YO/Prabhupada 1075 - Awa sin seto ile aye wa to kan ninu aye yi

Revision as of 14:20, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Oluwa sowipe anta-kāle ca mām eva smaran muktvā kalevaram (BG 8.5). Eni toba fi ara eda yi sile, pelu ironu nipa Oluwa Krsna, Eledumare, lesekese loma gba ara mimo toje sac-cid-ananda-vigraha (BS 5.1). Wanti salaaye dada Ilana lati f'ara eda yi sile ati basele gba ara imi ti wa Eda eyan ma ku leyin igba ton ba ti setoo iru ara eda wo loma ni ninu aye re to kan. Sugbon awon olori giga lon seto yi. gege ba sen ni ilosiwaju tabi ifaseyin ninu ise wa. Beena gege bi ise t'an se.. Awon iwa aye yi, lon setro iru aye ojio iwaju tale ni. Awa n'seto ara edato kan tafe ni pelu awon ise wa nisin. Beena taba le seto nisin ninu aye yi lati pada s'odo metalokan, beena o daju pe leyin igba taba f'ara eda yi sile... Oluwa sowipe yaḥ prayāti, eni to ba lo, sa mad-bhāvaṁ yāti (BG 8.5), mad-bhāvam... Iru ara t'Oluwa ni loun na mani. Nisin, Orisirisi awon eda mimo lowa, base salaaye tele. Awon brahmavādī, paramātmavādī ati awon olufokansi. Ninu sanmo mimo tabi ninu brahma-jyotir awon isogbe mimo wa nibe, aimoye awon isogbe wanyi, ati salaaye teletele. iwonba awon isogbe wanyi si po ju gbogbo awon agbaye ninu ile aye yi. ekāṁśena sthito jagat (BG 10.42) ni ile aye yi je. Ikan ninu apa merin gbogbo agbaye yi loje. odo metalokan ni meta lori merin to ku ninu apa kan lorin merin yi, aimoye awon agbaye na to wa bayi t'awa ti jeerisi nisin. ninu agbaye kan aimoye awon isogbe to wa. Beena aimoye awon orun ati irawo to wa ninu gbogbo agbaye yi, sugbon ikan ninu merin ni gbogbo agbayi yi ninu iseda aye. Odo metalokan ni meta lori merin to ku. Nisin, mad-bavam yi, eni to bafe wole sinu Brahman to gaju, won ma wole sinu brahma-jyotie Oluwa. brahma-jyotir ati awon isogbe mimo iyoku ninu brahma-jyotir nitumo Mad-bhāvam awon olufokansi, ton fe gbadun ninu asepo pel'Oluwa, won ma wole sinu awon isiogbe wanyi, isogbe Vainkuntha. Aimoye awon isogbe Vaikuntha to wa, at'Oluwa, Sri Krsna, pelu irisi re bi Narayana pel'owo merin at'oruko orisirisi, Pradyumna, Aniruddha, ati Mādhava, Govinda... Aimoye opruko towa fun irisi owo merin ti Narayana yi. Beena ikan ninu awon isogbe wanyi, mad-bhavam na niyen, iyen na wa ninu iseda mimo. Beena enikeni toba je onigbago, lasiko to ba fe ku, toba ronu nipa brahma-jyotir tabi toba ronu nipa Paramatma tabi toba ronu nipa Eledumare Sri Krsna, ikan ninu meta wanyi, asi wole sinu sanmo mimo. Sugbon awon olufokansi nikan ton ti ni asepo pel'Oluwa, awon lon le wole sinu isogbe Vaikuntha tabi Goloka Vrndavana. Oluwa sowipe, yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti nāsty atra saṁśayaḥ (BG 8.5). Kosi isiyemeji kankan. Eyan o gbodo ni iseyemeji. Ibeere to wa niyen. Beena eyin tin Bhagavad-gita ninu gbogbo aye re, sugbon t'Oluwa ba so nkan tio jo nkan to wa lori wa, ama ti segbe kan. Ilana to wa ko niyen fun kika iwe Bhagavad-gita. Gege bi Arjuna to sowipe sarvam etaṁ ṛtam manye, " Mo ni gbagbo ninu ounkoun teba so." Beena, igboran. Oluwa sowipe lasiko iku, enikeni toba ronu nipa re, boya bi Brahman tabi Paramatma tabi Eledumare, eni na ma wole sinu sanmo mimo, kosejo kankan nibe. Eyan o gbodo ni isiyemeji kankan. ilana to wa yi, wanti salaaye ofin yi ninu Bhagavad-gita, basele wole sinu odo metalokan t'aban ronu nipa Eledumare lasiko iku wa. Nitoripe wan ti salaaye wipe:

yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ
tyajaty ante kalevaram
taṁ tam evaiti kaunteya
sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ
(BG 8.6)