaye, taba si ni asepo ninu igbadun yi pel'Oluwa, inu wa ma dunsi, awa o le se nkan imi ju bayi. Ati salaaye tele wipe, eyikeyi ninu awon apa ara eda, owo ese, ika owo, toba danikan wa, kosi bi inu re se fe dun laisi'kun, beena, inu awon eda o le dun lai sise fun Oluwa. Nisin, ninu Bhagavad-gita wanti salaaye wipe aw o gbodo s'ebo si awon orisirisi orisa nitoripe.... wanti salaaye ninu ([[Vanisource:BG 7.20|Bhagavad-gītā seventh chapter, twentieth verse]]), Oluwa sowipe,kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ prapadyante 'nya-devatāḥ. Kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ. Awon ton wa labe iwa ifekufe, awon lon s'adura si awon orisa wanyi, ju kan s'adura s'Oluwa Krsna.  
Iṣẹ-ṣiṣe ni ẹsin ayeraye ti awọn ẹda alãye Ni tọka si erongba ti sanatana-dharma, a gbọdọ gbiyanju lati ni oye ero ẹsin lati idi itumọ ọrọ na ninu ede Sanskrit. Dharma ntọkasi si eyi ti o wa nigbagbogbo tẹlẹ pẹlu ohun kan pato. Bi a ti sọ tẹlẹ, nigba ti a ba sọrọ nipa iná o ti wa ni opin ọrọ ni akoko kanna wipe ooru ati imọlẹ ni wọn ba ina se pọ laisi ooru ati imọlẹ, ina ko ni itumọ lọrọ. Bákan náà, a gbọdọ se iwari ipa ti ko le se mani fun ẹda alãye kọọkan, apa ti o jẹ ojugba rẹ nigbagbogbo. Ibakan ojugba na ni o jẹ iwa rẹ ayérayé, bẹni iwa ayérayé yi ni ẹsin ayeraye rẹ. Nigba ti Sanatana Goswami beere lọwọ Śrī Caitanya Mahāprabhu nipa svarūpa __ ati salaaye tele nipa svarupa ti gbogbo eda -alaaye svarupa tabi ipo ti ara ẹda, Oluwa si dahun, wipe ipo ti ara ẹda, ti ẹda alãye kọọkan ni lati se iṣẹ fun Eledumare. Ti a ba se itupalẹ gbólóhùn ti Oluwa Caitanya yi, a le ri nirọrun pe gbogbo ẹda alãye kọọkan ni o nse iṣẹ nigbagbogbo lati sise fun elomi. Ẹda alãye kan nse iṣẹ fun awọn ẹda alãye miiran ni ipa orisirisi. nipa ṣise bẹ, ẹda alãye ngbadun aye. Awọn ẹranko ti wọn rẹlẹ nsin awọn eniyan bi awọn iranṣẹ se nsin oluwa wọn. A nsin oluwa B, B nsin oluwa D, ati D nsin oluwa E ati bẹ bẹ lọ Labẹ awọn ayidayida wọnyi, a le ri wipe ọrẹ kan nsin ọrẹ keji, iya nsin awọn ọmọ rẹ, aya nsin ọkọ, ọkọ nsin iyawo ati bẹ bẹ lọ. Ti a ba se iwadi ninu ẹmí yi siwaju si, a o ri pe ko si ẹniti o da silẹ ninu asayan iṣẹ-ṣiṣe ninu awujọ awọn ọmọ eniyan nibo lo wa le ti a ko ri si'se kankan. Oniselu fi eto àkọsílẹ rẹ han fun gbogbo eniyan lati fi da wọn loju agbara rẹ fun iṣẹ. Awọn oludibo na fun awọn oselu ni ibo wọn to niyelori pelu ireti, pe wọn o se iṣẹ to niyelori fun awujọ. Onisowo nsin awọn onibara, awọn onisẹ-ọwọ na nsin awọn olowo. Awọn olowo-ọlọrọ nsin ẹbi, awọn ẹbi na nsin ipinlẹ ninu awọn ofin ti agbara ayeraye ti awọn ẹda alãye ainipẹkun. Ni ọna yi a ti le ri wipe ko si ẹda alãye kan ni imukuro ni iṣẹ-ṣiṣe fun ẹda alãye miiran, nitori naa a le pinnu wipe iṣẹ ni ibakan ojugba ti awọn ẹda alãye, ati nitori naa a le pinnu laifokan pe iṣẹ-ṣiṣe ni ẹsin ayeraye ti awọn ẹda alãye. Nigbati eniyan