YO/Prabhupada 0062 - Ri Krishna fun wakati merinlelogun



Lecture on SB 1.8.18 -- Chicago, July 4, 1974

Prabhupāda: Ārādhito yadi haris tapasā tataḥ kiṁ. Ti o ba ti le sin Olorun, ko tun si nilo fun aawe, tabi ifira eni jiya... Nitori wipe lati ni ikoni loju, tabi lati mo Olorun, ilana pupo lo wa, aawe orisirisi, ifiranijiya. Nigba miran a nlo sinu igbo, lo sinu igbo lati lo wa ibugbe Olorun, ibi... Nibe, awon orisirisi ilana wa, sugbon iwe mimo so wipe ti eyin ba nsin Olorun ni ododo, ārādhito yadi haris tapasā tataḥ kiṁ, pe ko si iwulo fun ifirani jiya lile, ati awon aawe. Ati narādhito, narādhito yadi haris tapasā tataḥ kim, ati leyin gbogbo nkan leyinti o ba nse awon awe lile...,ti won se awon awe lile ati awon ijemu, Ti e ko ba mo nkan ti Olorun je, kini iwu lo? O ja mosan. Narādhito yadi haris tapasā tataḥ kim, antar bahir yadi haris tapasā tataḥ kiṁ. Bakanna, ti o ba le ri Krishna fun wakati merinlelogun, ninu ati nita, nigba na ni gbogbo tapasya de opin.

Bee na Krishna tun so nibi wipe, Kunti so pe wipe "Bi o ti le je wipe Krishna wa ninu ati ode, nitoripe a o ni awon oju lati Ri," alaksyam, " ko se ni riri" Gege bi nibi Krishna wa loju ogun Kurukshetra, awon Pandavas mararun nikan, gege bi, ati mama won Kunti, awon ni o ye wipe Krishna ni Atobiju Eda Olorun-oba Ati awon melo kan. Bee ni bi o ti le je wipe Krishna wa nbe nigbana, awon kan ro wipe eleda eniyan pere ni. Avajā..., avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritam. Nitoripe O ni anu pupo fun iran awon omo eniyan, O so kale wa Fun Ra Re. Sibe sibe, nitoripe won o ni oju lati Ri, won o le riran. Nitori idi eyi Kunti so pe, alaksyam, "Iwo ko se fi han, Bi o ti le je wipe Iwo ni antaḥ bahiḥ, sarva-bhutanam." Ki ise antah hahih ti awon omo ijosin - ti gbogbo eniyan. Olorun wa ninu okan onikaluku, īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe. Won fi nhan, hṛd-deśe, nibi ninu okan, Olorun wa nbe. Bayi, nitorina, isaro, ilana yoga, nse ni lati se iwadi Olorun ninu okan. Iyen la npe ni isaro.

Bee ni ipo Olorun ni gbogbo igba je alainibawon. Ti a ba gba eto alaininbawon yi, isokan Olorun, awon ofin ikoni ni johun, ati lati se iyanju lati gbara wa sile ninu igbesi aye ese Nitoripe e ko le ri Olorun tabi ni oye nipa Olorun nigba ti e ba nse ipinu ese. Nigba na ko le se se. Na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ prapadyante narādhamāḥ. Awon ti won je duṣkṛtinaḥ...Krti tumo si itosi, ere to to si ni; sugbon, duskrit, awon ere to to fun igbesi aye elese Bee ni, nitorina a nbeere ki awa... A o ni beere, eyi ni nkan wa, mo fe so wipe, awon ofin ati ilana, wipe a gbodo gbara wa sile ninu ese. Awon igbesi aye elese, awon opo igbesi aye elese, ni won je, sina, eran jije, otin mimu ati tete tita. Bee ni a gba awon omo eleko wa ni moran..., ki ti le se imoran, o je dandan pe won gbodo tele awon ofin won yi; bi beko iyen a je isubu fun won. Nitoripe elese ko le ni oye Olorun. Ni owo kan a gbodo tele awon ofin ati liana nipa eto esin, ni owo keji a gbodo koyin si ese. Igbana ni Olorun yi o si fara han, e sile ba Olorun soro, a si le wa pelu Olorun. Olorun ni anu pupo. Gege bi Kunti se nba Krishna soro bi omo ibatan re. bakanna e le ba Olorun soro, gege bi omo yin, gege bi oko yin, gege bi ololufe yin, gege bi ore yin, gege bi Oga yin, bi o se wu yin.

Bee ni inu mi dun lati ri ile ijosin ti Chicago. E nse daradara, yara nla ti esin na si dara. Bee na e ma ba ise yin lo pelu iwa to joju ki e si mu mu Olorun se. Igbana ni ile aye yin yi o si je aseyori.

E se pupo.

Olujosin; Ogo! E fi ogo fun Oluwa!