YO/Prabhupada 1070 - Ise ifarasi Oluwa l'esin tayeraye fun awon eda aye yi

Revision as of 11:23, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1070 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Taba tun pada si itumo sanatana-dharma, A le gbiyanju lati ni oye nipa itumo esin lati itumo orisun oro dharma ni ede Sanskrit. Itumo re ni wipe oun to wa nigbogbogba pelu nkan. gege base so tele, taba soro nipa ina lesekese na o yewa pe oru ati ina wa pelu ina yi. lais'oru ati ina, kosi tumo kankan si oro ina. Beena, agbodo sewaadi lati mo nkan to wa pelu awon eda aye yi nigbogbogba. Nkan to wa pelu awon eda nigbogbo'gba ni amuye re tayeraye, nkan tosi wa tayeraye ninu amuye eda ni esin tayeraye re. Nigbati Sanatana Gosvami beere lowo Śrī Caitanya Mahāprabhu nipa svarupa - ati salaaye tele nia svarupa to wa ninu gbogbo eda - svarupa tabi ipo talakoko gbogbo eda, Oluwa si daaun, pe ipo talakoko ti awon eda ni lati sise fun Oluwa. Sugbon t'aba tun oro Oluwa Caitanya yi wo, a le riwipe gbogbo awon eda wa ninu ise lati sise fun elomi. Awon eda sin sise fun elomi lori orisirisi ona, beena eda wanyi sin gbadun aye won. Awon eranko n'sise fun eda eyan, oniranse n'sise fun oga re, A ma sise fun oga B, B ma sise fun oga C, C ma sise fun oga D ati bayi bayi lo. Ninu awon nkan bayi, a le ri wipe ore kan le sise fun ore keji, iya le sise fun omo re, iyawo le sise fun oko rek tabi ki oko sise fun iyawo. Taba sewaadi ninu emi yi, a le riwipe kos'ayafi kankan ninu awujo awon eda nibo l'awa le wo tio si'se kankan. Awon oselu ma wa siwaju awon aawujo eda Lati danwon loju nipa ise tole se fun won. Awon eyan ton dibo na ma dibo fun nitoripe won reti pe oselu na ma sise fun awujo yi. Eni ton t'aja n'sise fun onibara, awon onise n'sise fun ijoba. Ijioba na n'sise fun ebi re, awon ebi na n'sise fun olori ile. Bayi a le riwipe koseni tio wa ninu iyika yi lati sise fun elomi, nitorina a le ri wipe ise ni nkan to wa pelu awon eda fun gbogbo'gba, beena a le sowipe ise sise fun awon eda ni esi tayeraye fun won eda. T'okurin ba sowipe oun wa ninu esin kan lat'asiko ati ibi ton bi si, imi atun sowipe, Hindu lojem tabi Musluman, tabi Kristeni, tabi Buddhist tabi elesin imi, awon esin bayi o paraapo pelu sanātana-dharma. Eni toje Hindu le paaro igbagbo re kodi Musluman, tabi ki Musluiman paaro igbagbo re kodi Hindu tabi Kristeni, ati bayi bayi lo, sugbon ninu gbogbo awon ipaaro igbagbo wanyi iyen o wipe onitoun na ti paaro ise tonse fun awon eyan. Boya Hindu, Musluman tabi Kristeni, ni gbogbo'gba, iranse eni kan loje, beena lati gbe igbagbo kan sori , sanatana-dharma ko niyen, sugbon nkan ton tele awon eda n'isw tonse, sanatana-dharma niyen. Beena looto gbogbo wa ni asepo pel'Oluwa ninu ise tanse. Onigbadun l'Oluwa je, awon eda agbodo sise fun. Fun igbadun re lase wa laaye, taba si ni asepo ninu igbadun yi pel'Oluwa, inu wa ma dunsi, awa o le se nkan imi ju bayi. Ati salaaye tele wipe, eyikeyi ninu awon apa ara eda, owo ese, ika owo, toba danikan wa, kosi bi inu re se fe dun laisi'kun, beena, inu awon eda o le dun lai sise fun Oluwa. Nisin, ninu Bhagavad-gita wanti salaaye wipe aw o gbodo s'ebo si awon orisirisi orisa nitoripe.... wanti salaaye ninu (Bhagavad-gītā seventh chapter, twentieth verse), Oluwa sowipe,kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ prapadyante 'nya-devatāḥ. Kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ. Awon ton wa labe iwa ifekufe, awon lon s'adura si awon orisa wanyi, ju kan s'adura s'Oluwa Krsna.