YO/Prabhupada 1072 - Ka fi ile aye yi sile ka pada s'aye tio le paari ninu ijoba towa tayeraye

Revision as of 11:51, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1072 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Oluwa ti funwa l'ore ofe re ninu ara re Śyāmasundara-rūpa. Sugbon awon eyan tio logbon sin foju kekere wo. Avajānanti māṁ mūḍhā (BG 9.11). Nitoripe Oluwa ti wa bi ikan ninu wa, ton sere pelu fere bi eda eyan, nitorina awa o gbodo rowipe ikan ninu wa l'Olorun je. Pelu agbara re lati wa nibiki toba fe lose wa niwaju pelu ara re to si fi awon akoko idaraya re fi han, lati le nipa odo metalokan re. Beena odo metalokan Oluwa, aimoye awon isogbe na to wa ninu brahma-jyotir yi. gege b'ase ni aimoye awon isogbe ton fo kaa kiri lori ina orun, beena, ninu brahma-jyotir, ton jade kuro ninu odo metalokan Oluwa, Krsnaloka, Goloka, ānanda-cinmaya-rasa-pratibhāvitābhis (BS 5.37), mimo ni gbogbo awon isogbe wanyi. ānanda-cinmaya ni won; awon isogbe lasan ko lon je. Beena Oluwa ti sowipe,

na tad bhāsayate sūryo
na śaśāṅko na pāvakaḥ
yad gatvā na nivartante
tad dhāma paramaṁ mama
(BG 15.6)

Nisin enikeni tole summo sanmo mimo yi koni pada si sanmo ile aye yi. Toje pe awa si wa ninu ile aye yi, kama wa soro nipa isogbe osupa... Isogbe osupa, lo summo wa ju, sugbon taba tie de isogbe to gaju yi, ton pe ni Brahmaloka, nibe, awon isoro aye yina wa, Mon soro nipa ibimo, iku, ojo arugbo at'aisan. Kosi isogbe aye yi tio awon isoro merin wanyi o si mo. Nitorina Oluwa ti soro ninu Bhagavad-gita wipe, ābrahma-bhuvanāl lokāḥ punar āvartino 'rjuna (BG 8.16). Awon eda aye yi tonse irin ajo lati isogbe kan sikeji. konsepe da dede losi awon isogbe imi pelu awon ero sputnik. Enikeni toba fe losi awon isogbe imi, ilana toma tele wa. Yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ (BG 9.25). Teyan bafe losi awon isogbe imi bi osupa, awa o gbodo lo sputnik lati de bee. Bhagavad-gita ti salaaye wipe, yānti deva-vratā devān. Awon isogbe osupa tabi isogbe orun tabi awon isogbe lori Bhūloka, tonpe ni Svargaloka. Svargaloka. Bhūloka, Bhuvarloka, Svargaloka. Awon isogbe pelu ipo orisirisi leleyi. Beena Devaloka, bonse mo won niyen. Bhagavad-gita ti funwa ni itosona to rorun pe teyin ba fe lopsio awon isogbe giga wanyi, Devaloka. Yānti deva-vratā devān. Yānti deva-vratā devān. Deva-vratā, taba se adase lori eto ebo si awon orisa to wa lori isogbe yi, lehin na a le losi isogbe tafe. A le losi isogbe orun gan, isogbe osupa, ale losi awon isogbe orun, sugbon Bhagavad-gita o fe ka losi awon isogbe wanyi ton wa niu ile aye yi, nitoripe taba tie losi Brahmaloka, isogbe to gaju, ti awon onisayensi ti siro pe lati de bee pelu awon sputnik wanyi o ma to odun 40,000. Nisin kosi basele gbe laye yi to odun 40,000 lati de isogbe to gaju yi ninu ile aye yi. Sugbon teyan ba fi ile aye re fi s'adura s'orisa to wa lori isogbe yi, o le losi be, bon se juwe ninu Bhagavad-gītā: yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ (BG 9.25). Beena, Pitrloka leleyi. Beena, enikeni toba fe losi isogbe to gaju... Krsnaloka loje isogbe to gaju. Ninu sanmo mimo yi, aimoye awon isogbe to wa nibew, awon isogbe sanatana, awon isogbe tayeraye, tio le paare. Sugbon ninu gbogbo awon isogbe mimo wanyi, o ni'kan, t'alakoko, ton pe ni Goloka Vrndavana. Beena awon iroyion wanyi wa ninu Bhagavad-gita, a de ti gba'aye lati jade kuro ninu ile aye yi, kasi gba ile aye towa tayeraye ninu odo metalokan tayeraye.