YO/Prabhupada 1078 - Ton ronu t'okan t'ara wakati merin le-logun nipa Oluwa: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 1: Line 1:
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0001 - in all Languages]]
[[Category:Prabhupada 1078 - in all Languages]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1077 - Oluwa tosi wa ni pipe, kosi iyato kankan laarin Oruko re at'Oun fun ara re|1077|YO/Prabhupada 1079 - Iwe mimo ti gbogbo awon eyan gbodo ka dada ni Bhagavdad-gita je|1079}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|V4RzPKgzWmk|Absorbed Both By The Mind and Intelligence Twenty-four Hours Thinking of the Lord - Prabhupāda 1078}}
{{youtube_right|V4RzPKgzWmk|Ton ronu t'okan t'ara wakati merin le-logun nipa Oluwa - Prabhupāda 1078}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip22.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip22.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Nigbat'eyin ba ni ife to le gan fun Eledumare, lehin o daju pe ale sise wa kasii ronu nipa re. Beena agbodo ji iye ara wa soke. Gege bi Arjuna sen ronu nipa Oluwa nigbogbo'gba. Kode gbagbe Krsna fun iseju kan. Alabasepo Krsna nigbogbo'gba. Lesekana, jagunjagun. Oluwa Krsna o so fun Arjuna pe ko ma jagun mo, pe ko losinu aginju, lori Himalaya ko lo sasaro. Nigbato sofun Arjuna kose yoga, Arjuna o gba, pe "Ilana yi ti le ju fun mi." Lehin na Oluwa sowipe, yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntarātmanā ([[Vanisource:BG 6.47|BG 6.47]]). Mad-gatenāntarātmanā śraddhāvān bhajate yo māṁ sa me yuktatamo mataḥ. Beena enikeni toba ronu nipa Eledumare, ouin ni yogi to gaju, oun ni jnani to gaju, oun de ni olufokansi to gaju lese kanna. Olorun ti funwa ni itosona pe tasmāt sarveṣu kāleṣu mām anusmara yudhya ca ([[Vanisource:BG 8.7|BG 8.7]]). " ksatriya loje kosi bosele fi ogun jija si;e. Ogbodo jagun. Beena lasiko kanna o gbodo ranti Mi nigbogbogba, lehin na o le sese." anta-kāle ca mām eva smaran ([[Vanisource:BG 8.5|BG 8.5]]), "lehin t'asiko iku ba de wasii le ranti Mi." Mayy arpita-mano-buddhir mām evaiṣyasy asaṁśayaḥ. Leekan si otun sowipe kosi isiyemeji kankan. Teyan ba farafun si ise Oluwa, ninu ise ife s'Oluwa, mayy arpita-mano-buddhir ([[Vanisource:BG 8.7|BG 8.7]]). Nitoripe awa o kin sise pelu ara wa nikan. Awa n'sise pel'okan wa at'ogbon. Beena ti ogbon at'okan wa ba wa ninu ironu Oluwa, leyin na iye ara wa ma ni nkan se ninu ise Oluwa. Asiri Bhagavad-gita niyen. Eyan gbodo k'ogbon yi, beyan sele fokan le nkan dada, pel'okan at'ogbon, wakati merinle logun lori ironu Oluwa. Eleyi ma ranwalowo lati pada s'odo metalokan tabi si adugbo mimo leyin igba toba f'ara eda yi sile. Awon onisayensi won sowipe o ti pe ton ti gbiyanju lori eto na, lati de isogbe osupa,sugbon titi dision won o ti dee be/ Sugbon ninu Bhagavad-gita, won ti daba fun wa. kasowipe awson okurin le wa laaye fun odun aadota si... Koseni to fe ni ilosiwaju ninu eto imoye mimo fun odun aadota. Apeere to da leleyi. sugbon teyan ba gbiyanju lati s'ise yi fun odun mewa tabi marun, mayy arpita-mano-buddhir ([[Vanisource:BG 8.7|BG 8.7]])... Oro eto adase leleyi. Eto adaase yi le bosi pelu ise ifarasi Oluwa, śravaṇaṁ. Śravaṇaṁ. Ilana to rorun ju lati gboran.  