ba jẹri iru ẹsin kan pataki ti o tọkasi akoko ati igba ti wọn bi, ki o si wa pe ara rẹ ni Hindu, Musulumi, Kiriyo, Buddhist tabi ọmọ lẹhin ẹlẹgbẹ-nsẹgbẹ miran, awon ẹsin bayi o paraapo pelu sanātana-dharma. Ẹlẹsin Hindu le yi igbagbọ rẹ pada ko di Musulumi, tabi Musulumi le yi igbagbọ rẹ pada ko di Hindu, tabi Kiriyo le yi igbagbọ rẹ ati bẹ bẹ lọ Sugbọn ni igbakugba iru iyipada igbagbọ yi ko ni ipa lori ojúṣe ayeraye rẹ ti iṣẹ-ṣiṣe fun awọn miran. Ẹlẹsin Hindu, Musulumi tabi Kristiẹni ni igbakugba jẹ iranṣẹ ti ẹnikan. Bayi, lati jẹri iru igbagbọ kan ni pato ni ki a kọ ẹhin si sanatana-dharma wa. sugbon ibakan ojugba ẹda alaaye, eyini ni iṣẹ-ṣiṣe ni sanatana-dharma. Nitootọ nipa iṣẹ ni a fi jọmọ Oluwa Atobiju. Oluwa Atobiju ni onigbadun ju lọ, awa ẹda alaaye si jẹ awọn iransẹ Rẹ ayeraye. Fun igbadun Rẹ ni a se sẹda wa ti a ba si kopa ninu igbadun ayeraye pẹlu Ẹni Isaju Eledumare, inu wa a dun. A ko le ni idunnu ni ọna miran Ko ṣee ṣe lati ni idunnu ni adani, gẹgẹ bia ti salaaye tẹlẹ pe ni adani, ko si ẹya ara kan, ọwọ, ẹsẹ, ọwọ-ika, tabi ẹya ara kan, ti o le ni idunnu lai sowọpọ pẹlu inu-ikun, bakanna, ko ṣee ṣe fun awọn ẹda alãye lati ni idunnu lai se iṣẹ imọlẹ tọkantọkan fun Oluwa Atobiju. Nisin, ẹsin awọn orisirisi orisa akunlẹbọ tabi ki a ma s’àjo iṣẹ fún wọn ko ni ifọwọsi ninu Bhagavad Gita nitoripe... O jẹ imẹnukan, ninu ori iwe Keje Bhagavad-gītā ẹsẹ ogun ([[Vanisource:BG 7.20 (1972)|Bhagavad-gītā Apa meje, ese-iwe ogun]]), Oluwa so wipe, kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ prapadyante 'nya-devatāḥ. Kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ. Awọn ti afẹ aye ti pa oye wọn rẹ, fi ara wọn fun isin awọn orisa akunlẹbọ, ati pe ki ise Oluwa Ọlọrun Atobiju ni nwọn nsin.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:30, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Iṣẹ-ṣiṣe ni ẹsin ayeraye ti awọn ẹda alãye Ni tọka si erongba ti sanatana-dharma, a gbọdọ gbiyanju lati ni oye ero ẹsin lati idi itumọ ọrọ na ninu ede Sanskrit. Dharma ntọkasi si eyi ti o wa nigbagbogbo tẹlẹ pẹlu ohun kan pato. Bi a ti sọ tẹlẹ, nigba ti a ba sọrọ nipa iná o ti wa ni opin ọrọ ni akoko kanna wipe ooru ati imọlẹ ni wọn ba ina se pọ laisi ooru ati imọlẹ, ina ko ni itumọ lọrọ. Bákan náà, a gbọdọ se iwari ipa ti ko le se mani fun ẹda alãye kọọkan, apa ti o jẹ ojugba rẹ nigbagbogbo. Ibakan ojugba na ni o jẹ iwa rẹ ayérayé, bẹni iwa ayérayé yi ni ẹsin ayeraye rẹ. Nigba ti Sanatana Goswami beere lọwọ Śrī Caitanya Mahāprabhu nipa svarūpa __ ati salaaye tele nipa svarupa ti gbogbo eda -alaaye svarupa tabi ipo ti ara ẹda, Oluwa si dahun, wipe ipo ti ara ẹda, ti ẹda alãye kọọkan ni lati se iṣẹ fun Eledumare. Ti a ba se itupalẹ gbólóhùn ti Oluwa Caitanya yi, a le ri nirọrun pe gbogbo ẹda alãye kọọkan ni o nse iṣẹ nigbagbogbo lati sise fun elomi. Ẹda alãye kan nse iṣẹ fun