YO/Prabhupada 0061 - Ara yi je apo awo, egungun, eje
Northeastern University Lecture -- Boston, April 30, 1969
Eyin odo mokunrin ati obinrin mi owon, mo dupe pupo fun asepo yin ninu ipade yi. A ntan egbe ifokansin Olorun ka kiri. nitoripe awon eniyan nilo egbe yi gidi gan nikari gbogbo aye, ati pe eto na si rorun pupo. Iyen ni anfani to wa nbe. Ni akoko, e gbiyanju lati mo nkan ti o je ipo alainibawon. Nipa eyi ti o kan igbesi aye wa, ipo wa yato sara won. Nitorina a gbodo ni oye ti alainibawon ni akoko. Nigbana ni o kan ise isaro alainibawon. Ninu ori Keta, Bhagavad Gita, e ma ri wipe a ni ipo igbesi aye ninu ide ti won yato sara. Ikini ni indriyāṇi parāṇy āhur... (BG 3.42). Ni Sanskrit, indriyani. Nkan akoko ni iye inu ti ara. Olukaluku wa ninu aye yi, wa ninu iye inu ti ara yi. Mo nro wipe "Omo India ni mi." Iwo nro wipe omo Ameika ni e. Enikan nro wipe, "Omo Rosia ni mi." Enikan nro wipe "Elomiran ni mo je." Bee ni olukaluku nro wipe "Ara yi ni mi." Eyi lo se dede, tabi ipo kan na. Ori pepe tabi ipo yi je pepe ife ara nitoripe titi igba ti iye inu wa ba je ti ara, a o ro wipe igbadun ara ni ayo. Ko ju yen lo. Ayo tumo si igbadun ara nitoripe ara je awon oju-imu, owo-ese. Bee ni indriyāṇi parāṇy āhur indriyebhyaḥ paraṁ manaḥ (BG 3.42). Oluwa Krishna so wipe ninu iye inu aye ti eda, tabi iye inu ti ara, awon ipa ara wa ni won se pataki. Iyen nlo lowo lowo nisinyi. Ki tile se nisinyi sugbon lati igba ti a ti daye. Aarun na ni yen, wipe "Emi ni ara yi." Śrīmad-Bhāgavata so wipe: yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma ijya-dhiḥ (SB 10.84.13), wipe "Eni ti o ba ni iye inu ara yi, ni oye wipe, "Emi ni ara yi..." Ātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātu. Ātma-buddhiḥ tumo si iye inu ara eni gege bi apo awo ati egungun. Apo ni eyi. Ara yi je apo awo, egungun, eje, ito, igbe ati awon nkan to dara pupo. Se o ye yin? Sugbon a nro wipe "Emi ni apo egungun, ati awo ati igbe ati'to Iyen ni ewa wa. Iyen ni gbogbo nkan wa."
Awon itan to dara wa... Lai seye meji, asiko ti lo. Sibe sibe, mo fe pa itan kekere kan, O sele pe ewa omoge kan fa odomo kunrin yi mora. Sugbon omoge na o gba fun, odomo kunrin yi fi ake kori. Bee na ni orile ede India, laiseye meji, awon odomo binrin ma nkora won nijanu ni le gan. Bee ni omoge na se nyari. O ba wa so wipe, "O dara bayi, mo gba fun e. Pada wa l'eyin ose kan. O se idahun, "L'ojo bayi ati l'asiko bayi, o le wa." Bee ni inu odomo kunrin se dun pupo. Ni omoge ba ko ogun yagbe-yagbe lo laarin ojo meje na, be lo se bere si nyagbe, l'ojumo ati l'ooru, be na lo si nbi, o si fi awon eebi ati igbe re pa mo sinu ikoko to dara. Nigbati o di ojo adehun, odomo kunrin si de, omoge ta nwi si joko lenu ona. Odomo kunrin ba bi leere, "Nibo ni arabinrin mi wa?" O si dalohun pe, "Emi ni arabinrin na." "Rara ra. Iwo ko. Iwo burewa bayi. Oun omoge arewa ni. Iwo ko ni arabinrin na." "Rara, emi ni arabinrin na, sugbon mo ti yo ewa mi kuro sinu ikoko." "Ewo ni yen"? O ba si fi han: "Ewa na re, igbe at ebi yi. Awon nkan erooja re ni yi. Ni ododo eniyan le ri rubutu ko dara l'ewa gan - ti o ba nyagbe fun ojo mete tabi merin, gbogbo nkan lo ma d'iyato l'enu kannan.
Bee na koko oro ni wipe, bi won se so ninu iwe Śrīmad-Bhāgavatam, wipe iye inu ti ara yi ki se agbojule. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke (SB 10.84.13).