Oye ati ọkan ba nfi gbogbogba npero ti Ọlọrun Ọba wakati merin le-logun Ti ẹ ba ni ori ifẹ to lagbara fun Oluwa Ọlọrun, nigbana ni a si le ṣe iṣẹ ojuse wa ati tun se ranti Oluwa nigba kanna. Ṣugbọn a ni lati mu ori ifẹ na dagba. Arjuna, fun apẹẹrẹ, ti nlero Ọlọrun l’ọkan nigbagbogbo. Ninu wakati mẹrin-le l’ogun, ko fi iseju kan gbagbe Ọlọrun. O si jẹ ibakan ojugba Ọlọrun, bi o tun se jẹ jagunjagun lọwọ kanna. Ọlọrun kò fun ni imọran ki o fi jijagun silẹ ki o si lọ farati sinu igbo lati ṣe àṣaro lori Himalaya. Nigba ti Oluwa Ọlọrun salaaye awọn ọna sîsê yoga fun Arjuna, Arjuna sọ pé asa ọna sîsê yi ko ṣee ṣe fun oun, Arjuna sọ pé asa ọna sîsê yi ko ṣee ṣe fun mi.." Lehin na Oluwa sọ wipe, yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntarātmanā ([[Vanisource:BG 6.47 (1972)|BG 6.47]]). Mad-gatenāntarātmanā śraddhāvān bhajate yo māṁ sa me yuktatamo mataḥ. Nítorí náà, ẹni ti o ba nse ero ti Ọlọrun Ọba nigbagbogbo oun ni Yogi to ga julọ, jñānī to lokiki julọ, ati olufọkansin ti o ga julọ ni igba kanna. Ọlọrun ti se eyi nimọran tasmāt sarveṣu kāleṣu mām anusmara yudhya ca ([[Vanisource:BG 8.7 (1972)|BG 8.7]]). "Gẹgẹ bi kṣatriya, ajagun, ko le fi jijagun rẹ silẹ, ṣugbọn ti Arjuna ba nse iranti Ọlọrun ninu ija, nigbana yio see se," anta-kāle ca mām eva smaran ([[Vanisource:BG 8.5 (1972)|BG 8.5]]), "nigbana yio see se lati ranti Ọlọrun ni akoko ikú" Mayy arpita-mano-buddhir mām evaiṣyasy asaṁśayaḥ. Lẹẹkan si O tun sọ wipe ko si isiyemeji kankan. Ti eniyan ba jọwọ ara rẹ patapata ninu iṣẹ Oluwa. ninu iṣẹ ìfẹ imọlẹ ti Oluwa, mayy arpita-mano-buddhir ([[Vanisource:BG 8.7 (1972)|BG 8.7]]). Ki ise ara wa ni a fi nṣiṣẹ, lododo. ṣugbọn pẹlu ọkan ati ọgbọn wa. Bẹ ti oye ati ọkan ba nfi gbogboigba npero ti Ọlọrun Ọba, laifagbarase ni awọn iye-ara na ma kopa ninu iṣẹ Rẹ. Eyini si jẹ asiri ti Bhagavad-gita. Eniyan gbọdọ kọ ise ọna yi, bi a se nfi, ọkan ati oye sinu ero ti Oluwa, wakati mẹrin-le-logun. Iru ifọkansi na yoo jẹki eniyan le gbe ara rẹ si ijọba Ọlọrun tabi si sakaani ọrun lẹyin igba ti o ba ti fi awọ ara yi silẹ. Awọn eniyan iwoyi ti ngbiyanju fun ọdun si ọdun jọ gidigidi gan, lati de ori oṣupa, sugbọn sibẹ wọn ko ti sunmọ. Sugbon ninu Bhagavad-gita, won ti daba fun wa. Ti eniyan ba nireti a ti tunbọ se adọta ọdun si laye... o yẹ ki o fi akoko finifini yi se riro asa irántí Ẹni Isaju Eledumare. Eyini jẹ ero ti o dara gan. sugbọn ti eyan ba gbiyanju sise yi fun ọdun mẹwa tabi marun, mayy arpita-mano-buddhir ([[Vanisource:BG 8.7 (1972)|BG 8.7]])... O jẹ ọrọ ise ti iwa nìkan. Ati pe asa na le jẹ ṣiṣe ni rọọrun gidigidi nipa ilana isẹ Oluwa, śravaṇaṁ. Śravaṇaṁ. Ilana to rọrun julọ ni lati gbọran.  


:śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ
:śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ
Line 36: Line 39:
:arcanaṁ vandanaṁ dāsyaṁ
:arcanaṁ vandanaṁ dāsyaṁ
:sakhyam ātma-nivedanam
:sakhyam ātma-nivedanam
:([[Vanisource:SB 7.5.23|SB 7.5.23]])  
:([[Vanisource:SB 7.5.23-24|SB 7.5.23]])  


Awon ilana mesan wanyi lowa. Igboran lo rorun ju ninu gbogbo won.  
