YO/Prabhupada 0033 - Patita-pavana ni oruko Mahaprabhu



Morning Walk -- October 4, 1975, Mauritius

Puṣṭa Kṛṣṇa: Awon ijoba ojo oni nfi ôwô ti awon iwa isé ti won ya ni lénun ti won si buru julô. Nitorina bawo lo se ma seese lati se irapada awon opo eniyan?

Prabhupāda: Se é ro wipe ijoba ko ni abawon?

Puṣṭa Kṛṣṇa: Rara.

Prabhupāda: Ti o ba je be? Won gbodo yô wôn kuro. Ijoba lôjô oni tumo si, alai nilari gbogbo. Awon alai nilari dibo fun awon alai nilari. Iyen ni isoro na. Ibi ki ibi ti é ba lô, awon alai nilari ni é ma padeè Manda. A sô itumô ré, manda. Ninu egbe wa paa pa awon alai nilari pô nbé. E wo irohin. Won ti wa paa pa lati se irapada, alai nilari ni won. Won o le fi iwa aini lari won silé. Nitori eyi won ti so ni gban gba ita, manda: gbogbo won ti bajé. Sougbon iyato kan to wa nibe ni wipe ninu egbe wa awon asebajé nyi pada, sugbon ni ode ko si iyi pada. Won ni ireti lati di eni rere, sugbon ni ode, ko si ireti. Iyen ni iyatô. Bi beko gbogbo won ni won buru. La ifi teni kan se, e le wi. Mandāḥ sumanda-matayo (SB 1.1.10). Bayi, bawo ni ijoba se ma dara? Eyi na o dara. Oruko Mahaprabhu ni Patita-pavana; Eni ti o ngba gbogbo awon eni ibi la. Ni aye Kali-yuga, awon eniyan ti won dara ko si mo - awon oniburu gbogbo. E gbodo di akinkanju ki e fi le do ju ko gbogbo awon eniyan buburu.