YO/Prabhupada 0041 - Ile- aye nisinyi kun fun ainirere



Lecture on BG 9.1 -- Melbourne, June 29, 1974

Imo to pe. Nitorina ti e ba ka Bhagavad Gita, e o ni imo to pe. Kini Bhagavan so bayi?

idaṁ tu te guhyatamaṁ
pravakṣyāmy anasūyave
(BG 9.1)

Bhagavān, Krishna nko Arjuna. Beni ni ori iwe kesan O so wipe, " Arjuna mi owon, Mo nba e soro nisinyi ni pa imo to daju julo, "guhyatamaṁ Tamam tumo si oun to dara julo. Daju, dara ju ati dara julo. Tara-tama, ninu Sanskrit. Tara je afiwe akoko, tama na si tumo si eyi ti o ju loo. Bhagavan so ni bi nisinyi, Eda Oluwa Olorun so wipe, idaṁ tu te guhyatamaṁ pravakṣyāmy: "Nisisnyi mo nso fun o imo ti o daju ju lo." Jñānaṁ vijñāna-sahitaṁ. Imo na je imo to pe ni kikun, ki ise iro okan. Jñānaṁ vijñāna-sahitaṁ. Vijñāna tu mo si "sayensi," "ifihan ti o wulo" Nitorina jñānaṁ vijñāna-sahitaṁ yaj jñātvā. Ti e ba ko imo yi, yaj jñātvā mokṣyase 'śubhāt. Aśubhāt. Mokṣyase tumo si pe e o ni igbala, asubhat si tumo si "lainirere" Ainire. Ile aye wa nisinyi, lowolowo bayi, ile aye nisinyi tumosi wipe fun igba ti a ba si wa ninu ara yi, o kun fun ainirere. Mokṣyase aśubhāt. Asubhat tumo si wipe, ainirere.