Awọn ilana mẹsan wọnyi, eyi ti o rọrun julọ ninu wọn jẹ śravaṇam.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:31, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Oye ati ọkan ba nfi gbogbogba npero ti Ọlọrun Ọba wakati merin le-logun Ti ẹ ba ni ori ifẹ to lagbara fun Oluwa Ọlọrun, nigbana ni a si le ṣe iṣẹ ojuse wa ati tun se ranti Oluwa nigba kanna. Ṣugbọn a ni lati mu ori ifẹ na dagba. Arjuna, fun apẹẹrẹ, ti nlero Ọlọrun l’ọkan nigbagbogbo. Ninu wakati mẹrin-le l’ogun, ko fi iseju kan gbagbe Ọlọrun. O si jẹ ibakan ojugba Ọlọrun, bi o tun se jẹ jagunjagun lọwọ kanna. Ọlọrun kò fun ni imọran ki o fi jijagun silẹ ki o si lọ farati sinu igbo lati ṣe àṣaro lori Himalaya. Nigba ti Oluwa Ọlọrun salaaye awọn ọna sîsê yoga fun Arjuna, Arjuna sọ pé asa ọna sîsê yi ko ṣee ṣe fun oun, Arjuna sọ pé asa ọna sîsê yi ko ṣee ṣe fun mi.." Lehin na Oluwa sọ wipe, yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntarātmanā (BG 6.47). Mad-gatenāntarātmanā śraddhāvān bhajate yo māṁ sa me yuktatamo mataḥ. Nítorí náà, ẹni ti o ba nse ero ti Ọlọrun Ọba nigbagbogbo oun ni Yogi to ga julọ, jñānī to lokiki julọ, ati olufọkansin ti o ga julọ ni igba kanna. Ọlọrun ti se eyi nimọran tasmāt sarveṣu kāleṣu mām anusmara yudhya ca (BG 8.7). "Gẹgẹ bi kṣatriya, ajagun, ko le fi jijagun rẹ silẹ, ṣugbọn ti Arjuna ba nse iranti Ọlọrun ninu ija, nigbana yio see se," anta-kāle ca mām eva smaran (BG 8.5), "nigbana yio see se lati ranti Ọlọrun ni akoko ikú" Mayy arpita-mano-buddhir mām evaiṣyasy asaṁśayaḥ. Lẹẹkan si O tun sọ wipe ko si isiyemeji kankan. Ti eniyan ba jọwọ ara rẹ patapata ninu iṣẹ Oluwa. ninu iṣẹ ìfẹ imọlẹ ti Oluwa, mayy arpita-mano-buddhir (BG 8.7). Ki ise ara wa ni a fi nṣiṣẹ, lododo. ṣugbọn pẹlu ọkan ati ọgbọn wa. Bẹ ti oye ati ọkan ba nfi gbogboigba npero ti Ọlọrun Ọba, laifagbarase ni awọn iye-ara na ma kopa ninu iṣẹ Rẹ. Eyini si jẹ asiri ti Bhagavad-gita. Eniyan gbọdọ kọ ise ọna yi, bi a se nfi, ọkan ati oye sinu ero ti Oluwa, wakati mẹrin-le-logun. Iru ifọkansi na yoo jẹki eniyan le gbe ara rẹ si ijọba Ọlọrun tabi si sakaani ọrun lẹyin igba ti o ba ti fi awọ ara yi silẹ. Awọn eniyan iwoyi ti ngbiyanju fun ọdun si ọdun jọ gidigidi gan, lati de ori oṣupa, sugbọn sibẹ wọn ko ti sunmọ. Sugbon ninu Bhagavad-gita, won ti daba fun wa. Ti eniyan ba nireti a ti tunbọ se adọta ọdun si laye... o yẹ ki o fi akoko finifini yi se riro asa irántí Ẹni Isaju Eledumare. Eyini jẹ ero ti o dara gan. sugbọn ti eyan ba gbiyanju sise yi fun ọdun mẹwa tabi marun, mayy arpita-mano-buddhir (BG 8.7)... O jẹ ọrọ ise ti iwa nìkan. Ati pe asa na le jẹ ṣiṣe ni rọọrun gidigidi nipa ilana isẹ Oluwa, śravaṇaṁ. Śravaṇaṁ. Ilana to rọrun julọ ni lati gbọran.

śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ
smaraṇaṁ pāda-sevanam
arcanaṁ vandanaṁ dāsyaṁ
sakhyam ātma-nivedanam
(SB 7.5.23)

Awọn ilana mẹsan wọnyi, eyi ti o rọrun julọ ninu wọn jẹ śravaṇam.