YO/Prabhupada 0075 - O gbodo lo s'odo Guru



Lecture on SB 1.8.25 -- Mayapur, October 5, 1974

Nigba ti eniyan ba ni okan iwadi nipa ibeere lori awon nkan to ga. brahma-jijñāsā,, igba na ni o nilo guru. Tasmād guruṁ prapadyeta: "O ti lokan iwadi nipa liloye imo to ga, nitorina o gbodo lo s'odo guru." Tasmād guruṁ prapadyeta. Tani? Jijñāsuḥ śreya uttamam. Uttamam. Uttamam tumo eyi ti o wa loke okunkun yi; Gbogbo aye yi je okunkun. Nitorina eni ti o ba fe gori okunkun Tamasi mā jyotir gama. Ilana Vediki ni "Ma duro sinu okunkun. Lo s'oju imole." Imole ti a nwi na ni Brahman, brahma-jijñāsā. Bee na eniti o ba l'okan iwadi... Uttama ... Udgata-tama yasmāt. Udgata-tama. Tama tumo si aimokan. Bee ni ko si aimokan ni iseda ôrun. Jñāna. Awon ologbon Maayaavaadi, nkan so wipe, jñāna, jñānavān. Sugbon jñāna ko nse nkan ti ko ni keji. Orisirisi jñāna lo wa. Gege bi ni Vrndavan, jñāna wa, sugbon oniruru re lo wa. Enikan fe ni ife Olorun bi oluranse. Enikan fe ni ife Olorun bi ore. Enikan fe ni ife ola Olorun. Enikan fe ni ife Olorun gege bi baba ati iya. Enikan fe ni ife Olorun gege bi olufe, tabi aale - e ma se yonu. Bee na enikan fe ni ife Olorun gege bi ôta. Bi Kamsa. Vrndavana-lila na ni yen. Oun se ronu Olorun ni gbogbo igba ni ona kona, bawo lo se le pa Krishna. Putanaa, oun na wa bi olufe Krishna, lati fun loyan. sugbon ero inu re ni bi o se le pa Krishna. Sugbon iyen na si je bi ife aisetaara, ife ti ko se taara.. Anyvat.

Bee ni Krishna se je jagad-guru. Oun ni Oluko atilewa. Oluko na nko wa fun Ra Re ninu Bhagavad-Gita, awa ti a nse alailofin, a o gba eko na. E foju wo. Nitorina mudhas ni wa. Enikeni ti o ba ni étô lati gba eko ti jagad-guru fun ni, mudha ni. Nitorina agogo iyewo wa ni: eni ti o ba mo Olorun, Eni ti o ba mo bi won se ntele ilana Bhagavad-Gita, a fi mu lowo kanna gege bi alaimofin. E ma se yonu, bi o ti le je wipe oun ni aare alakoso, o si le je adajo ile-ejo giga, tabi... Rara "Rara, o je aare alakoso. O je adajo ile-ejo giga. Sibe na, mudhah ni? Bee ni. "Bawo" Māyayāpahṛta-jñānāḥ: (BG 7.15) Ko ni imo Olorun. Etan maya ti fi abo bo lori. Māyayāpahṛta-jñānā āsuraṁ bhāvam āśritāḥ. Nitorina mudha lo je. Bee na ka wasu taara. Ni daju, e le so awon nkan yi ni ohun riro, lati moju pe, ko ni si atako. sugbon enikeni ti ko ba gba Krishna gege bi jagad-guru ti ko si gba imoran Re, alaimofin ni. Bi mudha to wa ni Jagannatha puri yi. O so wipe "Ni gba aye yin miran. Nigba na ..." Mudha na, gba bi alaimofin. Fun kini? Oun ni jagad-guru, oun na so wipe, "Emi ni jagad-guru." Sugbon ki s'oun ni ni jagad-guru. Ko tile ti ri ohun ti won npe ni jagat. Opolo ni. O si npe ra re ni jagad-guru. Nitori na mudha ni. Bee ni Krishna wi. O je mudha nitori wipe ko gba awon eko ti Krishna fi sile.