awọn ẹda alãye miiran ni ipa orisirisi. nipa ṣise bẹ, ẹda alãye ngbadun aye. Awọn ẹranko ti wọn rẹlẹ nsin awọn eniyan bi awọn iranṣẹ se nsin oluwa wọn. A nsin oluwa B, B nsin oluwa D, ati D nsin oluwa E ati bẹ bẹ lọ Labẹ awọn ayidayida wọnyi, a le ri wipe ọrẹ kan nsin ọrẹ keji, iya nsin awọn ọmọ rẹ, aya nsin ọkọ, ọkọ nsin iyawo ati bẹ bẹ lọ. Ti a ba se iwadi ninu ẹmí yi siwaju si, a o ri pe ko si ẹniti o da silẹ ninu asayan iṣẹ-ṣiṣe ninu awujọ awọn ọmọ eniyan nibo lo wa le ti a ko ri si'se kankan. Oniselu fi eto àkọsílẹ rẹ han fun gbogbo eniyan lati fi da wọn loju agbara rẹ fun iṣẹ. Awọn oludibo na fun awọn oselu ni ibo wọn to niyelori pelu ireti, pe wọn o se iṣẹ to niyelori fun awujọ. Onisowo nsin awọn onibara, awọn onisẹ-ọwọ na nsin awọn olowo. Awọn olowo-ọlọrọ nsin ẹbi, awọn ẹbi na nsin ipinlẹ ninu awọn ofin ti agbara ayeraye ti awọn ẹda alãye ainipẹkun. Ni ọna yi a ti le ri wipe ko si ẹda alãye kan ni imukuro ni iṣẹ-ṣiṣe fun ẹda alãye miiran, nitori naa a le pinnu wipe iṣẹ ni ibakan ojugba ti awọn ẹda alãye, ati nitori naa a le pinnu laifokan pe iṣẹ-ṣiṣe ni ẹsin ayeraye ti awọn ẹda alãye. Nigbati eniyan ba jẹri iru ẹsin kan pataki ti o tọkasi akoko ati igba ti wọn bi, ki o si wa pe ara rẹ ni Hindu, Musulumi, Kiriyo, Buddhist tabi ọmọ lẹhin ẹlẹgbẹ-nsẹgbẹ miran, awon ẹsin bayi o paraapo pelu sanātana-dharma. Ẹlẹsin Hindu le yi igbagbọ rẹ pada ko di Musulumi, tabi Musulumi le yi igbagbọ rẹ pada ko di Hindu, tabi Kiriyo le yi igbagbọ rẹ ati bẹ bẹ lọ Sugbọn ni igbakugba iru iyipada igbagbọ yi ko ni ipa lori ojúṣe ayeraye rẹ ti iṣẹ-ṣiṣe fun awọn miran. Ẹlẹsin Hindu, Musulumi tabi Kristiẹni ni igbakugba jẹ iranṣẹ ti ẹnikan. Bayi, lati jẹri iru igbagbọ kan ni pato ni ki a kọ ẹhin si sanatana-dharma wa. sugbon ibakan ojugba ẹda alaaye, eyini ni iṣẹ-ṣiṣe ni sanatana-dharma. Nitootọ nipa iṣẹ ni a fi jọmọ Oluwa Atobiju. Oluwa Atobiju ni onigbadun ju lọ, awa ẹda alaaye si jẹ awọn iransẹ Rẹ ayeraye. Fun igbadun Rẹ ni a se sẹda wa ti a ba si kopa ninu igbadun ayeraye pẹlu Ẹni Isaju Eledumare, inu wa a dun. A ko le ni idunnu ni ọna miran Ko ṣee ṣe lati ni idunnu ni adani, gẹgẹ bia ti salaaye tẹlẹ pe ni adani, ko si ẹya ara kan, ọwọ, ẹsẹ, ọwọ-ika, tabi ẹya ara kan, ti o le ni idunnu lai sowọpọ pẹlu inu-ikun, bakanna, ko ṣee ṣe fun awọn ẹda alãye lati ni idunnu lai se iṣẹ imọlẹ tọkantọkan fun Oluwa Atobiju. Nisin, ẹsin awọn orisirisi orisa akunlẹbọ tabi ki a ma s’àjo iṣẹ fún wọn ko ni ifọwọsi ninu Bhagavad Gita nitoripe... O jẹ imẹnukan, ninu ori iwe Keje Bhagavad-gītā ẹsẹ ogun (Bhagavad-gītā Apa meje, ese-iwe ogun), Oluwa so wipe, kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ prapadyante 'nya-devatāḥ. Kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ. Awọn ti afẹ aye ti pa oye wọn rẹ, fi ara wọn fun isin awọn orisa akunlẹbọ, ati pe ki ise Oluwa Ọlọrun Atobiju ni nwọn nsin.